I would suggest to the honorable governor of Ogun state to choose another King within that 6 month suspension to serve as a deterrent to others , if you check comments in any pages you would never see a single positive comment on him.
Baba Ondo , amoran mi siyin nipe eta ile yin ki epada si ile oluji , nitori wipe emi yin ko safe , biwon yo oba buruku yii loye ,bi won koyo loye ori ewu lemi re wao , abo oro lama sofun omo luwabi o
Olorile of orile ifo, Abdul Semiu Adewale Ogunjobi must be dethrone and prosecuted b'cos he is a disgrace to the Yoruba race. His scripts has been ended. Job well done Yoruba gidi TV. ❤❤❤
Eranko ni ogbeni were to pe ara re ni oba yi o. Use late Deji of Akure ( oba Adesina) as a case study. He publicly assaulted his late wife. The video got to the public and Govt did the needful. He was dethroned & banished to another city.
Semiu oba-ifo olofo Ogun state yii, koniraje jeun tomotomo konsini sorire mo lagbara Olodumare gbogbo epe tonse wonyen niyoje tie tebitara tomotomo tibangbesi oba eleribu yii lehin.
Ki awon olopa pese abo topeye fun baba Abraham love toripe awon janduku oba eranko yi le lo pa baba na o. Eleyi a ko awon oba onigberaga yoku logbon. 😅😂
Gov. Dapo Abiodun pls Oba is not fit to return to the palace he will pai this baba one day only him can count the no of people he has send to the great beyond without anyone knowing the baba already said it oooo let him serve a SCAPEGOAT to others who are custodian of our culture.
Oba onigberaga, . A dupe lowo ijoba ipinle ogun ati olopa . Nigeria pelu idide won si Oro naa. More elbow there Grace o . Aju ni lo Kan ko just . Olorun lo ( pride goes before a fall)
Dis Assaulted baba still have additional statement, quote " ebami be ki o ma pami bi o se ma npa awon eniyan", definitely dis baba know kabiesi as a killer.
O ma se o nnkan ti awon oloselu so ile Ooodua ni eleyii .nigbati won awon oloriburuku oloselu awon obaye oloselu jegudu jera anikanjopon ika eda ti nfi awon ti ko ye je oba ni yoruba ni aburu ti bere sii sile ni ile Ooodua afi ki Edunmare gbawa ki a gba ominira kuro lowo awon aninilara ni Nigeria .
Na the king go kpai for your sake if he plan any death against you. He is no more a king since the day he humiliated you. The most senseless self acclaimed king
Ejo ta wa ni, bikose jegudujera Are Nigeria nigbati o ne Gomina Ipinle Eko ti awon Agbero ngba agbatungba owo ero moto wiwo to be ge ti Gomina Bola Ahmed Tinubu do nigbana pe ko si nkankan ti oun le se, nitoripe awon Agbero ni won gbe oun jawe-olubori idibo ñaa.
Oba ni ohun ni ohun ni gbogbo naijiria police ki baba yen ku awon ma sin ni.kosinidaa fun oba orile ifo koni sa nkan tio dara je.gbogbo epe tio fi baba yen se odi ori re ori omo re pelu.
My big question is how did these Fulani herdsmen worked their way to the “Obaship” throne in Yoruba land . You can see clearly that they do not know our culture and traditions . That’s why they they keep misbehaving . An Oba should be father to everybody not a tout as presented in those clips shared
Nibo ni won ti ri awon jaduku ti won fi joba nitori olorun e ro baba yi loye o.olorun loti mo iye enia to ti pa danu .ki e to fiyan joba e se biwon ti nse kole ri botiye kori o.
Aje pe kabiesi ti Pa awon Eyan tipe.abi iru oro wo lo Ja de lenu kabiesi. Kilode TI awon Oba ile Yoruba sese bayi.this is totally degrees in Yoruba lands 🥲🫣
The government should provide adequate protection for the old man, the tug called king should write an undertaking, nothing must happen to the old man been humiliated
Thug King, the man Abraham should come clean as well, there's an issue with them which i believe the man betrayed the King based on his statement but whichever way the Oba misuse his power, he must learn the hard way.
This Oba is never near in anything to our God Almighty. This type of similar cases must have been going on for long, and no justice upheld. But right now he's time is up.
