AGBA FULANI YI FI EPE RANSE SI OBA GHANDI TI ILU OGBOMOSHO

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 8 июл 2024
  • Awon Fulani yi ti wa di karanjongbon si ile Yoruba
  • РазвлеченияРазвлечения

Комментарии • 36

  • @Ogundeinola1
    @Ogundeinola1 22 дня назад +6

    Imam egba ati imam Ogbomoso ko ni da fun won

  • @aderibigbefelicia6906
    @aderibigbefelicia6906 22 дня назад +3

    Baba 10 10 eku eto. Ni okeoya,awon fulani won yi highest u can rent their place 5yrs,they will eject the person out beco staying there too long one day u will claim as part of the family and also claim their inheritance and exactly thats what they are doing.

  • @ahmedadeleke1722
    @ahmedadeleke1722 17 дней назад

    I remembered the songs the Fulanis they used to sing, It goes thus, "E ma pe wa lalejo mo, awa yin la ni ilu"

  • @vickyyorubanationnownogoin8787
    @vickyyorubanationnownogoin8787 22 дня назад +2

    Agbaya Fulani gbogbo epe ti Ose yio da sori awon omo re lati Iran kini titi de Iran kewa oloriburuku agbaya fulani eranko

  • @abayomiaboy2
    @abayomiaboy2 20 дней назад +1

    A Fulani man has the audacity to curse a yoruba king in Yorubaland

  • @sakamoses606
    @sakamoses606 20 дней назад +1

    That's why I like the ibos they will never allow this mixed multitude in there environment.

  • @martinadebowale3839
    @martinadebowale3839 19 дней назад

    Kabiye is thinking about his future and Yoruba roots I’m proud of him

  • @adetonaadesola6536
    @adetonaadesola6536 22 дня назад +2

    Interesting words

  • @yomibabalola5277
    @yomibabalola5277 22 дня назад +3

    WON A PE AWON ALALE FUN WON,... A DABI TI O BA JE ALEJO NI WON NI ILE YORUBA.

  • @richrich6950
    @richrich6950 22 дня назад +2

    Iro nii gbogbo e ko si ohun kohun , ogun ati awon alujanu ni baba yii nlo , Agbara Olohun ju won lo o. Awon ika eda very wicked tribe's Fulani

  • @solabolaji5364
    @solabolaji5364 19 дней назад

    Won ti tuuba lori ọrọ yii! Imam Ẹgba si ti pada gba adura fun Oba Ghandi. Ẹ jọwọ, e yee maa hu ọ̀rọ̀ ti o ba ti ku dide nitori alaafia!!!

  • @adefemiojokanke5222
    @adefemiojokanke5222 22 дня назад +2

    Is very painful

  • @ceciliabola1650
    @ceciliabola1650 21 день назад +1

    Ko si bi a se le se ebolo ko Ma rungbe Fulani ni e ri yen ki Fulani lo odun na mi n nale nile yoruba Ota aye ati torun ni won je fun omo Yoruba. gbogbo Alawo, Onisegun, Woli, bishop , bo le wa bo je yoruba si yoruba, e ti Ma na ara yin logun to won ni ri ewo re Fulani de bayi e le se ohun kohun.

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 21 день назад +1

    Agba rederede ni Imam Egba yi. Rederede naa ni baba Imam Egba yi ma baku Lase Edumare. Awon Agba ati omode won, oni jagidijagan ni gbogbo won

  • @adenikeayinla5231
    @adenikeayinla5231 22 дня назад +1

    Eleyi tun gao Baba Arole epe ti Baba Fulani yi se poju. Ki Eledua o gbe yoruba leke Awon fulani yi Ase.

  • @OlogundeEsther-lu2qs
    @OlogundeEsther-lu2qs 22 дня назад +3

    Se baba to to koku ti o ku amona orun ma lo

  • @ceciliabola1650
    @ceciliabola1650 21 день назад +1

    e ku ise Takuntakun Baba mi arole 10 10 onile a gbe yin ooo

  • @adefemiojokanke5222
    @adefemiojokanke5222 22 дня назад +2

    Ekueto baaami

  • @morufuhammed9248
    @morufuhammed9248 22 дня назад +2

    Baba mi eku eto sa

  • @aminuphilip1841
    @aminuphilip1841 19 дней назад

    Arakurin mi, ko tile si ohun to buru ti Soun Ogbomoso se. Mo ti so tele naa pe afaimo ki agbalagba radarada yi ma je iran fulani oun ati imaamu Ogbomoso, Mufuti iwo, Oluwo ati awon beebee lo. Iran fulani ni gbogbo won. Ise ibi won lati gba ile yoruba tipa-tipa nipase isilaamu ni won nse.

