A ko gbodo tun ri iru Samuel Ladoke omo Akintola mo ni Ile Yoruba. Ifashein ayeraye ti o se si gbogbo omo Yoruba ko sehin “Akintola taku” ti o sele ni western house of assembly ni ipinle iwo orun Nigeria ni 1962. O di gbere, Yoruba ko tun ni ri enia bi Ladoke Akintola Amin, Amin ati amin.
Olorun ko ni je ki Yoruba tun ri iru Samuel Ladoke Akintola mo ni ipinle iwo orun not Nigeria. Amin ati Amin. Lately, certain uninformed man said that”Akintola did not betray Awolowo” The person is young and informed. The truth was: Akintola Betrayed Sons and Daughters of Yoruba race.
A ko gbodo tun ri iru Samuel Ladoke omo Akintola mo ni Ile Yoruba.
Ifashein ayeraye ti o se si gbogbo omo Yoruba ko sehin “Akintola taku” ti o sele ni western house of assembly ni ipinle iwo orun Nigeria ni 1962.
O di gbere, Yoruba ko tun ni ri enia bi Ladoke Akintola Amin, Amin ati amin.
Eku igbiyanju Oluwa alaanu julo yio sanyin lesan daradara Akintola akinkanju okunrin,sun re ooooo, Ogbomoso ko ni baje lase edumare ❤
Mansulo laya Olugbala Ajala Aagbe
OLOHUN YIO JE KI A TUN RI IRU AKINTOLA
Monife se iwadiyi gan ni ooooooo ni tori omo ogbomosho ni emiyi
Ẹ ṣeun, ẹ kú ìmọyì rẹ̀.
Ẹ tún bá wa tàn án sọ́dọ̀ àwọn mìíràn tí ẹ bá tún mọ̀.
When I young I take fruit in his house in ogbomoso masifa are to sabo ogbomoso then I was in ogbomoso DC primary school in 1977to1980
Kí Ọlọ́run ó tẹ́ wọn sí afẹ́fẹ́ rere
Ẹkú îsẹ tâkûñtâkûñ o iya wâ
Ẹ ṣeun púpọ̀ o
Rest on baba Samuel Ladoke Akintola…May God Almighty continue to bless your generations endlessly. Amen
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun o
Thanks for the updates and Bless you.
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o
Rest on Baba
Olorun ko ni je ki Yoruba tun ri iru Samuel Ladoke Akintola mo ni ipinle iwo orun not Nigeria. Amin ati Amin.
Lately, certain uninformed man said that”Akintola did not betray Awolowo”
The person is young and informed.
The truth was: Akintola Betrayed Sons and Daughters of Yoruba race.
Eyi dara pupo
Ẹ ṣeun púpọ̀ o.
Samuel Ladoke
Ẹ ṣeun púpọ̀ o ìyá wa pàtàkì
Your story telling was not cognitive , sorry