Ejowo nibo ni awon omo baba yi wa ki won sere ino 🔥 fu property okunrin yi mi o lepe ni oba tori oba ki jagun bi eru akiton ni oba.oba agbo bi alaigbo oba ari bi eni tikori.ire loba un wu fun ilu e.oba ki sepe.alale ati awon orisa loun ja fun oba.. YORUBA EJOWO EJE KA TUN ILE BABA WA SE
Kii se oba,. Oba kii force respect ni idobale. OMO ale niii
This king is mad
I would suggest to the honorable governor of Ogun state to choose another King within that 6 month suspension to serve as a deterrent to others , if you check comments in any pages you would never see a single positive comment on him.
This Oba should be dethroned for this public humiliation behavior towards one of his Baale is unacceptable
Yoruba ronu this one is much e dekun ati maa fi amugbo je oba
Shame on those who appointed this tyrant to be king over them. O ti bleach gbogbo alafia ara re danu.
O bleach alafia ati ogbon ori
This is very barbaric. He has taken law into his hands. The Governor must investigate this matter and punish the offender accordingly.
All the human rights activists in Nigeria need to come to this man rescued?
Ko ni da fu oba ye o, Eranko, gbogbo ira di ra oba yi, ko ni shorire o. Omo eru ni oba ifo, eru a ba luje, gbogbo ira ati ebi oba ifo wo o ni kure.
Oloye kọ ni Baba yi , ọmọ ilu mi ni okunrin yi.
Imagine if this vampire is still in police force carrying arms, Imagine how many life he would have taken with his hot temper.
Oba to n bora
Baba Ondo , amoran mi siyin nipe eta ile yin ki epada si ile oluji , nitori wipe emi yin ko safe , biwon yo oba buruku yii loye ,bi won koyo loye ori ewu lemi re wao , abo oro lama sofun omo luwabi o
Best decision for now ❤
Yes baba should relocate back to another place I trust Nigeria they will help him financially
Exactly o.... May God protect him and his family
Tabani kasoto sekiisepe obayi. Obayi oyekofade pita ni tori wipe igberaga yipo eleyi koye loba
This is hooligan in that village , he is not a king,
Oba buruku Oba Carol white eleke kengbe. Government should investigate this Oba of Orile- Ifo.
😂 , maybe it's the Carol white that messed up his brain
Ti baba omo ile Oluji ni ipinle Ondo o ba tile jewo omo ile Oluji fun oba ika oloriburuku yii pe oun lo ma
Iru oba wo leleyi? Awon oba ti wo so Ara won di olorun.
Olorile of orile ifo, Abdul Semiu Adewale Ogunjobi must be dethrone and prosecuted b'cos he is a disgrace to the Yoruba race. His scripts has been ended. Job well done Yoruba gidi TV. ❤❤❤
Oba bora bora eleke jengbe amugbo
Won fi ra won sepe ke se baba ni oni eepe awon tika Lara won loni epe yio sise mo won lori amin lagbara eledua
Hmmm nkan nbe, epe yi po ju
Terrible news ogaooo..nibolalo niluyi.. ekuse takutaku bami
Eranko ni ogbeni were to pe ara re ni oba yi o. Use late Deji of Akure ( oba Adesina) as a case study. He publicly assaulted his late wife. The video got to the public and Govt did the needful. He was dethroned & banished to another city.
Semiu oba-ifo olofo Ogun state yii, koniraje jeun tomotomo konsini sorire mo lagbara Olodumare gbogbo epe tonse wonyen niyoje tie tebitara tomotomo tibangbesi oba eleribu yii lehin.
oba eleribu obayeje enianu tikoye loye, oba lasan-lasan ekeji Aja
Ki awon olopa pese abo topeye fun baba Abraham love toripe awon janduku oba eranko yi le lo pa baba na o. Eleyi a ko awon oba onigberaga yoku logbon. 😅😂
Oloriburu ni oba radarada yen. He should be arrested and dealt with. Ori ade oshi bleached thing.
Oba yi ko ye ni apere oba, ogbudo je fulani, ti se ota omo YORUBA
The technology has caught up with the, Kabiyesi, he is in messy situation, yet, Mr Gov is in order so far so good.
Gov. Dapo Abiodun pls Oba is not fit to return to the palace he will pai this baba one day only him can count the no of people he has send to the great beyond without anyone knowing the baba already said it oooo let him serve a SCAPEGOAT to others who are custodian of our culture.
