GOVERNOR BABAJIDE SANWO-OLU TUN TI SÈ TUNTUN OOO, EGBAWA IYA YI PỌ.

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 30 сен 2024

Комментарии • 12

  • @BiolaOpabola
    @BiolaOpabola 3 месяца назад +3

    Olorun ma deal pelu won ni n agbara Olorun. Sanwoolu ronu re wo dada e bi npa ara ilu, road ko dara, n ina ko si, ko si security. OLORUN a da ejo

  • @florencedairo3888
    @florencedairo3888 3 месяца назад +1

    Awon governors won ko Leke Lara Olorun lo ma se Idajo fun won. Eleven ko ni lo lai Ki ya. Olorun ni ,Olorun ni Olorun owo ni mi , ton be see Baba wo Lara omo titi de Iran keta ati ekerin ninu awon to fe mi, emi asi ma fi ani Han fun awon to nfi mi ti won si npa Olin mi mo. Olorun neon won. Gbogbo wahala ti Babajide Sanwoolu n fi ya je awon ara eko, on fi ti na. ti won, Olorun now won. A ko mo nkan ti Olorun nipa mo fun won. Won ti gba gbe Olorun, won ro pe won ma gbe titi aiye ni, Oma se o. Ava ni ki lo je fun enia to jere Gbogbo aiye to so emi re ni. E je ka ka fi Gbogbo re le Olorun, ti ori ohun Gbogbo, to si le se ohun Gbogbo. E ku eto .

  • @imoleadini
    @imoleadini 3 месяца назад

    Olorun lomo.dayin.lejo eleyi lagbara.olorun.osiwo awon.eyanyi.niran osibawa
    Daseria
    Fawon eleribu.awon asiwaju.wonyi.osrinkan.sesawon odaju.won komo bawa.faisan tiogbogun.dawon.laraya.tomotomo komobawa fiseranlowo fawon.yawo tiwon atawon.ebi kobawon.fise.itore anu.funwon.abi.eyiti wonnpeni.sanwolu koni eyitowo.ohan larare eyitoribi skeleto.yi esiberu.olorun.olorun mamuyin.nijokan.botiseke.biamuku osan

  • @susanadedokun265
    @susanadedokun265 3 месяца назад

    God did not give him the money he took the money that suppose to be for the use of the country foolish wicked men thank you my sister God bless you ❤

  • @AyomideIyanu-ez4vm
    @AyomideIyanu-ez4vm 3 месяца назад

    Eni ti Olorun ba fi anu si oju lose, ema yo ara yin lenu.

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp
    @RemilekunAdeleye-ew4dp 3 месяца назад

    SE BI AWON IYALOJA NAA LOHUN DIBO FUN

  • @AyomideIyanu-ez4vm
    @AyomideIyanu-ez4vm 3 месяца назад

    Ika ni gbogbo won, won lanu.

  • @estherewetuga8245
    @estherewetuga8245 3 месяца назад

    O lagbara

  • @tayoakoni6356
    @tayoakoni6356 3 месяца назад

    LadyK

  • @MichaelAlake-b3l
    @MichaelAlake-b3l 3 месяца назад

    Yoruba Nation no going back.

    • @ednafieoku5086
      @ednafieoku5086 3 месяца назад

      Odale ni Yoruba. It will be worse if we get Yoruba Nation. I don't know where we're going to. Heartless Sanwo olu