SUNDAY IGBOHO GBA WA LOWO AWON FULANI,SEYI MAKINDE PARIWO SITA,

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 5 фев 2025

Комментарии • 36

  • @fadirantunde9905
    @fadirantunde9905 28 дней назад +3

    Baba Ekiti, l name you yerepeoro of Yoruba land 👍👍👍

  • @LiadiOlatunde
    @LiadiOlatunde 28 дней назад +1

    Baba Ekiti, a ku odun. E ku Oro ilu, loruko Jesu, Olorun a mu wa de Ile ileri.

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 7 дней назад

    AMIN AMIN ASE Edunmare ASEWA 👍 BA MI LEKITI. EKU ISE Ilu oooo OLORUN OBA a ma wa pelu yin oooooo Laseeedumare ♥️♥️♥️👍

  • @Joladeallison1351
    @Joladeallison1351 28 дней назад +3

    If they had heeded Chief Sunday Adeyemi and Baba Professor Banji Akintoye, all these would not have been happening!!!.
    They called Chief Sunday Adeyemi all sorts of names.
    YORUBA E JE KA RONU 🤔.

  • @ayoolababatunde4710
    @ayoolababatunde4710 28 дней назад

    Baba mi l'Ekiti, ekuuse takun, takun.
    Koni baje fun yin laelae lagbara Eleduwa.
    Orile Ede Yoruba maa duro deede,o si maa seso rere loju gbogbo awon asebi atawon aseebaje aye yii.
    Yoruba Nation now,now, now.
    Yoruba Nation, no going back.

  • @OmitogunDennis
    @OmitogunDennis 28 дней назад +1

    A ku alaja odun tuntun o 🎉🥳. Emin wa yio she opo re o 😊. Up Yoruba Nation ❤. No going back 😮.

  • @gladyaremu6943
    @gladyaremu6943 28 дней назад +1

    Amin Jesus gbogbo won lo ma ku pata pata ti a ma fi gba ile wa Yuroba lagbara Olorun Amin

  • @Joladeallison1351
    @Joladeallison1351 28 дней назад

    Baba Ekiti, eku igbiyanju. Olorun a gba Ile YORUBA NATION fun wa l'ase Edumare la'ipe la'ijina.

  • @taiwoedunjobi158
    @taiwoedunjobi158 28 дней назад

    Gbogbo eyin sorosoro wa olorun Olodumare a tubo ma dabobo nyin ni owo ewu riri ati ewu ti a ko ri, tiletona nyin, eo ni jade le iku lowo be si ni e ko ni sinrin, ni ipari ohun Gbogbo ajijo ma jere ile yoruba ni lase Edumare

  • @adenikefajuke5994
    @adenikefajuke5994 28 дней назад +1

    Baba Ekiti e ku ise takuntakun, gbogbo ilakaka yin koni jasi asan loruko Jesu Amin

  • @Sundaysipasi-z1n
    @Sundaysipasi-z1n 28 дней назад +1

    (*+++In❤JA baba lebute GOD bless name 🎉🎉🎉Amen in yoruba land Amen 🎉🎉🎉#

  • @fadirantunde9905
    @fadirantunde9905 28 дней назад

    Baba Ekiti, you are greatly appreciated

  • @Kanjuabenko
    @Kanjuabenko 28 дней назад +1

    Gaskia ni , 😂😂😂, so why is theifnubu uniting the ununitable

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami5257 28 дней назад +3

    Baba wa keith ekuisetakuntakun, olorun eledumare awa pelu yin titi lailai

  • @kintonjosh
    @kintonjosh 28 дней назад

    👏🏽👏🏽👏🏽👏🏽👏🏽

  • @jemilaagbaje6238
    @jemilaagbaje6238 28 дней назад

    Eku ise eku eto o baba ekiti, Olorun abawa peluyin kobawa so emin yin

  • @LiadiOlatunde
    @LiadiOlatunde 28 дней назад

    Baba Ekiti, afaimo koma je wipe awa ni asima soko ashitani won, nigbati asiko ba to.

  • @kintonjosh
    @kintonjosh 28 дней назад

    I just pray that Yoruba people will not forget all the wickedness that the Politicians perpetrated against us. If not addressed, same thing will be transitioned to Yoruba Nation.

