Ejowo se muyideen sope oreowun ni enitiosope owunleta agbala Gabriel gbogbo iwatosinwu o jomobe bi eniyanbari muyideen kienina kiogbagi relay nitori alakoba ni muyideen ko sick olowun monkan tiounse , ki oluwa olorun awon omo Ogun koduro ti Agbala Gabriel amin ni oruko jesu
Please, Mr. Banuso,mo ri show ti Pastor Ademola se recently nipa Arabirin to bi omo si clinic won ,ti oko re wa ni life imprisonment, ewon gbeere, mo ri pe okan Agbala Gabriel se iranlowo yen sugbon gbogbo nkan ti o lo lowo yi ko je ki won fe se iranlowo yen fun arabirin yen hun̈nnn,e so fun Pastor Ademola Gabriel pe ki won ma dawo oore sese duro oooo, Olorun nwo okan eniyan loma nwo oju ooo,He should continue his good work that he is doing and Almighty God shall strengthen him. Please tell him,mo ti nwa Ona ti mo ma fi ba Agbala Gabriel soro nigbati gbogbo rogbodiyan ti sele but i am very happy that through your platform ni mo ti ni opportunity lati so oro yi please sir e jeki won ri nkan ti mo ko yi nitoripe gbogbo nkan to sele yi Olorun momo jeki o sele ni o lati dan igbagbo won wo ,ki won fi ija fun Olorun ja ki won fi owo leran .tell him to leave the battle for God to fight it.Olorun a wa pelu eyin o Ire ooo.
Kosi ohun to kan wa pelu muideen afibisuoloore. Agbala Gabriel ko ni jabo l'agbara Olorun. Iwo naa ,o nii jabo. Amin. Muideen si nja pelu pastor ati Baba Kola Olotu.
Baba e ku lakaii ohun ti o n se egbon yen ogun ni abi ki eyan mape tori ohun ti e ye ki enian awon ikan merin yen lafi abosi si niwaju olorun ti gbogbo wa gbin yin fun sugban ni agbara olorun won ma bori ogun ni oruko jesu Amii baba ogbun ko ni lori yin
Işę buruku ni Muyideen nşe labę bridge, o fi charger boju ni, awon ole awon amugbo ni won jo nrin, iwa yęn şi wa lara ę, okan ę gan ko kuro nibę. Ęmi buruku kan ti tibę wonu aiye ę. Awon Alfa yęn gan o save lowo Muyideen.
Not only you my brother ,I even said it I swear... It's not the suffering that turned him that way , even not the drunk, plus 40 ... Not possible, even you don't have a father, mother and relatives. You can't be like this unless something is underground... 40 Years of age with that look, that's STRANGE!!!
Banuso o Ku lakaye o sinle nitotoigbati Pasto ATI muideen pe yin ni Reese wako Orin lgbeyawofun sugban iya muideen ATI afare ti jabo olorun agbala Gabriel soke eyin ATI idile yin koni damu loruko jesun
Muyideen is just not a straight forward person, and there are some strong people who are looking for agabala gabriel downfall that are behind all this things,muyideen is not acting on his own interests people are behind this,olorun atun asiri gbogbo odale eniyen.
Iya na lowa ntele muhideen ki ri lo ni iya muhideen ko ni ife muhideen rara o ntele lati tu bo ba ti e je ni ki ise ife ni iya muhideen ni si rara my brother
IN THE RIGHT SENSE OF IT, E JE KI. A WA NINU EMI , MR BANUSO, KIISE GABRIEL LO NBA MUYIDEEN SORO LOWO LOWO NI OJO YEN, OLOHUN LO DE SINU AYE MUYIDEEN NI OJO YEN , OJO IBAPADE OLOORE , ISE IYANU OLOHUN NI EYI, ONA ARA NI OLOHUN MAA NGBA SE ISE IYANU NINU AYE ENITI O FE RAN LOWO, TI E BA KA BIB DAADA, AWON ANGELI KAN WA TI OLOHUN NGBE ISE OMO ENIA LE AWON ANGELI YI LOWO, MALEKA ANGELI GABRIEL , TI AGBALA GABRIEL JE ORUKO MO TI O MAA NGBE IRE KO ENIA , TI OLOHUN RANSI AWON KAN NINU BIBELI LATI KURO NI IPO AGAN, DI IYA OMO.NI OLOHUN AKIRI SOORE RAN WONU AGBALA GABRIEL. NI OJO ITUSILE NINU IDE SATANI TI MUYIDEEN. WA NI OKO NA LATI SE OORE OJIJI FUN MUYIDEEN, BI MAGIC GABRIEL GBE SAYE AWON ALAANU, TI OLOHUN FOWO TO OKAN RE SARE DAWO FUN, O DI LANDLORD OJIJI ,O DI ONI SHOP LAIRO TELE , O TUN DI ONIYAWO LAINI ONE NAIRA, HAA! ADUN SE BI OHUN TI OLOHUN LOWO SI, SUGBON. OMA SEE OO, MUYIDEEN FI OWO ARA RE YI IRE AYE DANU PELU AWON OMO ASITANI TI WON ROGBA YII KA.
