IROYIN AYO TIDE DE O AWON AGBA YORUBA TI SE OUN TI AFE NI INU OLOYE BA N DUN O

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 28 янв 2025

Комментарии • 61

  • @TijaniShuaib-x9z
    @TijaniShuaib-x9z 28 дней назад +1

    Yoruba nation not going back ❤❤❤

  • @Josreal5932
    @Josreal5932 29 дней назад +4

    Yoruba Nation lafe. Oluwa edide eja fun wa ni oruko Jesu.

  • @RotmiBoyinbode-gm8km
    @RotmiBoyinbode-gm8km 29 дней назад +2

    Eyin gbogbo Omo oko yoruba atata e je ki gbogbo wa ji ni oju orun wa ki a ja fun ominira ile wa e ma se je ka laju wa kale ki talubo ko wo Yoruba Nation ni a fe oun lo le yanju gbogbo nkan to nsele ni ile baba wa yi ooo Yoruba Nation No Going Back oooooo

  • @beautywealth4935
    @beautywealth4935 29 дней назад +1

    Iru awọn Ọba bęę ki ijọba maa gba ade lori wọn, bi bęę kọ wọn o ni jawọ ninu katikati yi

  • @Josreal5932
    @Josreal5932 29 дней назад +4

    God will intervene in this situation in Jesus Christ mighty name. Psalm 68 says let God arise and His enemies be scattered.

  • @AlimiSunday
    @AlimiSunday 28 дней назад

    God bless you my brother, Yoruba nation lafe.

  • @agnesakande5157
    @agnesakande5157 29 дней назад +1

    Yoruba nation lafe ni kiakia laipe no going back, Ibukun ni fun Orileede Yoruba nisisiyi ati titi laelae Amin.

  • @FunmilayoElugbaju-lu3dy
    @FunmilayoElugbaju-lu3dy 29 дней назад +1

    Oba ojokoro ohun awon fulani naa lo ma pa amin

  • @olubunmiolusolasundayjob7817
    @olubunmiolusolasundayjob7817 26 дней назад

    We need Yoruba Nation now now in Jesus name amen and amen

  • @olubunmiolusolasundayjob7817
    @olubunmiolusolasundayjob7817 26 дней назад

    God is in control, Yoruba Nation do not fair at all, we have Jesus in this Yoruba Nation

  • @alaotijani6769
    @alaotijani6769 29 дней назад +2

    Yoruba nation no going back

  • @AjibolaMajiyagbe
    @AjibolaMajiyagbe 29 дней назад +1

    Nwon ti so wipe awon Yoruba lo ya ode ju ni Nigeria, awon few people wa nwo ile yin wa pariwo e gba wa o, se ko si okunrin ni ilu yen ni. To ba tiri be nyen ile Oba tabi Baale ilu yen ni ki awon ara ilu lo ya lu.

  • @BusariWahabiaderemi
    @BusariWahabiaderemi 29 дней назад +3

    Yoruba. Nation. Lafe

  • @bisolawe1996
    @bisolawe1996 29 дней назад

    Almighty God will intervene all power belongs to God amen

  • @FunkeAdeoti-o7t
    @FunkeAdeoti-o7t 29 дней назад

    Olorun ko ni gba fun gbogbo won loruko Jesu

  • @olusolaogutuga208
    @olusolaogutuga208 29 дней назад +2

    Iwona gbo nkan tonso lenu, bawo lo se ro pe Osee se, oro to yato patapata ni, ati gbo lati ose meji, ibeyen konse lagos state, Ogun state ni

  • @AishaOlatunji-cd8jy
    @AishaOlatunji-cd8jy 29 дней назад +3

    Ibeyen kise. Lagos. State. Ogun. Stats ni

  • @feliciaalatise8113
    @feliciaalatise8113 29 дней назад +1

    Yoruba Nation now nownow now,Yoruba Nation no going back

  • @christianahogundele2427
    @christianahogundele2427 29 дней назад

    Iyen kole bosi lagbara Olorun Oba oooooo

  • @KilliopeAstrid
    @KilliopeAstrid 29 дней назад +1

    Oluwo ati mufty

  • @FunsoAdeniyi-cr8pl
    @FunsoAdeniyi-cr8pl 29 дней назад +2

    GBOGBO OMO YORUBA, GBOGBO AGBAGBA, GBOGBO AWON ONI-MON, GBOGBO AWON ASAA-JU, GBOGBO AWON BAALE, GBOGBO AWON OBA, EJOWO,AFI-ADANIWAYE BEYIN, E MAA JEKI WON GBA-ILE WA LOWO WA, OMINIRA ILE YORUBA NI AWA FE

  • @frankbolarinwa8062
    @frankbolarinwa8062 29 дней назад +1

    Thanks for your information, but such things can never be possible,hence no king or baale has the right to infringe another person's property, no king will ever try that in Yoruba land.

  • @taofikilawal5127
    @taofikilawal5127 29 дней назад +1

    Dr Sunday adeyemo igboho Oosa and Professor Banji Akintoye are not a criminal they our representatives of Yoruba nation! Yoruba nation know going back

  • @FolorunshoTanimola
    @FolorunshoTanimola 29 дней назад +3

    MassB pls tell all yoruba indigenes not to sell land to who is not yoruba0

  • @YusufBakare-e6y
    @YusufBakare-e6y 29 дней назад

    BLESSED COUNTRY 💖💖💖 YORUBA NATION FREEDOM NOW NOW 💪💞🌈

  • @AbdiDanMakarfi
    @AbdiDanMakarfi 29 дней назад +1

    A note of warning lori nkan to sele ni Ojokoro is amongst the reasons ti won fi introduce Land Use Decree ti lots of former military top notches including Obasanjo, Buhari, Abacha etc fi gba ile lo bose wu won across the country. Oun na ni won fe fi bring in Ruga few years ago. Ti Ojokoro ba ti go unattended by awon ara ilu, just like you said, bi awon Fulani maa se wo arin ilu pata pata niyen.

  • @KamiluOlanrewaju-i9e
    @KamiluOlanrewaju-i9e 29 дней назад

    Horuba ladi lafe o. Ajagun ģale ni oba labe tele teĺe o

  • @AjibolaMajiyagbe
    @AjibolaMajiyagbe 29 дней назад +1

    A ni ki e ye ma pon awon Oba ile Yoruba le mo, Iba je 1st class tabi 0 class tabi monarch ko si eyi to ko le hu Iru iwa be to ba ri owo lowo Fulani.

  • @estherewetuga8245
    @estherewetuga8245 29 дней назад +1

    Yoruba Nation no going g back
    Yoruba Nation is the only Solution

  • @samuelokegbola1409
    @samuelokegbola1409 29 дней назад +1

    Ojokoro it's in Lagos State

  • @FaladeDale-u8o
    @FaladeDale-u8o 29 дней назад

    Se oba ile Yoruba lodan iru eleyi wo koyekoribe oye ki oba yi fi eekan pa awon Toni ile yi laifi ibanu pawon oti pawon saye bayi afi ki olorun bawa ran alanu si awon Toni ile

  • @mamaiya6633
    @mamaiya6633 29 дней назад +1

    Please Baba Bola Ahmed Tinubu, devide the country so that you and all of us your yoruba people will have peace in our own yoruba land!

  • @SEGODAFSEGODAF
    @SEGODAFSEGODAF 29 дней назад

    Ilu tabi adugbo woni otisele kiwon lo gbe gbogbo awon ajagungbale ati gbogbo awon tiwon ni koso awon onile denitikonile lorimo kiwon mu obaibe dada kokole won pada funwon, kode gbodo gbawon laiye ni iluna mo. So fun pe ile yoruba lawa kinse ile fulani.

  • @christianahogundele2427
    @christianahogundele2427 29 дней назад

    Se e sope awon oba ti se nkan ti e fe

  • @modupeolaehibor9978
    @modupeolaehibor9978 29 дней назад

    Awon fura won ni yio ko si kanga ti won ma gbe ni won ma sin ara won si

  • @folusadeokuwobi
    @folusadeokuwobi 29 дней назад

    Ogun state government ,wake up . Ministry of land and housing , justice, town planning . Help us . 30-12-2024 23.06 hrs

  • @AdejumobiSolomon
    @AdejumobiSolomon 29 дней назад

    Mass B , e jowo Lori lle wiwo Yi ,ni sabo lwaya nilu Eko ile wiwo sele nibe na ,a o Mon oun to sele nibe ? ti won fi wole na

  • @wemimojanet845
    @wemimojanet845 26 дней назад

    A ko ni fi aye GBA iru e ni ile yoruba

  • @IgeAlonge
    @IgeAlonge 28 дней назад

    Won ma da tira si inu re eyi ti won se si kanga ni ilorin

  • @kehindeajayi8905
    @kehindeajayi8905 29 дней назад

    Yoruba nation lafe ni kiakia

  • @cosmasadebowale5877
    @cosmasadebowale5877 29 дней назад

    This particular Oba should be arrested and jailed period .

