Our Bobby ekuise, Oluwa koni fiyinnsile. Amin Iba 'nafelefe, Iba sare wa wo Bobby. My husband and I added it to your name because you always explained iroyin to us very well, and my husband always called me to come and watch Ogbeni Bobby Baba wa Mico Ade loko 'mi o mo pe oju ogun laye
E ku ise o Ogbeni Bobby, Iba iroyin Funwontan. I always enjoy your unique presentation of news laced with humor and old time songs . Yoruba Nation: Aluta continua, Victoria a certa.
Ogbeni Bobby, a dupe ana oo,I listened to your response and well understood. Micheal Ade, a native of Ikere Ekiti, waxed the cassette. A ku ipamo Odun sir.
Well-done sir bobby, awon musician ile hausa niyen, won kiise onibara. Emefielle, esi ebi to pa awa omo nigeria laye NO CASH laye buhari niyen. Alaini ojuti ore tongba oko ore e. Sisi, OLUWA yio gbe ija yin. OODUA NATION, NO GOING BACK.
Ahhhh 😮, Emefioole, Yibooo, Se o fe gba Ijoba mo Olorun lowo ni, Kilode gan, Erii Okan yin ti kuu patapata, Ikun yin je Ogede, koo mo pee ohun to dun nio paakun, Esinsin yin pada kuu sori otii nii, Nitori Iwo na ti daa Emii awon eniyan legbodo, O nii ni Alaafia fun gbogbo Igba to kuu fun o laaye, O si tun ni baa Oju rere Olorun pade laelae ,Koni yee o laaye ati lorun, Aameen, loofu yuu my Brother ❤❤❤ Salaam
Ogbeni Bobby, I laughed and laughed But the man forget the Seven virgin. The Northern part of Nigeria were becoming jester the way they were thinking is no sense atall.Yoruba Nation No Going Back. Emefele needs to come out and confirmed this allegations 753 houses Na waa o..this is to much. ❤❤❤😂❤❤❤❤.May Almighty God helps US to Actualized our liabration. Thank you and God Blessed.
Ogbeni Bobby se eri Emefele ati gbogbo awon Oloselu Olori buruku wonyi IYA MAJE AROMO DOMO LAGBA OLORUN. YORUBA NATION LAWA FE OLORUN SI MAGBA FUN WA❤❤❤❤
❤cheese 😂, Mo ki yin Oo Ogbeni Bobby èku ise oo. inu wa ma dun ti abati ngbó iroyii yin. Adun ni ngbeyin ewuro Adun ni ti yin ni òjò gbogbo ni oruko Jesu Amin. Eniti o korin yèn ni (Micho Ade) ❤❤God bless America yoruba Nation no going back Yeye oge from Dallas
Good evening sir Ogbeni Bobby, eku ise takun takun, God Almighty will continue to strengthen you, the song mi o mo pe ogun laye was composed by Micho Ade.YORUBA NATION NO GOING BACK
Ogbeni Bobby Orin to lagbara gidi ni o, a fi ki Olorun ja ija yi fun wa ni.Ogun teeyan o ri Olorun lo le ja fun wa o "Micho Ade" lo ko Orin yen o. Yoruba Nation no going back.
Iba yannana, Imoran temi ni wipe,ki Ife oko ati iyawo je ojulowo, ki awon mejeeji ma faaye sile fun alagata, ki won ye fura odi si Ara won, ire o. Kasun layo, kaa ji ni segun.😍
Ogbeni Bobby ati Aya eku ise takuntakun Oluwa yio wa pelu yin ise yin yio lere,fun ra won noma fun ra won Logun je . Yoruba nation lafe now now now now now now
Emefiele eleyi oda rara, Iwa ika gba ni eleyi. Tinubu mo nkan to nse. On wa ija awon Hausa ni. Ofe ki won binu nitori laise wipe won binu oma difficult fun Tinubu lati gba Yoruba nation. Olorun malo Tinubu fun wa. Yoruba Nation no going back. Eku ise takuntaku Iba Bobiskoko
Ogbeni Bobby Kare.Omo Iwo Olodo Oba ti Biden koba padon omo re oju ti baba lawo ti omo re kun ni osan gangan IBA IROYIN MABA ISE RE LO YORUBA Nation No Giong Back
Ogbeni Bobby e ku ise takuntakun o Se e ri Emefiele Barao Bansa ni , won o ti tu isu de isale ikoko Emefiele estate miran wa nilu e . Ki Olorun gba Yoruba Nation fun wa good night
Good sir bobby, IBA YANNANA, awon hausa ati awon fulani osi maa tan ara won lori oro oti mimu ati tete tita, teba ri ibi ti awon eniyan yi ti ngego tabi ta tete, wallahi eo ni believe. OLUWA yio se ejiola ni riri alubarika ikunle abiyamo 🙏. Uncle teriba congratulations, guy yen tikole yen tipe die. Ayo maa kari gbogbo wa. Please come for Xmas in Nigeria to know you better. Ki iyawo yin oma mikan oo. Kosi wahala OO 😂😂❤❤
Àwọn ọmọ fulani yí, ọ̀rọ̀ wọn kò mú ọgbọ́n wá rárá, àwọn ọ̀fọ́n,ọ̀n😅 😂😂😂. Ọ̀rọ̀ taxation yí mú wọ́n lómi gaan ni o. Ìnira ńlá jẹ́ fún wọn. . Anyway, Yoruba nation actualization soonest possible time láṣẹ Èdùmàrè Ẹlẹ́dàá wa, ÀMÍN. Congratulations 🎉🎉🎉 fún wa láìpẹ́.
Ogbeni Bobby. michko Ade lo ko Orin na, mi o mo pe oju ogun laiye o mi o ba ma ti mura sile lati igba ewe ni ibama ti mura sile.Niajiria ko se gbe nija ki omiefele pelu tinubu pelu tinubu ma yanju oro Ara won fun ra won.Nation yoruba wa ni awa di ibosi fun.
Ogbeni bobby E kale o News teni yi o ni agbara die o ki enia kan ni aduru ile to yi eleyi ga o o gbenu tan kaye nla leleyi . e jo Yoruba Nation no going back ka ma ba ti wa lo o o daaaro o
Ogbeni bobby lagbara Olorun a ma ri 2025, sugbon oro nigeria ti kuro ni keremi to ba je pe Emefiole lo ni awon ileyen,sugbon to ba ribe se lo ye kan lo hang e but talo fe da ejo yen nilu to je pe Ole gbe Ole gba ni.oriola Oris frm dallas tx
Iba ifesowapo,iba yennana oro,Iba Olorun nikan lo le tu wa ka,Ogbeni Bobby oju ko ni ti yin oo.Baba wa Micho Ade lo ko orin yen o. Won ti se epe fun emiofewere ki lo fe fi gbogbo ile yi se,Oluwa gba Nigeria o.
Ogbeni Bobby/Aaya Iba irinkirindo. Mo kiyin e ku eto, Micho Ade lo ko orin yio, Orin yi kan naa ni Kola Olawuyi fi nse program re ni 1980s. We are for Yoruba Nations, Nigeria has gone forever.
Ogbeni Bobby -The first Biafra war led by Pa Late Ojukwu was immensely failed because of many reasons which will be mentioned shortly -greediness- (taking another person's land), inadequate food supply (This brought hunger), and failed currency.If care is not not taking Biafra planned will later scatter .Ireooo YORUBA NATION NI TI WA
Well done Mr Bobby lokan temi Tinubu no what his doing to break Nigeria Bcz it's not easy for someone to come whenever power he's ad ti kobadaru kole pin o hmm 2025 deh Ma hot Juu 24 Lo
Bobby boy se oni fi orin yi mu obinrin lole bayi,bi se wo enu e,to fi korin ni mo rerin,o dara, lomo kunrin,mi ni omo obinrin, ti mole fi fun e, ni iba gbe won debe,iba orin,lati America Houston TX
Nipa. ti ile (750 ni ABUJA) E MA DA WON LOHUN, ) LOKAN MI KI ISE EMEFELIE NIKAN LO MA NI OOOHH ) ASIRI SI MA TU PATAPATA ) OLORUN MA GBE WA DE ILE TI WA (YORUBA NATION) NO GOING BACK AMEN.
Iba Paronure,mo ngbadun yin ni gbogbo igba.Olorun ko ni jeki a sofo omo o,abiyamo ku oro omo.Ki Olorun jeki trailer gba aarin awon ota ati olojukokoro awa omo Yoruba koja,ki a ri ona abayo si orile ede Yoruba wa.Yoruba Nation no going back.