Banuso gbogbo wa lo mo pe agbala Gabriel SE itanlowl gun muideeen amonsa e o Soro nipa no agbala Gabriel SE n na muideeen nitoripe o ran ni owo SEbi igbati Iwo gan de Odo agbala Gabriel SE Ofi egba na e ni ? Ori gbogbo yin ti daru e Fe Kona agbala Gabriel. No gbogbo yin oju aye lense oba Soro SI iya e lolokan yin ofale6 no gbogbo yin e kosiloo e ti ya xet6
Ori grandfather e ope raraa Ori siwin kilode ti gbogbo yin o kinsoro nipa bi agbala gab6 SE nna muideeen mo? Haaa eyin Yoruba to ba je odale e oni sorire
Muhindeen is an Ibadan and that’s how they use to talk in comparison he never meant to sell him nor anything but trying to let him know then that he was well ok
Ekueto alagba banuso owuñ koni Ku moyin lenun omashe obinrin koleda toju omo okunrin Iya muyidini lobaje olorun Eledumare awapelu àwon omo wao kolobe Iya muyidini GBA adura fun ko lobe àgba gebureli ki olorun dariji onidi ITU silent
Please, my brother Banuso,tell Agbala Gabriel to continue what his doing it is God's work,real God's work, and pastor Ademola is facing temptation now, O de ti bori gbogbo adanwo yen so please e so fun ko te siwaju pelu ise ti Olorun ran ki o wa se ki o ma ba jebi lodo eni ti o ran ni se ,
Ejowo se muyideen sope oreowun ni enitiosope owunleta agbala Gabriel gbogbo iwatosinwu o jomobe bi eniyanbari muyideen kienina kiogbagi relay nitori alakoba ni muyideen ko sick olowun monkan tiounse , ki oluwa olorun awon omo Ogun koduro ti Agbala Gabriel amin ni oruko jesu
What a wisdom Banuso! That is why I love ur songs.
E ku lakaye ,oro leso ooo c
God bless you sir ,he truly need to pray for mercy and God will help him .
Please, Mr. Banuso,mo ri show ti Pastor Ademola se recently nipa Arabirin to bi omo si clinic won ,ti oko re wa ni life imprisonment, ewon gbeere, mo ri pe okan Agbala Gabriel se iranlowo yen sugbon gbogbo nkan ti o lo lowo yi ko je ki won fe se iranlowo yen fun arabirin yen hun̈nnn,e so fun Pastor Ademola Gabriel pe ki won ma dawo oore sese duro oooo, Olorun nwo okan eniyan loma nwo oju ooo,He should continue his good work that he is doing and Almighty God shall strengthen him. Please tell him,mo ti nwa Ona ti mo ma fi ba Agbala Gabriel soro nigbati gbogbo rogbodiyan ti sele but i am very happy that through your platform ni mo ti ni opportunity lati so oro yi please sir e jeki won ri nkan ti mo ko yi nitoripe gbogbo nkan to sele yi Olorun momo jeki o sele ni o lati dan igbagbo won wo ,ki won fi ija fun Olorun ja ki won fi owo leran .tell him to leave the battle for God to fight it.Olorun a wa pelu eyin o Ire ooo.
Kare omo Ondo toto ni e go on banuso I'm with you
Oti ta pastor Amusan fu gbogbo aye .
Olorun lo gba pastor Gabriel .
Kosi ohun to kan wa pelu muideen afibisuoloore. Agbala Gabriel ko ni jabo l'agbara Olorun. Iwo naa ,o nii jabo. Amin. Muideen si nja pelu pastor ati Baba Kola Olotu.
Baba e ku lakaii ohun ti o n se egbon yen ogun ni abi ki eyan mape tori ohun ti e ye ki enian awon ikan merin yen lafi abosi si niwaju olorun ti gbogbo wa gbin yin fun sugban ni agbara olorun won ma bori ogun ni oruko jesu Amii baba ogbun ko ni lori yin
True Talk Indeed.God Bless U And Ur Family.God Bless Ur Banuso Ministry.Amen IJMN.
Olorun ti nfi muideen ati awon alfa e sesin. Won ti l'ule. Hoobi won.
Olorun oba a ma te yin siwaju si. ogbon ori yin ko ni dibaje lagbara olorun.e si ku lakaye
Banuso. thank you for your wisdom and many God continue to bless you my dear ♥️ ❤️ 😘
Oro gidi,leso thanks my brother
You're rite my dear brother god blessings you and your household mr banuso i love you so much sir 💔💔💥🌟💖👍🤩🥰💪🌟🥰😍🤩💕⭐
True talk mr Banso God bless you
You have spoken well my brother and God will heal Muyideen in JesusName.
