Se aburo e kole wole fun yin kuro ni sitting room...this is plan work o....o mo nkan to se mo ...sugbon o ranti pe emeji ni😂😂😂 otun pe aburo ko basun... elo si ewon ni taaraaa
Ohun ti owa ni okan awon mejeji ni won nse o, oro oti ko rara, nigbati oba ti awon omo olomo je tan owa nbebe. Ki ise ejo won ejo awon omo olori buruku yen ni, baba won ati iya won ni awon mererin fijo, isekuse tiwa ninu eje awon idile wonyen tipe tipe.
Orisirisi awon omobinrin buruku yi na po ni igboro, awon ni won bi awon omo ale jo si ile Yoruba, iru awon omo tiwon bi ni won ya ajinigbe, agbebon, agbe sunmonmin, ati awon were ni arin igboro loni.
Ki lode ti e bu obinrin, Se okunrin kan ko lo basu to fi bi omo yan, omo to ba da ti baba ni eyi ti oba kun die Kato fun iya le ma da le lori, a fi Kolorun ko obinrin yo lowo yin.
Ema binu simi ma iwa alainitiju ti omobinrin yen hu ni omun inu bimi, emi feran lati mon ebi tabi ikan ninu awon obi obinrin ki ato dijo ma rin po, nitori wipe omo buruku se'fe anon buruku ni ko dara. Ki omobinrin losi ile okunrin ni igba akoko ki okunrin ri ihoho re, ohun ti oburu ni ma. Eniti ko mon ebi re kankan, ha oga o.
Parents have a huge role in the life of the children . You will notice these evil brothers have been involved series of scandals that’s above their age ..
Osejepe ogun state ni inkan buruku ti n ma sele ni gbogbo igba? 🤔 we all knw that in yoruba land nah ogun state ritualist full and many other things like this, se ogun state nikan Lowa nile yoruba ni?😢 why tie se ya alaburu eda bayii?
Ejowo ebami ra ( another Red Belt ) fun arakunrin yi ati aburo re, leyin igbati won ba mun tan, ki adajo bami fun enikookan won ni ewon ogota odun, ki won sare lo ki won bo pa. Won ( plan ) fun omo yen ni, kosi awa wi, won ti nse tipe tipe, eleyi koni akoko
All lies........ Both brothers are rapist i want to first believe him that his brother's is innocent until he mention Kaosara, definitely they both always plan and chop same girls that's unfair 💔put him to jail where he will no longer see bullet again talkless of sleeping with innocent girls........
Its a deliberate act between both of them... they need to face the law
Cultist ni awọn oloriburuku, ọmọ alè wonyi. At least 21 years with hard labour is my suggestion for both of the mad men.
😂😂😂
Eh kilooode😂
Shey won fi epe shey e nii
Is what they plan not highness atall
Yes I agreed it is what they planned together with the brother
It is not their first time .. awon omo buruku
Dnt mind this boy is not Highness is wickedness
This one na Oloriburuku.he still slap her
Its Premeditated... they have been doing this for a long time.
Facts, it's premeditated...they both need to face the consequences of their actions
They know what they’re doing not just shanyo or nonsense he is saying 😂
Planned .
😢😢😢😢😢.
@@bukkyabiona2888 exactly 👍
Deliberate act ni, is not alcohol...my judgement life imprisonment straight awon oloshi omoale gbogbo
Se aburo e kole wole fun yin kuro ni sitting room...this is plan work o....o mo nkan to se mo ...sugbon o ranti pe emeji ni😂😂😂 otun pe aburo ko basun... elo si ewon ni taaraaa
May God have mercy on your mum two boys behind bar
Jeesu 😢
This voice over bad oo😂😂😂😂😂
Uuuuunnnnnn eyin omo obinrin ebipolowoyin ooo eyin lefi Ole Ara jarayin o. Ilewe loronelo koto lomu bullet
Ohun ti owa ni okan awon mejeji ni won nse o, oro oti ko rara, nigbati oba ti awon omo olomo je tan owa nbebe.
Ki ise ejo won ejo awon omo olori buruku yen ni, baba won ati iya won ni awon mererin fijo, isekuse tiwa ninu eje awon idile wonyen tipe tipe.
They should put them in jail to serve others. Ladies should be careful of where they go ❤❤
True
Would they ever listen? They want to open eye na. Useless generation.
They won't listen
Ise esu ni
Tori Olorun mo pe oni ojo iwaju rere, Olorun a ko e yo. To ba sewon to pada de wa ronupiwada.sugbon to ba sewon oni mo ohun to se pe koda.
Anu semi...ntori oti mo wipe iku ni ere ese
Ise esu wo ni ? Ise jesu ni
Beeeniii
Oloriburuku omo osi Adojutini omo.