Our Bobby ekuise, Oluwa koni fiyinnsile. Amin
Iba 'nafelefe, Iba sare wa wo Bobby. My husband and I added it to your name because you always explained iroyin to us very well, and my husband always called me to come and watch Ogbeni Bobby
Baba wa Mico Ade loko 'mi o mo pe oju ogun laye
WOW, GOD BLESS YOUR HOME ❤️❤️❤️
Kuluso ni oruko kokoro ti o ma ju idi sehin ti oma Lu ile bi okoto ogbeni Bobby eku ise o Yoruba nation no going back ❤❤❤
E ku ise o Ogbeni Bobby, Iba iroyin Funwontan. I always enjoy your unique presentation of news laced with humor and old time songs . Yoruba Nation: Aluta continua, Victoria a certa.
Happy Birthday o iya wa . Igba Odun Odun kan o loruko Jesu.
Ogbeni Bobby, ejeki Ojuyobo ma se nkan towun, ohun ni Olorun ma lo lati gba Yoruba Nation fun wa, Amin. ❤❤❤❤❤❤❤
Micho Ade is the singer of the song .[Memo p'oju ogun l'aye o] Greetings to Aaya and OGBENI BOBBY
Iba áyá o. Ọrọ "Tax" yi o ma lęyin hajan ti e le❤😂.
Ogbeni Bobby se è gbo pe shetima so restructuring under my foot se è ti gbo ye ❤❤❤❤
Ogbeni Bobby, a dupe ana oo,I listened to your response and well understood.
Micheal Ade, a native of Ikere Ekiti, waxed the cassette.
A ku ipamo Odun sir.
Ogbeni Bobby, ẹ ṣeé mo dúpẹ́ lopolopo lọ́wọ́ yín, kí Ọlọ́run fún rara Rẹ bami dúpé lọ́wọ́ yín. E ṣeé mo dúpẹ́ o. Mo rí owó yin o.
Ogbeni Bobby (Boy Alinco) Iba always on point. May the Lord continue to be with you and your family. Micho Ade omo Ikere-Ekiti lo ko orin yen.
🥰❤️❤️🥰🥰🥰🥰💯👌
Well-done sir bobby, awon musician ile hausa niyen, won kiise onibara. Emefielle, esi ebi to pa awa omo nigeria laye NO CASH laye buhari niyen. Alaini ojuti ore tongba oko ore e. Sisi, OLUWA yio gbe ija yin. OODUA NATION, NO GOING BACK.
Iba gbewon debe of Yoruba nation,...mo fe ki e se alaye "Ronu" fun mi ati bi mo se le darapo mon.yio dafunyin lase edumare.
Aku ipade olomo ilu tale yi o. Oluwa a maa ba wa se o. Yoruba Nation for sure 👍
Ahhhh 😮, Emefioole, Yibooo, Se o fe gba Ijoba mo Olorun lowo ni, Kilode gan, Erii Okan yin ti kuu patapata, Ikun yin je Ogede, koo mo pee ohun to dun nio paakun, Esinsin yin pada kuu sori otii nii, Nitori Iwo na ti daa Emii awon eniyan legbodo, O nii ni Alaafia fun gbogbo Igba to kuu fun o laaye, O si tun ni baa Oju rere Olorun pade laelae ,Koni yee o laaye ati lorun, Aameen, loofu yuu my Brother ❤❤❤ Salaam
Congratulations to you lanre teriba, And congratulations to you Baami Ogbeni Bobby i knew one day we will meet.
Ogbeni Bobby, I laughed and laughed But the man forget the Seven virgin. The Northern part of Nigeria were becoming jester the way they were thinking is no sense atall.Yoruba Nation No Going Back. Emefele needs to come out and confirmed this allegations 753 houses Na waa o..this is to much. ❤❤❤😂❤❤❤❤.May Almighty God helps US to Actualized our liabration. Thank you and God Blessed.
Happy birthday to our sister. Long life in good health and wealth Amenn.