I love you bro you’re so funny with the course of the Ogun stuff
God bless you banuso more knowledge in Jesus name AMEN
Muyideen ni aarun opolo 💯
Is that not that same woman following him around against the man of God now 🐎you’re 100% right 👍mo pity lady to fe 😂
Hmmmmmm. Egbon that is perfect said true talk
Ori e pe Banuso and God will give you wisdom that surpasses all understanding IJMN .
God bless you my brother
😂😂😂😂 i love the way you talk...
Muideen lo le mo nkan to se ohun oooo, banuso u talk sense but muiden ti se eleda re oti se olorun , e ku oye agbekale
Işę buruku ni Muyideen nşe labę bridge, o fi charger boju ni, awon ole awon amugbo ni won jo nrin, iwa yęn şi wa lara ę, okan ę gan ko kuro nibę. Ęmi buruku kan ti tibę wonu aiye ę. Awon Alfa yęn gan o save lowo Muyideen.
A da fun e
Best comment ever 🤔
Oro loso okulakaye
God bless you sir more wisdom and understanding
Odo oro! I knew that Muyideen was not 💯 % there from day one. You are absolutely correct. GOD BLESS YOU.
Thanks, Mr Banuso God bless you.
Yes you have a point
Thank you for dis post. U have given him d steps to take, let d wife and relatives do something before it is too late
Thank you, my brother. Ogun idile wa lara Muideen jare.
😂😂 banuso you can't kill me...ogun ile lo un ja muimui ole oloju jokoro
Muhideen mumu were alailope alailopolo didinrin eni ile ti won kii te eni fun alailope elenu jagajaga An ungrateful soul
God will be with you in Jesus name I love you so much more anything than Sri ❤❤❤
Great talk like your statements
We love Agbala and we all praying for Agbala.
Muyideen dabi judasi isikariot,ti o fi Jesu han .
Ọmọ loogun, oigho ẹ pe jae😂
More wisdom brother mi 🙏🏻
Ekimogun
God bless you Banuso.🎉
Banuso Oriekonidaru Ountimomabainumisnye sgbaan mamaye
Not only you my brother ,I even said it I swear... It's not the suffering that turned him that way , even not the drunk, plus 40 ... Not possible, even you don't have a father, mother and relatives. You can't be like this unless something is underground...
40 Years of age with that look, that's STRANGE!!!
True talk.
But God will judge muideen let God judge him.
Banuso o Ku lakaye o sinle nitotoigbati Pasto ATI muideen pe yin ni Reese wako Orin lgbeyawofun sugban iya muideen ATI afare ti jabo olorun agbala Gabriel soke eyin ATI idile yin koni damu loruko jesun
I have said it before that Muideen is sick upstairs he is not normal thank you my brother
Muyideen is just not a straight forward person, and there are some strong people who are looking for agabala gabriel downfall that are behind all this things,muyideen is not acting on his own interests people are behind this,olorun atun asiri gbogbo odale eniyen.
Iya na lowa ntele muhideen ki ri lo ni iya muhideen ko ni ife muhideen rara o ntele lati tu bo ba ti e je ni ki ise ife ni iya muhideen ni si rara my brother
Good analysis, God will bless the pacifier. Amen
Truth great talk
I like your perspective on this matter.
Oju kokoro ati ole lo nda Muyedeen laamu . He said people are telling him that he’s supposed to be a millionaire and not living as he is.
God bless you
IN THE RIGHT SENSE OF IT, E JE KI. A WA NINU EMI , MR BANUSO, KIISE GABRIEL LO NBA MUYIDEEN SORO LOWO LOWO NI OJO YEN, OLOHUN LO DE SINU AYE MUYIDEEN NI OJO YEN , OJO IBAPADE OLOORE , ISE IYANU OLOHUN NI EYI, ONA ARA NI OLOHUN MAA NGBA SE ISE IYANU NINU AYE ENITI O FE RAN LOWO, TI E BA KA BIB DAADA, AWON ANGELI KAN WA TI OLOHUN NGBE ISE OMO ENIA LE AWON ANGELI YI LOWO, MALEKA ANGELI GABRIEL , TI AGBALA GABRIEL JE ORUKO MO TI O MAA NGBE IRE KO ENIA , TI OLOHUN RANSI AWON KAN NINU BIBELI LATI KURO NI IPO AGAN, DI IYA OMO.NI OLOHUN AKIRI SOORE RAN WONU AGBALA GABRIEL. NI OJO ITUSILE NINU IDE SATANI TI MUYIDEEN. WA NI OKO NA LATI SE OORE OJIJI FUN MUYIDEEN, BI MAGIC GABRIEL GBE SAYE AWON ALAANU, TI OLOHUN FOWO TO OKAN RE SARE DAWO FUN, O DI LANDLORD OJIJI ,O DI ONI SHOP LAIRO TELE , O TUN DI ONIYAWO LAINI ONE NAIRA, HAA! ADUN SE BI OHUN TI OLOHUN LOWO SI, SUGBON. OMA SEE OO, MUYIDEEN FI OWO ARA RE YI IRE AYE DANU PELU AWON OMO ASITANI TI WON ROGBA YII KA.
