Ilẹ Yoruba Ni Ilorin

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 21 дек 2024
  • Laipẹ yí ni Sheik Abeeb ṣe wasi kan ni Ìlọrin pé Ilorin kiise Ilẹ̀ Yorùbá lèyí to tako ojulowo Ìtàn àti Ẹri.
    Baba Àfọ̀njá mẹta lo jẹ Balẹ Ilorin tẹle rawọn, 1. Láderin 2. Pàsìn 3. Alùgbìn lehin àwọn mẹta ni Àfọ̀njá jẹ Balẹ láti orí balẹ ni Àfọ̀njá tí jẹ Kakanfo nítorí balẹ ìlú lọ ma ń jẹ Ààrẹ Ọna Kakanfo nigbana abẹ Aláàfin Ọ̀yọ́ lo si wa pelu Basorun Gaa lọ pa Balẹ Ìlọrin kejì Pàsín.
    Aare Laji Abbas +2348023687432

Комментарии •