He must be jailed. Am interested in this case. Bad boys
No sound
Abi won tini awon ose ejomo ni
Ewan lema kusi. Eyin Oloshi
Ki gbagbe won sewon ki won ku sibe.Olorun amu awon toku.
5years minimum is okay at prison 😢
Oma she ere Aniyan yen wo ogba ewon ni, omo ale
Isé esu Ni but efun Ni life in prison
O MA SE OO 😮
Hummm
This is not there first time awon oloriburuku omo alee
Ka aa ye omokomo
Nawah o.
Awon ale
Sise loye ki won maage inkan omokurin eni ti oba fi ipa ba obirin sun, hnnn ki sise ebi yin bikose awon omo birin ti won rin irin kurin
Oloriburuku omo e pe lewon
Awon oloriburuku omo
Hummm o lagbara oo
Orisirisi awon omobinrin buruku yi na po ni igboro, awon ni won bi awon omo ale jo si ile Yoruba, iru awon omo tiwon bi ni won ya ajinigbe, agbebon, agbe sunmonmin, ati awon were ni arin igboro loni.
Ki lode ti e bu obinrin,
Se okunrin kan ko lo basu to fi bi omo yan, omo to ba da ti baba ni eyi ti oba kun die Kato fun iya le ma da le lori, a fi Kolorun ko obinrin yo lowo yin.
Ema binu simi ma iwa alainitiju ti omobinrin yen hu ni omun inu bimi, emi feran lati mon ebi tabi ikan ninu awon obi obinrin ki ato dijo ma rin po, nitori wipe omo buruku se'fe anon buruku ni ko dara.
Ki omobinrin losi ile okunrin ni igba akoko ki okunrin ri ihoho re, ohun ti oburu ni ma.
Eniti ko mon ebi re kankan, ha oga o.
Ile lon Lor Tarara ewon tin reti ee ile lo Lor Tarara
Parents have a huge role in the life of the children . You will notice these evil brothers have been involved series of scandals that’s above their age ..
Oloriburuku niè
Irolonpaaa..elewon
This one na original criminal.
Enibo nibe eyin were gbogbo yi
😂😂😂
Aseeewaaa
Hard criminal!
A fọwọ́ fà nìyí
Odaran ni egbon ati aburo wonyi. They are rapists and they should be punished accordingly.
Ironiwonpa Kinse akoko won niyen awon eyan radarada
Oloriburuku aye atorun in Iwo omokunrin yi, otun laya Latin gbaa leti, oni no ninu e lase edumare
Eo ni bo nibe
Ola ti Kaothara ti takoko yen
Egun buruku ni toba mo
Ai sun mo olohun to
Na tun wa kun
"highness " just try to explain this to the judge
Onibo ni be.oloriburuku omo.ewon loma ku si
Osejepe ogun state ni inkan buruku ti n ma sele ni gbogbo igba? 🤔 we all knw that in yoruba land nah ogun state ritualist full and many other things like this, se ogun state nikan Lowa nile yoruba ni?😢 why tie se ya alaburu eda bayii?
Oloriburuku ni Bobo yii. Ewon ni o ma kusi ati iwo ati Omo ale aburo re
Why this
This guy is so foolish with his narrative, he shot himself in the leg..let him face the consequences of his actions,so disgusting 😮
Hmm this guy lawyer try sha,,he keep defending his brother and saying he was under the influence of alcohol
They must be jail.
🐎
He acted under the influence of alcohol,no case ,ladies next time use your sense
Okay no problem .....but definitely your daughter will go through same situation. Ode
Too much now@@tayoolubode1931
So sad
These guys are well researched criminals 😂😂
It's this boy's don't know the consequences of what they do, they should be jail
HNNNNNNNNNN
JAIL PLEEEEEASE.... OLORIIBU NI AWON MEJEJI... THEY BOTH PLANNED TO BE RAPISTS IN LIFE NI...
This boy is a criminal they have be on this mess for long that can not be influence of alcohol
Ejowo ebami ra ( another Red Belt ) fun arakunrin yi ati aburo re, leyin igbati won ba mun tan, ki adajo bami fun enikookan won ni ewon ogota odun, ki won sare lo ki won bo pa.
Won ( plan ) fun omo yen ni, kosi awa wi, won ti nse tipe tipe, eleyi koni akoko
This one is stupid, they did it intentionally 😢😢😢😢
He is just giving excuse he knows what he is doing. he did those things deliberately
You are a criminal'enyan le see aburo tire bayii' ogun state shaaa
You guys are evil it's sad you are from same parent... The Law should take it's full course🙏🏾 una parent no try🙁😢
All lies........ Both brothers are rapist i want to first believe him that his brother's is innocent until he mention Kaosara, definitely they both always plan and chop same girls that's unfair 💔put him to jail where he will no longer see bullet again talkless of sleeping with innocent girls........