AWON AJINIGBE IJẸBU -IGBO JẸWỌ: GENDE MẸTA LA TI PA LẸYIN TA A GBOWO ITUSILẸ LỌWỌ WỌN

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 27 авг 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Комментарии • 42

  • @OkerindeAbiodun-qn6ir
    @OkerindeAbiodun-qn6ir Месяц назад +6

    Haa olopa ogun Moki yin pupo ekuse takuntakun olorun atubo pin yin lere Amin 🙏🙏🙏

  • @omoshewayinka2581
    @omoshewayinka2581 Месяц назад +9

    Ahh! Olorun o! 😢😢... ki won wa awon arawon toku jade ki won pa gbogbo won straight 😢. O ga o .

  • @Omoayo7066
    @Omoayo7066 Месяц назад +8

    Eyin Olopaa ilu Abeokuta 👍 mo kiyin pe eku ise naa sir/ma...

  • @RazeedAyinki
    @RazeedAyinki Месяц назад +4

    Oloriburuku ni awon eleyi oooooooooo

  • @saheedadewale5901
    @saheedadewale5901 Месяц назад +2

    Iku ni ere ese, awon ika eniyan

  • @SikiruYusuf-jp6qy
    @SikiruYusuf-jp6qy Месяц назад +3

    Ejoo gbogbowonnikoepa patapata ejoo

  • @lanrea9373
    @lanrea9373 Месяц назад +1

    Oye ki won wa idi awon ajinigbe yi de ilu won ki won to ye igi fun won ati awon ebi won.

  • @OlowoleSunday-xg1gv
    @OlowoleSunday-xg1gv Месяц назад +3

    Awọn ọmọ yibo nile yoruba haa

  • @moyomoyo4860
    @moyomoyo4860 Месяц назад +3

    Olóríburúkú people! Owó òhún kò yo lára won.

  • @kamaldeenaolatunji7282
    @kamaldeenaolatunji7282 Месяц назад +4

    After kidnaping nd taken 😢 ransom, they will b telling u they are the most intelligent tribe in Nigeria who know how to do business most, nd hv money than others... Bragging on criminality, we never ready in D's country, when it's time we do d necessary things..

  • @mikelowo7493
    @mikelowo7493 Месяц назад +3

    Ijebu people self dey sleep......awon omo agemo merin din logun e ma sun oo.

  • @SaniAtiku-lg8hx
    @SaniAtiku-lg8hx Месяц назад +1

    Ki won lo pa won lesekese.. Ko ni need ile ejo botiwule ko ma... Ki won lo ge Ori awon mejeji ti owo te yi... Ki awon yoku na to wa pade iku gbona won...

  • @gnwmaster
    @gnwmaster Месяц назад +2

    Sad 😢

  • @user-fp1pz2gg8x
    @user-fp1pz2gg8x 25 дней назад

    ALAROYE EKU ISE TAKUN TAKUN KO SI UNKAN MEJI NI PE KI WON PA WON LO 😢😢😢😢😢

  • @abetoba2331
    @abetoba2331 Месяц назад

    Ao feri OMO YIBO kankan ni IJEBU IGBO mon

  • @user-rh2ws3pv1t
    @user-rh2ws3pv1t 23 дня назад

    Don't forget the young girl Elizabeth, that make 4 innocent Ijebu Igbo people lilled

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 Месяц назад +1

    E tete pa awon oloriburuku ajinigbe wonyi ooooo. Asiri awon kidnappers ko ni bo mo ni ile Yoruba ni oruko Jesu amin...alale ile Yoruba loma seku pa gbogbo eyin ajinigbe ati eyin ritualists ni ile Yoruba ni agbara olorun amin ase Edumare

  • @adebayophilip6011
    @adebayophilip6011 Месяц назад +1

    God bless Ogun state police ..
    If na another state they will cover the evils .
    God bless all sincere security agents

  • @lanrea9373
    @lanrea9373 Месяц назад +2

    Ki won ye igi fun won.

  • @TheGreatestAlmight
    @TheGreatestAlmight Месяц назад +5

    awon omo aje okuta mamu omi ti gbe kidnapping de ile yoruba

  • @fatalkehinderaheemat1513
    @fatalkehinderaheemat1513 Месяц назад

    Ahah aye too to Akamora

  • @OlowoleSunday-xg1gv
    @OlowoleSunday-xg1gv Месяц назад +1

    Eranko ni awon Igbo yi o

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 Месяц назад

    HMMMMMMMMMM kudos to you ogun state police force..God will protect you guys

  • @user-vx2py3yy6z
    @user-vx2py3yy6z Месяц назад

    This is very sad

  • @user-rh2ws3pv1t
    @user-rh2ws3pv1t 23 дня назад

    Ogun State Governonr, you are sleeping on duty, sir.

