ewa wo bi Imam Ogbomosho se sadua ibere ni carnival Ati bose yipo abata ile ebo nje o ba Sunnah mu

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 31 янв 2025

Комментарии • 48

  • @matthewahisu1650
    @matthewahisu1650 21 день назад

    Se wọn fi ìró seyin ní

  • @Mirabik
    @Mirabik 29 дней назад

    😊Bobo yii, try ko beru Olohun. Ati ojo ti wa pade Olohun re o.

    • @sobowalet
      @sobowalet 28 дней назад

      Why not pray for this guy ... You should observe that he is not well. Pray for him to find perfect healing.

  • @sulaymanyusuff216
    @sulaymanyusuff216 Месяц назад

    Imam is right on

  • @ramotaabiolaraji1041
    @ramotaabiolaraji1041 Месяц назад +8

    Gbogbo bi e se n se ibaje Imam, bee ni oore Olohun n po si ninu aye won. Ibaje eniyan ko da ise Oluwa duro. Inshallah, Imam ni o leke gbogbo yin amin.

  • @BelloQomorudeen
    @BelloQomorudeen 28 дней назад

    Esin Islam esin ododo eniti o ba fe ko gbo.Imam nso ododo fun yin laibu enikeni

  • @ishaqayoola7663
    @ishaqayoola7663 Месяц назад

    Ibaje eniyan

  • @tiamiyuabdulateef9832
    @tiamiyuabdulateef9832 Месяц назад +1

    Emi o ri tabi gbo bi imam se sadura o.iro ni iwo okunrin yi pa mo imam.

  • @gafarabdulsallam9195
    @gafarabdulsallam9195 Месяц назад +6

    ODODO ORO NI IMMAM SO

  • @olasege
    @olasege 11 дней назад

    In every society, bastards who feel alienated or marginalized often resort to making disruptive or controversial accusations, seeking to instigate hates, chaos, and anarchy to attract attention for their grievances.

  • @olanrewajusheu7042
    @olanrewajusheu7042 Месяц назад +2

    May ALLAH continue to bless Imam Tolihat, the chief Imam of blessed Ogbomosho land

  • @AzeezSaheed-pu2mr
    @AzeezSaheed-pu2mr Месяц назад +1

    HAAAAAAA 😂😂

  • @adexadexd1
    @adexadexd1 Месяц назад +1

    Imam Ogbomoso na 2face.

  • @HamzatAjaniMuibi
    @HamzatAjaniMuibi 24 дня назад

    Ori boy yi tidaru ooo.
    Edakun nibo ni Imam tise Adura.nibi eleyi atipe ni Imam ti bawonjo..

  • @_Abdussalama
    @_Abdussalama Месяц назад

    People can repent and recant on what they've done in the past. You surely have that concept in your religion too.

  • @SuleamanLukman
    @SuleamanLukman Месяц назад +1

    Ejekia ranti atubotan o
    Leave Imam alone
    Let Allah judge him

  • @JamiuLawal-st5dc
    @JamiuLawal-st5dc Месяц назад +2

    Opolore tiyioro

  • @IbrahimFolohunso-np5yy
    @IbrahimFolohunso-np5yy Месяц назад +6

    Irọ tí báyé bọbọ yen jẹ 😅😅
    Opurọ gbáà ni

  • @odusholamargaret3115
    @odusholamargaret3115 Месяц назад +2

    Eku ise, Olorun a wa pelu yin. More wisdom In Sha Allah. Ogbomosho a gbe wa L'oruko Jesu. Awon alabosi loju ma ti lagbara Olorun.

  • @sundayoladimeji584
    @sundayoladimeji584 Месяц назад

    Epe yi naa ni shaa

  • @toheebadebimpe9321
    @toheebadebimpe9321 Месяц назад +2

    Eku ise

  • @shinaajiboye2929
    @shinaajiboye2929 Месяц назад +2

    Olorun ase idajo re

  • @andriykonila3206
    @andriykonila3206 29 дней назад +1

    Imam Yunus Toliat Ayilara The Second as come and he's comes to stay.... Long life too ologbomosho of Ogbomosho land ALH Dr Al Imam Yunus Toliat olusina Ayilara The Second 🙏🙏 Sheuuuuuuu Sheuuuuuuu

  • @UltimatumSavage
    @UltimatumSavage Месяц назад +1

    Werey oloribu or what do you call yourself.
    We can't see imam at where they are circulating the abata

  • @agboluajebolanle41
    @agboluajebolanle41 Месяц назад +1

    Eyin re to gbe omo pon yen oni lakaye rara, se ajodun ebo ni won hun se ni oponu, ohun to je ko je ko gbon rara

  • @leahayodele2526
    @leahayodele2526 Месяц назад

    OKUNRIN YI...ORIRE TI FOKA.