  • @SerahGibson
    @SerahGibson 20 дней назад +1

    Anti so TIPETIPE pe omo fulani ni yinise abi bawo ni ense pe ni Ogbomosho. Immamti e gbe wa si Ogbomosho, igbagbogbo ni anso fun nyin pe omo fulani.nibo ni enyin ,nle se iwo fun rare,sebi lara obinrin niwo na ti jade.Ti Olorun koba fun o se nko.Emura si,baba ni Agbara oba ti o laiye on orun, eo ni,roju raiye.pelu ase ti Olorun fi da orun on aiye,Yinusa koni je Imam Ogbomosho. Kise omo Ogbomosho, se ohun ti on se yi,a wa waninu ilu Ogbomosho.Eo ripe oju awon ara Ogbomosho nri gan ni.Sugbon momope ki se omo Ogbomosho. Sugbon ninu eyi eo kogbon ninu.re.

  • @tawakalitutayo3263
    @tawakalitutayo3263 18 дней назад

    E le bu Fulani to nsepe fun Oba ti e ba wo ohun ti olriburuku Oba Iwo nse e ri wipe won ti fi aye gba fulani koja oun ti a le so se awon Oba ti won pa Yoruba ti won so nkankan si nkan buruku ti awon fulani oloriburuku nse. Awa Yoruba la da a si ni ife ara wa.

  • @user-kk9vx6tb6j
    @user-kk9vx6tb6j 20 дней назад +1

    Baba were opolo baba ti yoro Please ignore him Ode

  • @iretiebiesuwa9071
    @iretiebiesuwa9071 22 дня назад +1

    E ku ise takuntakun Olorun a kuku saanu wa

  • @euniceadeleye7400
    @euniceadeleye7400 22 дня назад +2

    This is so pathetic, all his curses is back to sender lori ọba wa Ghandi Ọlaoye. Alalẹ a mu gbogbo yin, asiri yin o ni bo ẹyin fulani yi.

  • @AA-lx8zc
    @AA-lx8zc 22 дня назад +3

    A TRUE SON OF OGBOMOSHO WILL NEVER DISRESPECT SOUN'S THRONE....THAT ACCLAIMED IMAM IS NOT A SON OF OGBOMOSHO. THEIR PLAN IS TO FULANIS ED. HIJACK AND CONTROL OGBOMOSHO. IF OBA GHANDI DOESN'T ACT FAST, MORE DISGRACE ARE STILL COMING

    • @waleikujuni9463
      @waleikujuni9463 21 день назад

      Correct talk.
      Imam TOILET is a bastard in Ogbomosho. He is from Iporo Ake in Ogun State

  • @sakamoses606
    @sakamoses606 20 дней назад

    Please let someone get olarewaju adepoju record on edeaiyede.

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 21 день назад +1

    Imam TOILET 😂🤣😄😂🤣😄, omo ale ponbele ni Yunusa. He is from Iporo Ake in Ogun State NOT Ogbomoso indigene

  • @sakamoses606
    @sakamoses606 20 дней назад

    Gbogbo ntowukoje baba okinse Olorun moreso you are stranger in yoruba land bi eru bape Nile ajobi niwon bu.

  • @modupeolotu2918
    @modupeolotu2918 19 дней назад

    Epee ti won se lo ma pada le gbogbo awon agba agba fulani ati lori usman danfodio ati gbogbo awon omo yoruba ton gbabode ni won ma segbe ti won ma pare ma aiye ni Ase Eledumare. What is our concerns with fulani jihadist terroists Islamic caliphate in Yoruba lands, alale Yoruba will perish them all over their curses on the soun Ogbomoso. Usman danfodio will never have a rest wherever he is right now with all his followers/ofoo by the powers of all the Alale.

  • @user-dm2lm2dw2e
    @user-dm2lm2dw2e 22 дня назад

    E Se Atun Se bayi.

  • @Kabisanra
    @Kabisanra 21 день назад

    Please sir baba ti sadura fun baba wa soun oooo stop all this propaganda sir

  • @olaoluwaamoo9910
    @olaoluwaamoo9910 20 дней назад

    O mo olorun. Iwo baba yi iro lopa. Ko si nkan nto lese. O oto olohun! Eyan ni e osi jube lo