IBANUJE NLA!! NITORI ORO TI KO TO NKAN, AZEEZ FO HAMMER MO IYAWO RE LORI

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 3 фев 2025

Комментарии • 5

  • @toyinkolawole1713
    @toyinkolawole1713 8 дней назад

    Omase ooo,ibinu je nkan to buru jai ati pe ti ija ba ti nwaiye larin oko ati aya ni gbogbo igba ki won tete yago funra won ni kiakia,ogun aiye ko ni bori wa ni agbara Olorun Alaiye
    Aanu Azeez se mi lopolopo,ki Olorun ko fi orun ke eni to ti ku ooo,unnn,omase ooo

  • @Boye-efex
    @Boye-efex 7 дней назад

    Olotu pls come to my brother rescue pls sirr

  • @foyekealawode4963
    @foyekealawode4963 7 дней назад

    Olorun lo mo ejo da, huuuuun

  • @SoulyaAtanda
    @SoulyaAtanda 11 дней назад +2

    Ohun na ko ba si se suru nigbati won ti ba soro ti oko ba mo pe bio ti ri re koba molo si odo iya re abamo ke gbe iwaju eyin lo mo duro si olorun yio fi ori jin eyin loko laya emo se suru keni kan je ewure keni kan je aguntan loda

  • @gracesowunmi4838
    @gracesowunmi4838 8 дней назад

    AWON OMO ASIKOYI WON KO NI SURU RARA LATI KEKO IGBEYAWO OLORUN KO MA KO GBOGBO AWON OMO WA YO NI