- Видео 131
- Просмотров 79 326
BABA EKITI TV
Нигерия
Добавлен 12 ноя 2018
OMOLUABI YORUBA NI MI
BEHALF OF MY BROTHER YINKA AYEFELE,WE ARE SORRY PLEASE FORGIVE ME
BEHALF OF MY BROTHER YINKA AYEFELE,WE ARE SORRY PLEASE FORGIVE ME
Просмотров: 1 222
Видео
AWON TO GBABODE FUN IRAN WON TORI OWO ATI IPO, NOVEMBER 7 MEETING
Просмотров 4786 часов назад
AWON TO GBABODE FUN IRAN WON TORI OWO ATI IPO, NOVEMBER 7 MEETING
ETEKETE AWON OLOSELU TI SO AWON OBA YORUBA DI OTA ORISUN WON
Просмотров 1,1 тыс.6 часов назад
ETEKETE AWON OLOSELU TI SO AWON OBA YORUBA DI OTA ORISUN WON
AWON OLOSELU TI SO AWON OBA WA DI (BINGO) WON, BECAUSE NOVEMBER 7 MEETING
Просмотров 8958 часов назад
AWON OLOSELU TI SO AWON OBA WA DI (BINGO) WON, BECAUSE NOVEMBER 7 MEETING
GBOGBO ABIYAMO ILE YORUBA E DIDE AWON OBA YORUBA FE SII IWE ERU FUN YORUBA LEKEJI
Просмотров 1,3 тыс.11 часов назад
GBOGBO ABIYAMO ILE YORUBA E DIDE AWON OBA YORUBA FE SII IWE ERU FUN YORUBA LEKEJI
EYIN ABIYAMO YORUBA,E MAA WO AWON OBA YORUBA YI NIRAN
Просмотров 1,1 тыс.11 часов назад
EYIN ABIYAMO YORUBA,E MAA WO AWON OBA YORUBA YI NIRAN
SE O YE KI AWON OBA WA WO ASO ABUKU NI TORI OWO (MONEY)
Просмотров 1,1 тыс.13 часов назад
SE O YE KI AWON OBA WA WO ASO ABUKU NI TORI OWO (MONEY)
NOV 7, MEETING IS A SCAM,IS FOR ONE NIGERIA, YORUBA PEOPLE SAY NO TO IT
Просмотров 87016 часов назад
NOV 7, MEETING IS A SCAM,IS FOR ONE NIGERIA, YORUBA PEOPLE SAY NO TO IT
IRO NLA NI,KII SE IPADE ALAAFIA FUN OMO YORUBA,ONA ATI TA YORUBA FUN FULANI NI
Просмотров 60316 часов назад
IRO NLA NI,KII SE IPADE ALAAFIA FUN OMO YORUBA,ONA ATI TA YORUBA FUN FULANI NI
WON TAN AWON OBA WA,LATI KO YORUBA WO OKO ERU ELEKEJI,E FUN RA OOOOO
Просмотров 2,4 тыс.16 часов назад
WON TAN AWON OBA WA,LATI KO YORUBA WO OKO ERU ELEKEJI,E FUN RA OOOOO
YORUBA GBE OGUN TI OMINIRA YORUBA,ITAN MAA SO NI PA TIYIN
Просмотров 1,8 тыс.18 часов назад
YORUBA GBE OGUN TI OMINIRA YORUBA,ITAN MAA SO NI PA TIYIN
IRU ITAN WO NI AWON OBA YORUBA FE KO FUN AWA YORUBA, NOVEMBER 7 2024 MEETING
Просмотров 56218 часов назад
IRU ITAN WO NI AWON OBA YORUBA FE KO FUN AWA YORUBA, NOVEMBER 7 2024 MEETING
IRU ITAN WO NI KI A SO IPA TIYIN,SE RERE NI,TABI BUBURU,EYIN AGBAAGBA YORUBA
Просмотров 67723 часа назад
IRU ITAN WO NI KI A SO IPA TIYIN,SE RERE NI,TABI BUBURU,EYIN AGBAAGBA YORUBA
E MAA SA ERE KU NI LORI ORO SUNDAY IGBOHO OSA,EYIN OTA
Просмотров 587День назад
E MAA SA ERE KU NI LORI ORO SUNDAY IGBOHO OSA,EYIN OTA
IRU ITAN WO NI KI A SO IPA TIYIN,part 2
Просмотров 73День назад
IRU ITAN WO NI KI A SO IPA TIYIN,part 2
IRU ITAN WO NI KIA SO IPA TIYIN,THE LEADER IN YORUBA LAND
Просмотров 1,1 тыс.День назад
IRU ITAN WO NI KIA SO IPA TIYIN,THE LEADER IN YORUBA LAND
ORO IMORAN FUN,(WOLI REGION) WALE OLAGUNJU,AGBA YAHOO PASTOR
Просмотров 944День назад
ORO IMORAN FUN,(WOLI REGION) WALE OLAGUNJU,AGBA YAHOO PASTOR
EMI BABA EKITI,MI O BEE FLORENCE AJAKAYE,IRO NI WON PA
Просмотров 2 тыс.День назад
EMI BABA EKITI,MI O BEE FLORENCE AJAKAYE,IRO NI WON PA
AWON OBA YORUBA FE MAA DA OWO RU, NOVEMBER 7 MEETING AT LAGOS
Просмотров 4 тыс.14 дней назад
AWON OBA YORUBA FE MAA DA OWO RU, NOVEMBER 7 MEETING AT LAGOS
OMI EKO,EKO NI,OMO YORUBA E LA OJU YIN O
Просмотров 68614 дней назад
OMI EKO,EKO NI,OMO YORUBA E LA OJU YIN O
IGBOHO OSA KO KU O,IRO NI WON PA,AWON OTA ORISUN YORUBA NI O MAA KU
Просмотров 2,6 тыс.14 дней назад
IGBOHO OSA KO KU O,IRO NI WON PA,AWON OTA ORISUN YORUBA NI O MAA KU
IKAN NINU AWON OMO DUPE ONITIRI ABIOLA TI KU SI EWON NI ILU IBADAN
Просмотров 85914 дней назад
IKAN NINU AWON OMO DUPE ONITIRI ABIOLA TI KU SI EWON NI ILU IBADAN
ARE SUNDAY IGBOHO YATO SI WON, OJULOWO OMO NI IGBOHO SUNDAY MI
Просмотров 3,1 тыс.14 дней назад
ARE SUNDAY IGBOHO YATO SI WON, OJULOWO OMO NI IGBOHO SUNDAY MI
IGBOHO OSA AT LONDON DINNER BY ALL OJULOWO OMO YORUBA IN LONDON
Просмотров 1,1 тыс.21 день назад
IGBOHO OSA AT LONDON DINNER BY ALL OJULOWO OMO YORUBA IN LONDON
LONDON MEGA RALLY TODAY,BE PART OF IT,OMO YORUBA ATATA
Просмотров 29621 день назад
LONDON MEGA RALLY TODAY,BE PART OF IT,OMO YORUBA ATATA
WON TI TA ILE YORUBA NI #100 MILLION DOLLARS FUN DANGOTE, PLEASE SUPPORT LONDON MEGA RALLY
Просмотров 49021 день назад
WON TI TA ILE YORUBA NI #100 MILLION DOLLARS FUN DANGOTE, PLEASE SUPPORT LONDON MEGA RALLY
ASIKO RE LATI DIDE FUN OMINIRA WA,OMO YORUBA, LONDON MEGA RALLY
Просмотров 58021 день назад
ASIKO RE LATI DIDE FUN OMINIRA WA,OMO YORUBA, LONDON MEGA RALLY
SENATE LEADER CONSTITUENCY, OMO YORUBA RONU O
Просмотров 41621 день назад
SENATE LEADER CONSTITUENCY, OMO YORUBA RONU O
Orie tigbale baba ekiti.nitoripe efe gba yoruba nation ni egbodo fe mafi awon kan paro nitori ole tefeja
From the point 👉 of view, nobody is against Ayefele . Where is the repented serial killer to come out publicly online to tell us and our children and prove everything to us if all what he said are TRUE OR FALSE to clear the nonsense talk and the damages of iesese flowing and grooving around the globe 🌎 ?
Baba Ekiti, no one is against Yinka Ayefele, what the Alabalaye are asking is for Yinka to provide the guy who spoke about an Orisha that he said he is sacrificing women blood too Lo batan. Secondly, baba ekiti . You said the man spoke that he has been in prison, very true ; but he needs to clear the air that all his members are all died because they shouldn't be in the midst of people Thirdly, you, Baba ekiti, said as they are corrupt people in other religion, so they are. I am not here to argue that it's not true, but I will ask you to go and investigate those corrupt Adahunse. They are not true, Alabalaye. They are either a pastor or muslim. Please go and do your investigation.. Lastly, you, Baba ekiti, said that our forefathers were peaceful people and did not fight others. This is what brought the Alabalaye to where we are today Where emir iwo(amugbo iwo) has the audacity to be misbehaving like a mad dog that has no gaurd, with that dirty mufti whose mouth is the pithole of a toilet
Baba Ekiti let Yinka Ayefele bring out the man
Please, have mercy on him. Omo oba wa ma jagun bi eru. please and please.
Jagun bi Eru, Really Ka ma ba jagun bi eru, is why we have to correct, many negativity that the Yoruba movies and the foreign religions have portrayed us to be.
OMODE KI MO ORI JE KO MA RA LOWO:EJOWO E DARIJI AIYEFELE..
O ti wa di owe aiye Atijo Maybe after the chastising and cleaning of all negativity behold upon our forefathers, we can return back to the Owe.
Please Yoruba let’s settle our grievances and unite together as ONE UNITED YORUBA. Let’s forgive Ayefele and move on. Baba Ekiti thank you so much. God will continue to strengthen you. Amen
We all sorry for onisese please and please sir
Weldone sir Dr yinka ayefele he is a nice guy
Eseun pupo baba Ekiti, nwon o ba aiyefele ja ju wipe ki o gbe eni ti o SE eto fun lo gbe oju re sita
Who are the Yoruba seeking and demanding self determination from? Is it obas, UK, cow citizen, Igbo, Hausa, UN, foreigners, 419 religion scammers, diaspora, japa, Ecowas, AU, ojelus 419, bankster, L419 or ourselves?
Oloriburuku ni aiyefele
Please forgive him, such will never happen again.
Oloriburuku ni aiyefele
Please e ma sepe fun. A lot of things have gone wrong in our forefathers' land.
❤❤❤ Yoruba nation no going back
Gbogbo ota Yoruba Koni dale gbogbo eniti obanika losinu igbekun, igbekun niwonyio lo Amin
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤ Talk 🦜🦜🦜🦜🦜🦜🦜🦜🦜💯💯💯💯💯💯💯💯💯💯💯
Bi awon Kan ninu awon ti won pe ra won ni oba yoruba se parapo lo gba owo lowo Abudl Salam won fun won lowo lati fi be won pe won pa omo Iya won Mowhood Abiola
Ki nwon ma KO Ile Jo bi ti eye ni a ri nwon si, awon oba radarada ATI rederede ooooole ATI ooooolosa oba
Aiye ATI IPO nwon ti Jo reyin NI gbogbo agbaiye awon oba alabode ATI amunisin
Elegusi saheed have said he's not Yoruba Alfa Rasheed Akanbi both of them are bird of the same feder this two guys marry fulani they were not relevant, Yoruba people should beware of this fucking betrayal.
Meeting ti won fe se,Ede ara won ko ni ye ara won ti o ba je pe meeting abosi ni won fe see.fulani pa omo Yoruba e ti meeting se Lori yen.president bola tinubu du 2027 election ki o ma no mo oun lowo, kini bola tinubu ti wa kiri ti won da omo Yoruba lamu.alale Yoruba a gbija wa,omo Fulani melo lo wa ni abroad ti o toju arugbo,ko si rara,ti e ba de Lybia awon omo Yoruba naa po ni ibe.idajo olorun ju ti eda lo.
Ko si ki awon Oba ati agbagba Yoruba ma je ijekuje lodo awon oloselu fun yeye ati meeting ti won fe se,Olorun ni ko gba wa lowo won, apo ti ara won nikan ni won du.olorun ni ko gba Yoruba nation fun wa, ki ojuti awon ota Yorubas.gbogbo eni to ni a ni gba Yoruba nation, eyin onitoun ni a ma gba lagbara olorun.
Ahmed Sangodele Tinubu you have achieved your aims to become president of Nigeria now forget 2027 you will not the election again if you fail to loose Yorubas from Fulani and Nigeria boundage you will see wroght of God before 2027...now let Yoruba breath
Oba ile Yoruba tio ba gba owo lowo oloselu ati Fulani against awa omo Yoruba lku esin ni gbogbo awon Oba na ma ku danu ni agbara olorun amin ase Edumare
Atenuje lon pa awon kabiyesi, won ti gbagbe wipe ti Fulani bagba ile Yoruba which can never happened Ori won na maa pada si🎉
Mo be awon oba wa ni ile Yoruba. Ki won mase gba lati fi awa omo Yoruba sinu igbekun leķan si. Yoruba Nation la fe o
Good for you. I love you and l ♥️ that. Keep on with this good job. Don't be too concerned Ajekay. She has lost everything including her life.
Baba ekiti more greeze to your elbow,if the obas sign any document,we the Yorubas will raise up our voice to int,community against the obas.
OBA ORUN JU OBA AIYE LO.NITORINA OBA AIYE KAN KO NI KO WA SI ERU ELEKEJI MO. IGBESE NI KI OMO YORUBA NATION GBE LAI FI ASIIKO SOFO.:ACTION NOW BEFORE IT IS TOO LATE:YORUBA NATION NO GOING BACK:
Nigeria Law makers are discussing about Nigeria should introduce Sharia law ,Nigeria is a Curcular State.
Baba ekiti, please I need your contact number please very important and urgent.
E ku ise takuntakun Olorun yio wa pelu re Yoruba Nation no going back
Right now we don't have any Oba in Yoruba land until they do what we the Yorubas want
Is going to affect oba too they will be the one to suffer it
If oba sign let them know they too don't have people to rule on
AAAA square, Adisa Adeniyi Adetunji Adeyemo gbosaaa gbosaaa gbosaaa
Well said Baba Ekiti, god bless you.
Baba Ekiti, e sewun, eku ise atunse. Daradara ni yio ma ba yin. Ipade ote ni won pe awon oba si o. Ki won mase lo.
Yoruba Youth must wake up. They must stage a No protest on that day. Tonight must boycott that meeting and ask for Yoruba autonomy. Elegushi is working against Yoruba Nation.
Talo NI oba to lo si ipade na, ki iru oba bee, KO ma pads si aafin mo
Baba. Editi I love you, you are too much. Tell them we are watching,.Almighty ALLAH would crown all our efforts. We would reach the promise land .
Baba Ekiti, E jowo. Obakoba to ba lo si ipade lobaloba laafin oba onifila elegushi, paapa lati Ekiti tabi Ondo State. Ti oba na a ba lo layo won ko ni pada layo si ori ijoko won. Nitori, igba ti won npa oba ni Ekiti ati Ondo State, Tinumbu ati elegushi oba Onidoti ati onifila won o pe ipade lobaloba lati fi opin si, tabi ki won so ona abayo ti won ko ni fi ma a day emin awon oba wa loola.
Absolutely
The next step for Yoruba obas is to determine if we can still fold our hands and be looking our destroyers to continue take our life away from we.
Awon onile ko ni gba fun won o damiloju de be a Fi bi won ba Fe je tan Oju ti la ju be lo
Yio dara fun yin baba , haa eledumare yio maa daabo bo yin sir
Well done àbá Èkìtì. Congratulations 🎊 🎉🎉🎉🎉🎉 ló máa gbẹ̀hìn ọ̀rọ̀ Yorùbá nation actualization soonest possible time láṣẹ Èdùmàrè. Á ṣojú èmi, ẹ̀yin náà àti gbogbo àwọn tó gbàgbọ́ nínú ìdásílẹ̀ ìlú ńlá Olómìnira wa Yorùbá nation nínú àlàáfíà ara pẹ̀lú ÌDÁNILÓJÚ ÀṢẸ ÌRỌ̀RÙN ÀJÍǸDE ÀTI ÌYÈ ÀÌNÍPẸ̀KUN JÉSÙ KRISTI ALÁÀÁNÚ ÀTI ALÁṢEPÉ IGBAGBