Ẹku isẹ takuntakun, baba. Eledua yíò ma fún yín ṣe o. Ẹjọ́wọ, leyin ti aba ti fi atare ajah nu ara, se ao bo ewe ẹkọ yi ki ato ki atare ajah yi sí àrin ẹkọ nán? Ewe ama jẹ o.
Ẹkú iṣẹ takuntakun, bàbà. Ewé ama jẹ. Awọn onilẹ at'iyin lẹyìn. Àmín àṣẹ. Lẹyìn taba fi Atare Aja mu ara tan se ao bó Ẹkọ ki ato ki Atare Aja nan sínú ẹ? Ati pe se ao tun fi ewe Ẹkọ bo pada?
E se adupe o olorun oba eledumare yoo bawa Sanu eyin na Amin ase o.
OLOHUN YOO JE ki E GUN LEMI FUN WA BABA PELU ALAAFIA ARA ATI ARISIKI OPOLOPO
Esun baba yo dara😂fun yin sir
Oba oke yoo ma gba fun yin , ewe a ma je fun yin lase oba oke .
Eledua yio ma ran yin lowoo baba
Eejo se alefi ina gas joo ise yii
Ẹku isẹ takuntakun, baba. Eledua yíò ma fún yín ṣe o. Ẹjọ́wọ, leyin ti aba ti fi atare ajah nu ara, se ao bo ewe ẹkọ yi ki ato ki atare ajah yi sí àrin ẹkọ nán? Ewe ama jẹ o.
Ese pupo sir, a ma ju yin se
Ẹṣe sir.
Baba e sun pupo
Ate yin ati awon omo ti ebi
Eoni se sin keyin aiye ooo
Baba a ju se ,okeoke lowo yin ma lo.mo fe Ogun cataract sir.
Thank you sir olorun abami dupe fun yin oo Amin
E seun adupe sa, adura to yin na agba lase Eledumare
Koni bajee fun yin baba ewe amaje oooooo eseun baba
Adupe lowoyin sir, olorun a maa wa pelu Yinoooo , ejowo se gbogbo irawo lo le loo ise yii
Bẹẹ nio
Amin Baba mii
Baba mi, nibo ni ègbé ni ilu cotonou
Ẹkú iṣẹ takuntakun, bàbà. Ewé ama jẹ. Awọn onilẹ at'iyin lẹyìn. Àmín àṣẹ. Lẹyìn taba fi Atare Aja mu ara tan se ao bó Ẹkọ ki ato ki Atare Aja nan sínú ẹ? Ati pe se ao tun fi ewe Ẹkọ bo pada?
O8 my wife has
Thank you so much sir
Thank you sir
A dupe sir
I really like listening to you.... But dnt understand yoruba dat much...
Thank you sir