  • @AFESOMUENITANOGBONNUTAPA
    @AFESOMUENITANOGBONNUTAPA Месяц назад

    Oponu ni ogbeni imman yiii

  • @AzeezSaheed-pu2mr
    @AzeezSaheed-pu2mr Месяц назад +1

    IRO YI NAN NII 😂😂 KILODE

  • @oluwadamiOlajide
    @oluwadamiOlajide Месяц назад

    Jo se iwo je onisese ni abi baba Imam Ni ki won Mon se kanifa oje kuro nibi abosi

    • @wasiukehinde-xg9wg
      @wasiukehinde-xg9wg Месяц назад +1

      Must Imam join them before and he never preached against it but when the table turn round is now seeing at bad.
      Imam is not straight forward on so many.

  • @adewalejamiu8633
    @adewalejamiu8633 20 дней назад

    Please don't adress grand cheif of ogbomosho land again next time please

  • @SanoussiSalami
    @SanoussiSalami Месяц назад

    Odo Oro ni imam noso ki lode ti eya alabossi bayii inchallah awom omo re Oro alatako titi layelaye

  • @iskeelamolegbe3488
    @iskeelamolegbe3488 Месяц назад +1

    Na'am! Ija ILARA ni kii tan boro o!
    No 1. Awon video/pictures ti e fi han yi ko ko se atileyin oro Imam ti e n so nipa pe (a) Nibo ni Imam ti se Adua Ibere nibe?! Awon eegun la koko ri ti won n jo! Ao ri video Adua Ibere ati eni to see depo pe ao waa maa gbo bo se n se Adua naa!
    No 2. Ibiti e ni won ti n yipo Oosa Abata (abi kin le pee?), ao ri Imam nibe, sugbon a ri Kabiesi!
    So, ibaje Imam ti e fee se nibi yi ko wole rara! Then to ba je pe Carnival lasan ni won fee se, ko si ofin Islam to ta koo pe ki Imam ma se Adua ibere nibe o.
    Ka waa so pe Imam wa nibe looto ni, itumo to fun wa ni pe bi Imam ba so pe oun o le lo sibe (nitori esin toun), sugbon boya latari ase Kabiesi, eyin yi naa lee maa so pe o r'oba fin!
    Bi a ba sakieyesi gan n, Kabiesi paapaa ti a ri yi, inu won ko dun si nkan ti eon n se yi nitiri pe o lodi di esin won, sugbon won gba kamu nitori aayee won! Mo mo pe bi yoo se ri lokan Imam naa niyen ti Imam ba tie wa nibe rara!
    Sugbon pelu bi nkan se ri niisinyi, imam ti ja ara re gba, ko s'eni to le tie da aba lati fi iru e lo Imam mo depo pe won o so pe ko loo maa yipo okuta kan!

    • @adebowaleadeoye281
      @adebowaleadeoye281 Месяц назад

      Iwo ni o ri Imam. Awon eniyan ri Imam ti o yika abata.

  • @oluwadamiOlajide
    @oluwadamiOlajide Месяц назад +1

    Jo kini isoro re ti iwo omon ju ki omon pegan lo amon kojowa koju emon se abosi yin lo esan detan

  • @AzeezLawal-c1o
    @AzeezLawal-c1o Месяц назад +1

    Oponu ni iwo bobo yi se ebo ni caniva ni eku to no idi abosi

  • @gafarabdulsallam9195
    @gafarabdulsallam9195 Месяц назад +1

    IRO RE TI POJU

  • @gafarabdulsallam9195
    @gafarabdulsallam9195 Месяц назад +1

    ORI RE KOPE

  • @adelekeakinpelumi5211
    @adelekeakinpelumi5211 Месяц назад

    Ibaje eniyan kodase oluwaduro asebaje o nigbayi baba imam wahinnaju dana lahumuli galibuna

  • @abdulawwalabdulwasiuadewum5941
    @abdulawwalabdulwasiuadewum5941 Месяц назад +1

    Oponu nie oro oye e rara, continue.

  • @jimohabdulafeeza.5761
    @jimohabdulafeeza.5761 Месяц назад

    You are a liar. Is he refer to Carnival as ọdún ẹbọ. Àtúnbọ̀tán rẹ ni ki o ma ranti.
    From all what you showed where is the vedio where the Imam is praying at a carnival? Do you think you can turn false to truth. Well, end shall tell.

  • @TundeOladosu-g2e
    @TundeOladosu-g2e Месяц назад

    Rubbish talk, you don't have a job

  • @taofeekayeyemi469
    @taofeekayeyemi469 27 дней назад

    You're a liar.