  • @mamaiya6633
    @mamaiya6633 29 дней назад

    No Oba or Baale should betray us in yoruba land. no real Omo-Oko yoruba tooto will allow this let think right and let us come together and get our freedom out of Nigeria. Yoruba Nation is what we need.

  • @mamaiya6633
    @mamaiya6633 29 дней назад +1

    All Omo-Oko yoruba tooto,let us come together and take our land out of Nigeria, so that we can have peace and Trasqulittes in Yoruba land enough is enough!. Yoruba Nation is the solution to all these nonsense happening in Yoruba land.before it's too late,

  • @jokeakinfewa385
    @jokeakinfewa385 29 дней назад

    AGBODO FI AYE GBA IRU E NI ILE YORUBA

  • @christianahogundele2427
    @christianahogundele2427 29 дней назад

    Ibo lawon ara ilu na wa ngbe bayi

  • @adeyemioladele
    @adeyemioladele 28 дней назад

    Can this happen to us in Yoruba land?Call this oba to order.

  • @hassadabdul6227
    @hassadabdul6227 29 дней назад

    President Bola.Tinubu should take the right action to save us in our land and Allah Subuanatahala will guide and help him to win the situation.

  • @AderemiAdewunmi-q6e
    @AderemiAdewunmi-q6e 29 дней назад

    Ki nwonlo mu obaoun,nikiakia ko di wahala

  • @olu7349
    @olu7349 29 дней назад

    You have to create problems for your enemies to keep them busy and occupied. What the he// is wrong with my people? You must not only defend all the time. Give them something to worry about.

  • @OlaoluOke-e8o
    @OlaoluOke-e8o 29 дней назад

    They will never have their way ijn,when their sibling, former president Buhari was at d helm of affairs, he did more than that upon d fact that he and his fulanis.really prepared for jihad but they have continued to meet brickwall and will continue to do so ijn (amen).I wish president Tinubu and all meaningfull.yorubas reason along Yoruba nation agitators, even though they're just postponing d big day cos it's God ordained.

  • @John-yk7og
    @John-yk7og 29 дней назад

    Lambe ki se omo Jankara ojokoro Tinuibu lo fi je oba nigba ti o wa ni Governor Lagos State Omo ita ajagungbale ni from day one
    Tinuibu will not do anything Tinuibu lo fi agidi gbe lori awon ara ilu is a stranger in that place is a criminal noting will happen to him only person to le challenge e ni CSI that's all

  • @seyioluwaseyin8323
    @seyioluwaseyin8323 29 дней назад

    Nonsense.

  • @AbdiDanMakarfi
    @AbdiDanMakarfi 29 дней назад

    I wouldn't agree with pe awon Fulani yi gangan ni owo. Awa la nplay si won lowo. Awa la allow won lati je ki kidnapping ati ransoms di business. Owo ti wo ngba fun ransoms ni won fi nra nkan ogun including vehicles, ibon ati eroja e, ounje, ibon, pelu more recruitment ti won fi nestablish si awon oko ati igberiko gbogbo.
    Emi o gbagbo pe a ni lati duro ki ijoba abi awon asiwaju kan so nkan ti a ma se nisisin yi fun ojo ola wa. Nkan to ba le gba loye ki a ma dide lati se titi ijoba ati awon ti o ba ye ki won gbe igbese ti o to ati eyi ti o ye maa fi take proper actions taken fe.

    • @OluborodeMoses
      @OluborodeMoses 29 дней назад

      Yoruba Nation now by the Grace of GOD

  • @josephdasho1100
    @josephdasho1100 29 дней назад

    U have big mouth.

  • @estherfawibe1280
    @estherfawibe1280 29 дней назад

    Yoruba nation no going back

  • @estherfawibe1280
    @estherfawibe1280 29 дней назад

    Yoruba nation no going back

  • @olunladeidowubabatunde5881
    @olunladeidowubabatunde5881 29 дней назад

    Yoruba nation no going back