Ogbeni Bobby se eri Emefele ati gbogbo awon Oloselu Olori buruku wonyi IYA MAJE AROMO DOMO LAGBA OLORUN. YORUBA NATION LAWA FE OLORUN SI MAGBA FUN WA❤❤❤❤
❤️❤️❤️❤️❤️😘
Dan Dan lowo ori, tulasi laso ibora! Awon Hausa ni kan ko lo ni Naijiria. Awon alapa pin buruku. Yoruba Nation, no going back❤
❤cheese 😂, Mo ki yin Oo Ogbeni Bobby èku ise oo. inu wa ma dun ti abati ngbó iroyii yin. Adun ni ngbeyin ewuro Adun ni ti yin ni òjò gbogbo ni oruko Jesu Amin. Eniti o korin yèn ni (Micho Ade) ❤❤God bless America yoruba Nation no going back Yeye oge from Dallas
Good evening sir Ogbeni Bobby, eku ise takun takun, God Almighty will continue to strengthen you, the song mi o mo pe ogun laye was composed by Micho Ade.YORUBA NATION NO GOING BACK
Ogbeni BOBBY eku etoo Mico ADE loko Orin yen o yoruba Nation no going back ADETAYO FRM NEWARK NJ USA
Ogbeni Bobby, IBA yaa olee SI olorun lorun. Miko Ade lo ko Ogun laye o ni year 90s . Olorun a ma bayin se o . Love you ❤❤❤
🤩😂😂😂😂😂
Ogbeni Bobby Orin to lagbara gidi ni o, a fi ki Olorun ja ija yi fun wa ni.Ogun teeyan o ri Olorun lo le ja fun wa o "Micho Ade" lo ko Orin yen o.
Yoruba Nation no going back.
Ole Barao ni Emiefele. Gbogbo awon olojelu yen ko ni ero awon Omo Naijiria lokan rara Afi ti ara won nikan.
Odidi ilu kan ni yeh o. Emiefele oleeeee
Eku eto o brother bobby. Segun Asewale loko orin yen. Eku ise takuntakun ❤❤❤
Segun Adewale loko orin yen
Iba yannana, Imoran temi ni wipe,ki Ife oko ati iyawo je ojulowo, ki awon mejeeji ma faaye sile fun alagata, ki won ye fura odi si Ara won, ire o. Kasun layo, kaa ji ni segun.😍
Ekuise takun takun babawa Bobby ❤️❤️❤️❤️❤️
Yoruba Nation no going back ooooooooo
MICHO ADE
Good evening sir, ekuse takutaku Oluwa Olodumare aranwalowo o amin Ase Edumare. Ogbeni Bobby I salute you sir..
🥰🥰❤️❤️❤️Amin Àṣẹ
Ogbeni Bobby ati Aya eku ise takuntakun Oluwa yio wa pelu yin ise yin yio lere,fun ra won noma fun ra won Logun je . Yoruba nation lafe now now now now now now
Ogbeni Bobby, ese ganni. Appreciate you so much ❤️ 💙 💓 💛. Almighty God will remember you for good in Jesus Might Name Amen 🙏🏼 🙌 😂😂😂❤❤❤🎉🎉😊😊😊.
Amennnnnn❤️❤️❤️❤️
Awon omo Igbo ko mo nko ti won se. Olorun a gba ile Yoruba fun wa.
Yoruba Nation is the solution no going back no surrender together we moved.
@Ọ́gbẹ̀ni Bọbi mí! Irè lójú gbogbo wà má rí lórúkọ Jésù Kristi Olúwa wá Àmín 🙏
O’ Bobby, E kuu Oginnitin yio, Olorun a jeki o bawa lara mu o Aameen,
AMIN O
Emefiele eleyi oda rara, Iwa ika gba ni eleyi. Tinubu mo nkan to nse. On wa ija awon Hausa ni. Ofe ki won binu nitori laise wipe won binu oma difficult fun Tinubu lati gba Yoruba nation. Olorun malo Tinubu fun wa. Yoruba Nation no going back. Eku ise takuntaku Iba Bobiskoko
Happy 🎉❤si Olojo ibi
Lagos just needs water purification instead of expensive parties ❤❤❤l❤❤
Ahujah Bello
CHIEF MICHAEL ALABA ADEDAYO A.K.A MICHO ADE . From ikere Ekiti my home town.
