Allahu Akbar Raheemahulla Taala for Sheik Adam Abdullahi Al-ilory Ki Olohun ba wa se alekun ike ati ige fun Baba wa Ki Olohun ba wa se alekun emi gigun, alafia, ifokanbale idunu, arisilki, imo ati alubarika fun gbogbo eyin Alfa wa, Baba wa daada yi e se ku Bijahi Muhammad Rasulullahi SAW
Allahu Akbar
Raheemahulla Taala for Sheik Adam Abdullahi Al-ilory
Ki Olohun ba wa se alekun ike ati ige fun Baba wa
Ki Olohun ba wa se alekun emi gigun, alafia, ifokanbale idunu, arisilki, imo ati alubarika fun gbogbo eyin Alfa wa, Baba wa daada yi e se ku
Bijahi Muhammad Rasulullahi SAW
صلى الله عليه وسلم