EMI NI MO DA EGBE 12 MEMBER OGUN AJOBO AYINLA OMOWURA SILE NI EKO…

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 30 сен 2024

Комментарии • 4

  • @laoyesuleimanabubakar4753
    @laoyesuleimanabubakar4753 3 месяца назад +1

    Adebutu ni omo Ijebu, Ayoku kii se Ijebu omo Ede ni ore lawon mejeji ti won fi da Face To Face Pool kale. Awon ko lo win 75 pounds eni to mu Ayoku ati S.O.B. Babalola de Eko ( elder brother to Fatai Rolling Dollars ) lo win owo yen, eni naa je baba ore mi ti oruko won nje Olagunju.

  • @kazeemagbede2777
    @kazeemagbede2777 3 месяца назад

    Bomode kobe ba Itan Aba aroba.Aroba ree baba Itan

  • @abigailadebola
    @abigailadebola 2 месяца назад

    Jesu loluwa gbogbo awon omo Ogun.

  • @tobitobi3482
    @tobitobi3482 3 месяца назад

    Nice one ❤❤❤❤