Even without returning to palace, this bàbá needs security
Oba onigberaga, . A dupe lowo ijoba ipinle ogun ati olopa . Nigeria pelu idide won si Oro naa. More elbow there Grace o . Aju ni lo Kan ko just . Olorun lo ( pride goes before a fall)
Dis Assaulted baba still have additional statement, quote " ebami be ki o ma pami bi o se ma npa awon eniyan", definitely dis baba know kabiesi as a killer.
O fi ola je yo hummm😭😭😭
Point of corrections, he is bearing Muslim name by accident, but he did not behave as such. Ogunjobi is related to ogun diety worshiper .
Love
Not by accident, we are yet to see one ogun worshipper behaving like this muslim oba.
Gbogbo ilu ooo fe loye ooo. Eniyan buruku ni eeee Oba for that matter.
O ma se o nnkan ti awon oloselu so ile Ooodua ni eleyii .nigbati won awon oloriburuku oloselu awon obaye oloselu jegudu jera anikanjopon ika eda ti nfi awon ti ko ye je oba ni yoruba ni aburu ti bere sii sile ni ile Ooodua afi ki Edunmare gbawa ki a gba ominira kuro lowo awon aninilara ni Nigeria .
OBA Caro tone 😊😊😊
Na the king go kpai for your sake if he plan any death against you. He is no more a king since the day he humiliated you. The most senseless self acclaimed king
According to this king name it's first king 👑 in him family
Ejo ta wa ni, bikose jegudujera Are Nigeria nigbati o ne Gomina Ipinle Eko ti awon Agbero ngba agbatungba owo ero moto wiwo to be ge ti Gomina Bola Ahmed Tinubu do nigbana pe ko si nkankan ti oun le se, nitoripe awon Agbero ni won gbe oun jawe-olubori idibo ñaa.
Criminal kings everywhere, small and big
Olorun a da oba yi lejo.
All These That Contributed in This Should be Dealt With With Not Only The King
Oba ni ohun ni ohun ni gbogbo naijiria police ki baba yen ku awon ma sin ni.kosinidaa fun oba orile ifo koni sa nkan tio dara je.gbogbo epe tio fi baba yen se odi ori re ori omo re pelu.
My big question is how did these Fulani herdsmen worked their way to the “Obaship” throne in Yoruba land . You can see clearly that they do not know our culture and traditions . That’s why they they keep misbehaving . An Oba should be father to everybody not a tout as presented in those clips shared
E so fun oba were yi pe, o ti yiwo fun.
Gbogbo epe ati egun ti were yi ge ko pada si ori e lagbara Olorun.
Ayé ìjekúje. Shame on the king makers.
Aah, kabiesi re olodumare
Bi olorun bati fe mu eyan asise lokoko ma ba onitihun asise ti ba oba yi
were ni oba yi oooo se iwo ni ijoba ma ralewon ba yi
Baba ejowo sir, e ma Bo wa si Ileoluji pada wa si ile. E majeki won paying ni ojo aipe.
Awon to laya tijade bayi, won de ti nbi e, awo ibi to majasi. Awon eni abuku ti won nperawon loba.
Abuku yi ti po ju fun Ogun state.
Awa ti a ni baba nwo yin.
One can imagine evil things he would've perpetrated while he was in the Police force..
It's time to give the youths chance.....see the crop of youths 😢😢😢😮😢
Oba owo Ni Ondo State ko Se to bayi ki Adekunle Ajasin Fi roo loye
Amugbo oba oba to nbora omo ita ,oye ki won fi oro lee kuro ni ori apeere ni .
This young Oba man and a retired policeman is embarrassment to ogun state government and children of Egba land.
Nibo ni won ti ri awon jaduku ti won fi joba nitori olorun e ro baba yi loye o.olorun loti mo iye enia to ti pa danu .ki e to fiyan joba e se biwon ti nse kole ri botiye kori o.
Se oba ni eleyi,abi toogi, gbogbo awon to nhuwa yi si,ki won yoju?
Oloriburuku oba ni.
E je ko lo ko eko ni ogba ewon.
Esin musulumi ma nse won bi were ni,oba ti ya were,elesin jagidijagan,won ti fi elesin were joba ni orile ifo.