  • @adefemiojokanke5222
    @adefemiojokanke5222 28 дней назад

    Yoruba nation now no going back

  • @fadirantunde9905
    @fadirantunde9905 28 дней назад

    Yerepeoro of Yoruba land (lekiti baba)

  • @samuelodeyemi6574
    @samuelodeyemi6574 27 дней назад

    ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤

  • @fadirantunde9905
    @fadirantunde9905 28 дней назад

    Aaamina yarobi

  • @AbubakarYahya-u7g
    @AbubakarYahya-u7g 28 дней назад

    Great baba ekiti

  • @FunsoAdeniyi-cr8pl
    @FunsoAdeniyi-cr8pl 28 дней назад

    BABA EKITI,AABO ADANIWAYE A DAJU LORI YIN LAGBARA ELEDUA,AYUN-LO,AYUN-BO LOWO-NYE-NUN,E MA LORE EEMA-BO -RE, LAGBARA ELEDUMARE OMINIRA PATA-PATA KURO NIUN NAJIRIA NI AWA OMO YORUBA FE.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 27 дней назад

    AWON Fulani ni yio pada pa Seyi Abiodun Makinde adabi ti ko ba gbe ogun ti Sunday Adeyemo lgboho nitori lgangan ti sunday Adeyemo lgboho lo. Adabi ti seyi Abiodun makinde ko ba mo bi won se attack ile sunday Adeyemo lgboho ni 1st July 2021 nikan loku ..olorun ma bere eje Alfa fatai ati eje Adogan lowo Seyi Makinde....

  • @fadirantunde9905
    @fadirantunde9905 28 дней назад

    Yes we love him

  • @fadirantunde9905
    @fadirantunde9905 28 дней назад

    Baba oniro, e lo fokanbale

  • @bigmummykofo8447
    @bigmummykofo8447 28 дней назад +1

    Please they should leave CSI alone. Seyi makinde is collecting security vote in abuja. Seyi makinde should spend the money now. What Seyi makinde is doing is hypocrite. He didn't need to shouts. It's Seyi makinde job. Not Chief Sunday igboho jobs.

  • @JohnDera-i3s
    @JohnDera-i3s 28 дней назад

    Then Why was they Sighned the agreement with the Devlish Britain When they knew this ???

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami5257 28 дней назад

    pls share share share show appreciation to baba lekiti ooooiiio❤❤❤😂

  • @fadirantunde9905
    @fadirantunde9905 28 дней назад

    Kin lo wa n sa fun? Alailojuti ti n wa n pariwo Igboho Oosa?

  • @emmanueladeniyitosin1172
    @emmanueladeniyitosin1172 28 дней назад

    Pls less pray for this baba ekiti. For God protection.

  • @OmidijiOdunayo
    @OmidijiOdunayo 28 дней назад

    @ Ohun Ti Ko Ye Awon Oponu Kokan To Ri Jaje Ninu Omo Yoruba, SUNGBON Ti Won Ro Wipe Kosi EWU Fun Awon Ni Wipe, Awon Gangan Ni Target Awon Ota To Fe Gba Ile Yoruba. Awon Lo Ma Padanu Julo.. All For Time .. Ki Won To Kede Sharia Law, Ni Awon Omo Ogun To Ma Fi Idi Sharia Law Ti Gbe Aradi Kakiri Ipinle Oyo, Ti Won Fi Ara Pamo Kakiri, .... @ Anyway Yoruba Yio. Pada Ri Gbogbo Asiri Awon Ota Larin Ore Ati Omo Ale Larin Omo Oko Nikeyin.... SUNGBON Sibesibe Ki Gbogbo Omo Yoruba Wa Ni Igbaradi, EWU U'nbe Nitosi.... Oju Ni Alakan Fi So Ori..... Eni Awifun Oba Je Ko Gbo...

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami5257 28 дней назад

    omo yoruba atata pls press likes and comments

  • @kintonjosh
    @kintonjosh 28 дней назад

    I just pray that Yoruba people will not forget all the wickedness that the Politicians perpetrated against us. If not addressed, same thing will be transitioned to Yoruba Nation.