EYI NIDI TI KOLLINGTON KO ṢE LỌ SIBI OKU IYA WASIU AYINDE

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 5 фев 2025
  • Secreat revealed: Why Kollington Ayinla, Saidi Osupa and Obesere refuse to visit Wasiu Ayinde over his mother's death.

Комментарии • 23

  • @olajumokeaworeni5882
    @olajumokeaworeni5882 13 дней назад +3

    Saheed Osupa yoju si Wasiu. E fi Obesere sile, oun ati Wasiu ko gba ti ara won. Awon fans Wasiu ti fe pa Obesere ri. Lehin naa, nigbati late Olubadan fe fi Obesere je oye ni Ibadan, Wasiu sofun Late Olubadan pe kiwon ma fi j'oye. Nnkan ti Obesere se ko buru. Dandan koni ko lo ki Wasiu s'ile. E fi sile o jare.

  • @femiinu7435
    @femiinu7435 13 дней назад +3

    He does no have to go there, he has done well enough to send him condolences message via letter and it was well received and acknowledged. Besides it is non of anyone business how they relate with each other. They both understand themselves.

    • @mustaphaodeshina5111
      @mustaphaodeshina5111 3 дня назад

      I totally agree with you, if you roll back the treadmill, he Wasiu will do worst

  • @adelekeakinpelumi5211
    @adelekeakinpelumi5211 12 дней назад +2

    King Dr saheed osupa loki alhaji wasiu ayinde nile

  • @rasheedtiamiyu4717
    @rasheedtiamiyu4717 6 дней назад +1

    Ti Obesere o ba lo ki wasiu e fi sile, to baje o pa lojo si nko, se emama soro kiki ni, Toje emi naa ni Alhaji Killington naa ni mo le ma lo ki, eje ko ma lo be, eje ki oni kaluku ma se tie, ese.

  • @skullrawman9567
    @skullrawman9567 12 дней назад +2

    😂😂😂😂😂😂saheed de there now

  • @ElewaTaiwo
    @ElewaTaiwo 13 дней назад +1

    Obesere, has done well

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 14 дней назад +3

    Se Wasiu na faina fun olori ni ati pe ja gidi Jagan ni Wasiu

  • @MustaphaRauf
    @MustaphaRauf 13 дней назад +3

    Egbenu buruku soun. Osupa oba orin kosini ile. Oti lo.ki ni ojo Thursday 23 Jan 2025

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 14 дней назад +4

    Ki lo kan yin pelu pe enikan Ko lo ki Kl pe oku aseyin de iya re eyin agbo randun

  • @Childofmeci
    @Childofmeci 6 дней назад

    But o ye ki obesere lo iya meji o ki biyan

  • @richardogunmeru6790
    @richardogunmeru6790 14 дней назад

    God is able

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 14 дней назад

    We’re ni ohun Ki fi ile ohun sere se iWo gan Ko fi ile e wole lo ngbe iyawo e sori aye limata oponu

  • @orikemiariyike1208
    @orikemiariyike1208 14 дней назад +2

    Kosi eniti o mo boya o wa tabi ko wa
    Onígberaga oshi ni obésere

  • @BoiTobecz
    @BoiTobecz 10 дней назад

    EWO LOKAN WASIU AYINDE BO YA OBESERE WA A BI KO WA. EYAN TO WA TI POJU, IJOKO OBESERE KO YO SILE.

  • @KausaratAbeke
    @KausaratAbeke 13 дней назад +1

    Onilara ara lota babae ni wasiu

  • @sundayalex9628
    @sundayalex9628 13 дней назад +5

    Akede ariya should correct itself to stop saying what is not, Kollington never no2 to Barrister, they both started Fuji together and both are nio1. More so, Kollington said barrister created Fuji because Barrister no more alive and to lay everything to rest and allow peace to reign in Fuji music industry but in real facts Barrister never created Fuji

  • @OlaJide-f5w
    @OlaJide-f5w 13 дней назад

    Kilo
    Kanyin
    Wasiu
    Ayinde
    Ki
    Seyan

  • @juniorbrowne3768
    @juniorbrowne3768 8 дней назад

    You guys just talking rubbish

  • @ElewaTaiwo
    @ElewaTaiwo 13 дней назад

    Obesere, has done well