History should be restored in schools in Yoruba Nation. It is very important to know the history of our roots. I always admire Prof Banji Akintoye talking about 1860,1890 etc. I will appreciate if we can learn from our father Akintoye before Jesus comes. I pray for long life and good health for our father. I pray that God will grant him success with regards to Yoruba Nation. Yoruba Nation a soju emi won.
Ifa is for real! No doubt about it! Yorubas have lost so much of its heritage, but thanks to Olódùmarè that we're coming back to Iṣẹṣe! Good information from Baba Solagbade!
Yomi falade Kini imo toni NINU esin IFA ko to ma bu ikin ni ekuro, Se eje jesu ni awon opori babanla nla e fi bi e, o se iwadi ara e komo itumo bi awon babanla e se se, Awon ti o ntele pe jesu , won je so ORO ti Iwo nso yi, won je ba won pe IFA lekuro, won mope otito lowa NINU esin IFA
@@yomifalade8690 Se o ri pe imo e kuru pupo ju, Nigbati kosi Eyiti o kan e nipa Oro IFA, ti o ni imo kankan nipa ti igbagbo okan e kosi nibe, kini on da si oro esin IFA si, Sebi bible ti on ka lo sope se iwadi oun gbogbo daju ki o si do otito ibe mu, kini iwadi ati imo e nipa esin IFA, IWO o omope ologberi ti oba nbu ikin IFA ni ekuro awon ijogun Orun lonja iru won logun Kosi Eyiti Okan e nipa esin IFA, tori e koya pa enu mo koma ba Jeki awon Irunmale ba e jaa, Sebi Falade ni awon BABA yin Nje, ose peni jesu lade, ai mokan lonba e ja, Awon to mo Nkan ti ifa je NINU Awon alagba ti iwo ntele ti ejo npe jesu koni ba e so iso kuso lenu
Wow!!! Baba oluwo popoola is my father and my mentor. God bless you daddy
History should be restored in schools in Yoruba Nation. It is very important to know the history of our roots.
I always admire Prof Banji Akintoye talking about 1860,1890 etc.
I will appreciate if we can learn from our father Akintoye before Jesus comes. I pray for long life and good health for our father. I pray that God will grant him success with regards to Yoruba Nation.
Yoruba Nation a soju emi won.
Olorun atunma waa pelu yin baba.
Ifa is for real! No doubt about it! Yorubas have lost so much of its heritage, but thanks to Olódùmarè that we're coming back to Iṣẹṣe! Good information from Baba Solagbade!
This is very interesting and should be made as part of our studies in some of Yoruba courses in the University
Ifa is pre-Old Testament divination probabilistic game theory with mythical poetry embellishment.
1. Eyin oni'fa, e lo ye'ro pa,
ekuro kii s'oro (2ce)
eyin oni'fa, e lo ye'ro pa.
ekuro kii s'oro
Can you imagine the scrapping of history in our educational curriculum? It was deliberate by the Northern hegemony!
P
So where can we go and learn this ifa?
Ibeere fun Posi ati AdeSquaredT: Nje igbala ayeraye wa ninu ifa sisin?
1.Posi o ni ku, Posi ko ni run, Posi ko ni fi Jesu sile, ko tun lo b'orisha.
O d'ade o, Olatubosun d'ade ogo jingbinni (2ce).
Yomi falade Kini imo toni NINU esin IFA ko to ma bu ikin ni ekuro, Se eje jesu ni awon opori babanla nla e fi bi e, o se iwadi ara e komo itumo bi awon babanla e se se,
Awon ti o ntele pe jesu , won je so ORO ti Iwo nso yi, won je ba won pe IFA lekuro, won mope otito lowa NINU esin IFA
@@ifaniyiawoyemi3962
`1. Eyin oni'fa, e lo ye'ro pa,
ekuro kii s'oro (2ce)
eyin oni'fa, e lo ye'ro pa.
ekuro kii s'oro
@@ifaniyiawoyemi3962 Eje Jesu ni awon opori babanla mi fi bi mi, eje Jesu naa ni a si fi gbamila o. Igbala ko si ninu ifa.
@@ifaniyiawoyemi3962 Eje Jesu ni awon opori babanla mi fi bi mi, eje Jesu naa ni a si fi gbamila o. Igbala ko si ninu ifa o.
@@yomifalade8690 Se o ri pe imo e kuru pupo ju, Nigbati kosi Eyiti o kan e nipa Oro IFA, ti o ni imo kankan nipa ti igbagbo okan e kosi nibe, kini on da si oro esin IFA si,
Sebi bible ti on ka lo sope se iwadi oun gbogbo daju ki o si do otito ibe mu, kini iwadi ati imo e nipa esin IFA,
IWO o omope ologberi ti oba nbu ikin IFA ni ekuro awon ijogun Orun lonja iru won logun
Kosi Eyiti Okan e nipa esin IFA, tori e koya pa enu mo koma ba Jeki awon Irunmale ba e jaa,
Sebi Falade ni awon BABA yin Nje, ose peni jesu lade, ai mokan lonba e ja,
Awon to mo Nkan ti ifa je NINU Awon alagba ti iwo ntele ti ejo npe jesu koni ba e so iso kuso lenu