  • @yemisioladapo2011
    @yemisioladapo2011 Месяц назад

    Haaa this is sad, 😭💔, their squad are really trying God will really bless and continue to protect them and their household amen,
    One thing i have about you people is...the suspect would have confess the evil they're doing with their own mouth o.
    Igbayen lema sope kiwon kowon losi prison, which evidence again is the government looking for? I don't understand,
    I don't really trust the government concerning that sha

  • @adebayophilip6011
    @adebayophilip6011 Месяц назад

    This is pure wickedness and parental negligence...
    God heal our ldnds

  • @olufelabarber7795
    @olufelabarber7795 Месяц назад +1

    Awon aje okuta .mamu omi ni won won tun wa npa yoruba nile yoruba. Oye ki adajo yegi fun gbogbo won ni. Kini won fi yato si Boko Haram

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 Месяц назад

    Elo so won ro

  • @suzanneawoleke6488
    @suzanneawoleke6488 Месяц назад

    So sad

  • @goldenroyal7351
    @goldenroyal7351 Месяц назад

    HUU IDIE NIYE TAFI GBODO MOJUTO AWAN AJOJI TAGBA NI AYE NI ILE YORUBA
    AWUSA FULANI IGBO ORI ORO WAN NI WAN WA WIPE AWAN FE GBA ILE WA
    AROPE ERE NI BE AWAN WAN UNKO SINUN AWAN OMO ALE YORUBA KOKAN
    TI WAN FIN WU IWA BURUKU TELE OMO YORUBA AOKIN JALE AOKIN PA EEYAN
    BE AOKIN PA IRO MON EEYAN AWAN WERE YI NI WAN KO IWA BURUKU WO ILE WA
    EYIN AGBA GBA EMATA ILE FUN WAN MON KADE MALO YE ILE AWAN OLORI WAN WO
    LADUGBO TABI INUN OJA LEKOKAN AWAN NI WANUN GBA ABODE FUN WA THANKS SO MUSH MR ALAROYE

  • @user-rh2ws3pv1t
    @user-rh2ws3pv1t 23 дня назад

    Bi won se n gba laarin awon Yoruba, gbo ede die, won a maa wa se ise terrorism in #Yorubaland for #Yoruba people.

  • @fatalkehinderaheemat1513
    @fatalkehinderaheemat1513 Месяц назад

    Eyin oloribu koni da fun yin e le lo ma ji awon Igbo egbe yin gbe e ra re ni you leave Igbo land and come to Yoruba land to kidnap Yoruba

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp
    @RemilekunAdeleye-ew4dp Месяц назад

    HAHAHA

  • @LawalOshoma
    @LawalOshoma Месяц назад +1

    Where are the useless blogger not mentioning igbos

  • @truthsquestions1532
    @truthsquestions1532 Месяц назад

    Victims are yoruba. Waow

  • @anneemitomo6134
    @anneemitomo6134 Месяц назад

    Bi awon agbofinro ti se nmu yin yi, O ye ki e mo pe iro lowa ninu ajinigbe ati ifinisowo, o ye ki e jawo ninu owo ti OLORUN Oba ko fowo si ati ti KO nife si, ti ko lere ki awon eleyi ko je eko fun awon odo ati gbogbo enia ti o nife si tita enia ati ritualists

  • @olumoolowu8326
    @olumoolowu8326 Месяц назад +1

    THE QUESTION IS .
    WHERE IS ALL THE MONEY THEY COLLECTED FROM PEOPLE.
    THEY DON'T LOOK RICH.
    THEY COLLECTED MILLIONS. WHAT DID THEY DO WITH THE MONEY.
    THERE IS MORE TO THIS. THEY NEEDED TO BE QUESTIONED WELL AND GET THE REST OF THEM HIDING SOMEWHERE. PIPA NI WON GBODO JE. NITORI AWON NAA TI PA OPOLOPO ENIYAN.

  • @madraneclue9641
    @madraneclue9641 24 дня назад

    Ogun state and crimes are 5and6