Iya o ni je yin sir
Even the boy that slapped that old man is supposed to be in prison as well
Aje pe kabiesi ti Pa awon Eyan tipe.abi iru oro wo lo Ja de lenu kabiesi. Kilode TI awon Oba ile Yoruba sese bayi.this is totally degrees in Yoruba lands 🥲🫣
O da be eniti olorun ole oluwa ko yin ti da
The government should provide adequate protection for the old man, the tug called king should write an undertaking, nothing must happen to the old man been humiliated
Asilo agbara. Where did you see christian king do like this throughout Yoruba land.
Muslim people!!!
Oba ika!!Oba koba!!ni oba buruku yen o!!
O GODUMARE OOOO
EPE YII PO OOO
EPE TO LAGBARA GIDI GAN NII OOO 😮😮😮
Oba radarada wo le yin
Is it proper to install any baale in the midnight
The claimed throne is under Olu of Ifo and not Ifo town. He should be jailed.
Eranko ninu eyan ni oba eleyi ika wa ninu e tori o gbe agbara wo bi ewu
Hmmm, o ga o!!!
But what Oluwo of Iwo did to his palace chiefs was more terrible than this o, yet, nothing happened. I hope he will not go scot free like Oluwo.
Nigeria when to see good gorgement on this matter
Social media is a powerful tool!
But use it wisely!❤
This is an humiliation of the highest order. This so call oba/kabiyesi must be one of the area boys mistakenly taken to the throne.
Awa ofe iru Oba eleyi nile Yoruba o
Oju gbamiti lati je Omo Bibi ipinle OGUN paapaa nitori ipinle OGUN yii kannaa ni iwa idojuti RITUALS gbile sii ju
AWON oba Yi kogbodo ni ore ofe ti CSI ni igberaga apoju,olorun loni kiwon se video
It is called power. The Baale or Oba was power drunk .
25:57 Eleyi a lo lau.Bye bye o Kabiyesi
When awon afobajes disregard ifa and tradition to choose tura ambassador 😢 no matter his position he should have respected the old man's age.
Eru Saudi ni, real Tura ambassador. Awon eeyan carol white
The government must bring the oba to the book, and deal with the Man,he is kabiyesi
OBA ABORAJEBI
Imagine that, emi ni mo ni olopa Nigeria? Oba tun boast Lori iwa buruku ti won Wu. E Fi aimo ko ma je pe eyin le ma lo ewo dipo baba Yi loruko jesu
Toripe ifa ko lo yan oba .owo na fi yan oba laye ode oni
Gbogbo ile Yoruba lo nreti abajade oro yio. Ofin gbodo sise lori oro yio.
MEKUNNU KO RI AYE WA. OTE NI OUN NA FI DI OBA. OTE LO FI DI OBA OLOPA.
Even the Yorubas have been embarrassed
He has to be dethroned immediately with his accomplishments we don't need hooligans as a king anywhere around Yoruba land.😔🤷
Eyin Omo Ondo kin le nwo?
Bi e ba se nkankan, E ki se Omo Yoruba, Ondo.
E pe oba na ati governor Dapo lejo, to ba ko,lai se nkankan si.
Thug King, the man Abraham should come clean as well, there's an issue with them which i believe the man betrayed the King based on his statement but whichever way the Oba misuse his power, he must learn the hard way.
And so what? So because there's something secrecy btw them now,he must be humiliated publicly?....
@davidomotayo5961 I hate arguments, if your brain can't comprehend my message, just stroll up👌
He is God's second in command
the king is just being stupd
This Oba is never near in anything to our God Almighty. This type of similar cases must have been going on for long, and no justice upheld. But right now he's time is up.
Thank God that the Oba didn't invite him into his palace, maybe if he was invited only God knows what must have happened to this elderly man.
The antics of these ABDUL-kings in Yoruba land is getting out of hand. There is one ABDUL-Rasheed acting like a drunkard in Iwo.
Eru ni won. Ti a ba fi eru joba, a ba ilu je
Ejowo nibo ni awon omo baba yi wa ki won sere ino 🔥 fu property okunrin yi mi o lepe ni oba tori oba ki jagun bi eru akiton ni oba.oba agbo bi alaigbo oba ari bi eni tikori.ire loba un wu fun ilu e.oba ki sepe.alale ati awon orisa loun ja fun oba.. YORUBA EJOWO EJE KA TUN ILE BABA WA SE
A ti pe ti oba yi a ti maa hu iru iwa buburu yi nigba to ti wa nise olopa .Boya akoko idajo re lo to.