Or maybe you couldn’t comprehend 🤷🏾♂️ He gave you principles it’s up to you to receive the message. May Olodumare unlock your mind and bless your ears.
Lotito ni pe"IFA"ti wa tipetipe.Sugbon eyiti a ko fura nipa"ESIN-OTITO TI ELEDA"ni pe,lati atetekose ti Eleda s'eda Adama eda-eniyan akoko,ni Eleda ti pase"ESIN-RE"fun pe,OLUWA OLORUN RE OKANSOSO NI,ON NIKANSOSO NI KI O MA SIN PELU IFORIBALE. "ASE-ELEDA"ni o de ori gbogbo eda-eniyan lori-ile-aye.(Deut5:7-10)(Q1:4). Eyiti a npe ni"esin-abalaye iseese"ni eyiti"ESU"ota akoko eda-eniyan fi gbe"asise-akoko"ba eda-eniyan lati gbe"ayipada"ba ase-Eleda nipa"esin-otito "ti Eleda palase. ASISE-ESIN MIRAN YI,lo gbe iparun ba"iru-omo Adama"lori ile-aye,ti o fi s'eku"NOAH". ASISE ESIN YI NA lo gbe"iparun-elekeji"ba iru-omo NOAH,ti o fi s'eku ABRAHAMU Baba nla wa,Abrahamu ni Eleda ba da majemu-orire,pe iru-omo re ni yoo kun gbogbo orile-aye,lati ma se"awokose-esin-Abrahamu Baba nla won ti o se dede pelu"ase-Eleda"ti o palase lati atetekose ni asiko"iseda-Adama". E JOWO SE ASE-ESIN-ELEDA LO SIWAJU NI,ABI ESIN-ABALAYE"IBORISA",EYITI ESU FI ROPO"ASE-ELEDA NIPA ESIN"LORI ILE-AYE???. ATIPE ASE TANI O YE KI EDA-ENIYAN TELE"NIPA ESIN"LORI ILE AYE?????. ELEDA LO NI ERONGBA NIPA ESIN,IDI NIYI TI KO FI GBA"IFE INU EDA" KOKAN LAYE NINU ESIN-OTITO RE,BIKOSE IFE-ELEDA FUNRARE. SUGBON ESIN-MIRAN TI"ESU"FI ROPO KO RI BE,OLUKULUKU NSE"IFE-INU-WON"BI O SE WUN WON NI.
Many are ignorant of the Holy IFA ORACLE
This guy avoided the question for the whole 18 minutes
its not everyone that knows how to answer questions accurately.
Or maybe you couldn’t comprehend 🤷🏾♂️
He gave you principles it’s up to you to receive the message. May Olodumare unlock your mind and bless your ears.