Aare Opitan, don't mind Prophet Ajipolowo Iku tantan, MKO "danidani kii banilagba kekere loti nbanilo". Ibanilorukoje ni awon fi gbajumo, oro e kiye lori baba ADEBOYE, OYEDEPO ati awon ijo nlanla miran. "Ori kii ri ara" koisanwo TIMILEHIN togba. Awon Pastor yin kiiri isele tofe sele koto sele, kiwon pe awon enia si akiyesi ki wahala to sele. Eyiti o ba sele niwon ma nriran si. Opolopo asotele won ofo lobade. Football prediction - F9. America Presidential Election - F9 etc. Kadupe lowo Tani Olorun toje kiwon ma jewo ewe ategbo pelu ofo ati ayajo ( incantation ) tiwonfi nkun Psalms sise oluwa. Kori awon yen so "Ariteni mowi afapadi boti e mole".
It still exists but the town has now been overtaken by weeds.it is well after Ilorin and close to Jebba in kwara state..the oyo ile today is being under some bandits as at today.
@@crownedking2567 since its after Ilorin and very close to Jebba by origin it is supposed tobe south west but because kwara state is under north central it is under north central.all those places Jebba and Oyo ile couldn't be up to 20km to River Niger.
E seun baami orisa itan. Ti ijoba ba se agbekele ilu daadaa, iru isele bayi ko ni po to be yen😢 Adaniwaye bawa tun okan awon obi na.
Aare Opitan, don't mind Prophet Ajipolowo Iku tantan, MKO "danidani kii banilagba kekere loti nbanilo". Ibanilorukoje ni awon fi gbajumo, oro e kiye lori baba ADEBOYE, OYEDEPO ati awon ijo nlanla miran. "Ori kii ri ara" koisanwo TIMILEHIN togba. Awon Pastor yin kiiri isele tofe sele koto sele, kiwon pe awon enia si akiyesi ki wahala to sele. Eyiti o ba sele niwon ma nriran si. Opolopo asotele won ofo lobade. Football prediction - F9. America Presidential Election - F9 etc. Kadupe lowo Tani Olorun toje kiwon ma jewo ewe ategbo pelu ofo ati ayajo ( incantation ) tiwonfi nkun Psalms sise oluwa. Kori awon yen so "Ariteni mowi afapadi boti e mole".
E ku ise opolo aare opintan, onibode ile yooba
Long life Aare Opitan
Aare Opitan,nibo ni location Oyo Ile nigba yen?
It still exists but the town has now been overtaken by weeds.it is well after Ilorin and close to Jebba in kwara state..the oyo ile today is being under some bandits as at today.
@akandesaheed3835 Thank you and again is the place or land still in the southwest?
@@crownedking2567 since its after Ilorin and very close to Jebba by origin it is supposed tobe south west but because kwara state is under north central it is under north central.all those places Jebba and Oyo ile couldn't be up to 20km to River Niger.
@akandesaheed3835 Thank you very much
Are Opitan you are also reading information that was written by someone. You can not be certain that they are saying the truth.