Very true talk my brother
God bless you 🙏🙏🙏
😂😂😂😂
Hunnnn Ododo oro ❤❤❤
Ban u so well done jare, muideen has serious problem, his Alfa will help him out when they finish his house money
The mother should caution him
Banuso gbogbo wa lo mo pe agbala Gabriel SE itanlowl gun muideeen amonsa e o Soro nipa no agbala Gabriel SE n na muideeen nitoripe o ran ni owo SEbi igbati Iwo gan de Odo agbala Gabriel SE Ofi egba na e ni ? Ori gbogbo yin ti daru e Fe Kona agbala Gabriel. No gbogbo yin oju aye lense oba Soro SI iya e lolokan yin ofale6 no gbogbo yin e kosiloo e ti ya xet6
Fortunately He sold Agbala Gabriel to more glory 😂😂😂😂
He has actually sold him.
Omo oro gidi ni on soo shugbon were gidi ni muyiden 101 ni were ikan ninu ni ti muyiden agbala gabriel rope oun male tojuu ni oun na mon pe were ni
More wisdom bai
Banso, Oro le so loto, sugbon awon Kan lowa nidi Oro yi ti won nti Muyideen.
Yes, Muideen needs medical evaluation. ❤❤❤❤❤
Proverb 17_13
You are right Banuso.
Banuso okulakaye orolonso fun enitoni lakaye tobaniwereni kosironibe babasini ayeninse ododo oroni
Good analysis sir😅
Ori grandfather e ope raraa Ori siwin kilode ti gbogbo yin o kinsoro nipa bi agbala gab6 SE nna muideeen mo? Haaa eyin Yoruba to ba je odale e oni sorire
Mr Banuso, oro le so jare, opolo yin ko ni doba, ko si nkankan mo fun muideen o ti fi oju oloree gun gi
True talk ❤
Eni toba ni opolo ati emi Olorun lole ronu bi ese hun soro yi
Awon alati leyin omo kunrin yine ni ero min lokan eyan bi ni won
My brother am also thinking in that direction God bless your wisdom ,he truly needs help
Uuuuuuuuuuu, Oto Oro lesooooo
Omo dada ni iyawo re,banuso.
O ti yeye iya re,idi to fi nse ranran ni yi,
Iwa iya re lo mu,owu ti iya gbon lomo o ran.
Were alaso ni Muyindeen. Oloriburuku omo ni
Se bi iya na lo tun tele kakiri yi . nkan se iya Muyideen na pelu .
Muhindeen is an Ibadan and that’s how they use to talk in comparison he never meant to sell him nor anything but trying to let him know then that he was well ok
Eni ti o le Insult Iya e, in public, tani muyideen o ni le baje?
Otito oro leso❤
What he said from day one. Is what he end up done. (Mo lee ta yin) He finally sold Agbala to the world.
To be frank koni emi arojinle ni oooo
Brain jibiti lo WA Lori Muheeden bodija. Oore ko ni ko ba wa😂😂😂
👍👍👍👍
E ne opolo
He's needs prayers, omologun you are welcome..
Audra ni oro re kan ki ori re ma ko Adura
Ekueto alagba banuso owuñ koni Ku moyin lenun omashe obinrin koleda toju omo okunrin Iya muyidini lobaje olorun Eledumare awapelu àwon omo wao kolobe Iya muyidini GBA adura fun ko lobe àgba gebureli ki olorun dariji onidi ITU silent
He look so shady 😡 bro more wisdom sir 😂🙏👍
Muyideen ki se were. Sugbon ko ni 'atigbo' ninu aye re.
Nkan to kàn ni kiwon lo wo muideen san o
Ete ati abuku lo kan fun muyideen..
Be ran lowo yio tun se aburu si.
E wo muideen o normal jare
Ojo ajent soka
Banuso eorantipe o sope ojabaranda lowunta otunmosi oja arumoje
Muideen is not well from
Please, my brother Banuso,tell Agbala Gabriel to continue what his doing it is God's work,real God's work, and pastor Ademola is facing temptation now, O de ti bori gbogbo adanwo yen so please e so fun ko te siwaju pelu ise ti Olorun ran ki o wa se ki o ma ba jebi lodo eni ti o ran ni se ,
Ese pupọ Ọgbọ́n Ọlọ́run koni fi yín silẹ o