Amen 🙏
Ogbeni Bobby Kare.Omo Iwo Olodo Oba ti Biden koba padon omo re oju ti baba lawo ti omo re kun ni osan gangan IBA IROYIN MABA ISE RE LO YORUBA Nation No Giong Back
Ogbeni Bobby e ku ise takuntakun o Se e ri Emefiele Barao Bansa ni , won o ti tu isu de isale ikoko Emefiele estate miran wa nilu e . Ki Olorun gba Yoruba Nation fun wa good night
Ogbeni bobby, iba jekoye won, eku ise takuntakun,The music is by Baba Wa Micho Ade, Yoruba nation no going back love you daku❤❤❤❤❤❤
❤️❤️❤️❤️💯💯💯🙏
Amin o
Hello Ogbeni Bobby kosi si omi leko oo Sugbon won ngbe bore hole, oni lati jin daradara, titii yio fi kan yanrin funfun, kotoo lee kan omi to dara
Operation OFN Obasanjo finish naira. Ebi npa ara ilu . Yoruba Nation no going back. Eku ise o Ogbeni Bobby. 🎉
Good sir bobby, IBA YANNANA, awon hausa ati awon fulani osi maa tan ara won lori oro oti mimu ati tete tita, teba ri ibi ti awon eniyan yi ti ngego tabi ta tete, wallahi eo ni believe. OLUWA yio se ejiola ni riri alubarika ikunle abiyamo 🙏. Uncle teriba congratulations, guy yen tikole yen tipe die. Ayo maa kari gbogbo wa. Please come for Xmas in Nigeria to know you better. Ki iyawo yin oma mikan oo. Kosi wahala OO 😂😂❤❤
Ó ga o. Divine alcohol 😂😂😂.
Kò sóhun tójú kò ní rí.
Onígbàgbó e funra o.
E kú isé o Ogbeni Bobby.
Yorùbá Nation. No going back.
Emefiele omo ale, oloju kokoro, ori awon ti iya nje ko ni je ko da fun won.
Happy birthday to you ìyá sagittarian! 🎂🍰🍫🥂🍾
Happy Birthday to our Sister 🎉
Baba Sanjo gba ile wa fun anfani ara ti e ni o. Gbogbo awon oloselu ile Nigeria ni ole, eniti ile ba mo ba ni barao.
Micho Ade lo korin
Micho Ade wa lati Ekiti State.
Ikere Ekiti Loti wa ni Agbo Ile Olukere
N se re o.
Baba yi ma laya o.
Mo rope ko le je oun nikan.
Awon eniyan min ti amo ti ako le daruko wa nidi oran naa❤. from Nigeria.
He Has Been Very Hard Working Because he’s Always In America 24/7 to Come and Make His Money I Thank God For His Life
Wow! That's great
Àwọn ọmọ fulani yí, ọ̀rọ̀ wọn kò mú ọgbọ́n wá rárá, àwọn ọ̀fọ́n,ọ̀n😅 😂😂😂. Ọ̀rọ̀ taxation yí mú wọ́n lómi gaan ni o. Ìnira ńlá jẹ́ fún wọn. . Anyway, Yoruba nation actualization soonest possible time láṣẹ Èdùmàrè Ẹlẹ́dàá wa, ÀMÍN. Congratulations 🎉🎉🎉 fún wa láìpẹ́.
Ekale ooh Ogbeni Bobby,werefele ti baye je o emi mo pe asiri gbogbo won koni bo lagbara olohun 😊
Àṣẹ Edumare ❤️❤️🙏
Ogo ogo ogo fun olorun,
Ooto ni Ronke nso o, orisi risi ore lo wa o.
Ogbeni Bobby, eku ise takun takun. E ku ise opolo.
Ogbeni Bobby, India ti poju China lo bayi o. Awon ni won ngbe ipo kini bayi.
Really. Eseun tẹ já mi sí ooo
Ogbeni Bobby Micho Ade ló kọ mi o mọ wípé ojú ogún ni aiye ẹ kú ìṣe kò ní sún ṣe lágbára Ọlọhun a ma bá yín ṣe o
Ejowo se gburo Yoruba gidi tv, awon olopa ranse si, eku ise ilu iba gbe wa debe
Ogbeni Bobby. michko Ade lo ko Orin na, mi o mo pe oju ogun laiye o mi o ba ma ti mura sile lati igba ewe ni ibama ti mura sile.Niajiria ko se gbe nija ki omiefele pelu tinubu pelu tinubu ma yanju oro Ara won fun ra won.Nation yoruba wa ni awa di ibosi fun.
Ogbeni bobby E kale o News teni yi o ni agbara die o ki enia kan ni aduru ile to yi eleyi ga o o gbenu tan kaye nla leleyi . e jo Yoruba Nation no going back ka ma ba ti wa lo o o daaaro o
Congratulations 🎉🎉🎉
O ye Kan yegi fun Emefiole ni o.
Thanks
Ogbeni Bobby ejeki Aya lo gba die ninu pata Dezian, okuku ma danu ni. Mo ki yin o, eku ise takuntakun o.
Ogbeni bobby lagbara Olorun a ma ri 2025, sugbon oro nigeria ti kuro ni keremi to ba je pe Emefiole lo ni awon ileyen,sugbon to ba ribe se lo ye kan lo hang e but talo fe da ejo yen nilu to je pe Ole gbe Ole gba ni.oriola Oris frm dallas tx
Bob Ijebu ni mi from American.
Iba ifesowapo,iba yennana oro,Iba Olorun nikan lo le tu wa ka,Ogbeni Bobby oju ko ni ti yin oo.Baba wa Micho Ade lo ko orin yen o. Won ti se epe fun emiofewere ki lo fe fi gbogbo ile yi se,Oluwa gba Nigeria o.
Ogbeni Bobby/Aaya Iba irinkirindo. Mo kiyin e ku eto, Micho Ade lo ko orin yio, Orin yi kan naa ni Kola Olawuyi fi nse program re ni 1980s.
We are for Yoruba Nations, Nigeria has gone forever.
Ahuja Bello ni
Congratulations
Maiko Ade lo ko orin yi o
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤all the way !!
❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️🥰🥰🥰😘😘😘😘😘😘😘😘😘😘😘😘🤩🤩🤩🤩🤩🤩🤩
Ekaale sir,
Ekale o
Ogbeni Bobby -The first Biafra war led by Pa Late Ojukwu was immensely failed because of many reasons which will be mentioned shortly -greediness- (taking another person's land), inadequate food supply (This brought hunger), and failed currency.If care is not not taking Biafra planned will later scatter .Ireooo YORUBA NATION NI TI WA
Eku ale, eku ise takuntakun sir ❤❤❤😂
❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️
Ogbeni Bobby, àwọn Hausa yi o seriosi rara.
Sir china peter
Ha eleyi ga o
Well done Mr Bobby lokan temi Tinubu no what his doing to break Nigeria Bcz it's not easy for someone to come whenever power he's ad ti kobadaru kole pin o hmm 2025 deh Ma hot Juu 24 Lo
😂😂😂 ote ofi. Ate tedi lo fi fi ika gbaka pelu oju yo bo.
E ku eto Iba Sanawole, Iba Gbewondebe.. Emefiele fe ra gbogbo Nigeria pa.Bibeli banba ti Emefiele nru kakiri fi han pe ofege ni
The Hausa , Igbo getting their blessing from Yoruba glory , the northern nakedness will reveal once Yoruba nation established .
Micho Ade, lo kò ò ó..
Haaa😢 EmefiOle , ranti ojo atisun🔥
Bobby boy se oni fi orin yi mu obinrin lole bayi,bi se wo enu e,to fi korin ni mo rerin,o dara, lomo kunrin,mi ni omo obinrin, ti mole fi fun e, ni iba gbe won debe,iba orin,lati America Houston TX
😂😂😂😂😂
Micho Ade ni o ko Orin "Mi o mo pe oju Ogun laiye".
Ogbeni Bobby se Aya ma fe mama baba mi. Mi o ni gba nkan kan lowo e o.
😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂
Nipa. ti ile (750 ni ABUJA) E MA DA WON LOHUN, ) LOKAN MI KI ISE EMEFELIE NIKAN LO MA NI OOOHH ) ASIRI SI MA TU PATAPATA ) OLORUN MA GBE WA DE ILE TI WA (YORUBA NATION) NO GOING BACK AMEN.
😊😅😮Lanre aburo Dino Melaye, okay o.
Nigeria has turned to a lawless country where rich People are more than the law. Total overhauling is needed
Ogbeni Bobby, Dele Taiwo😂😂 ni o,yoruba nation now now .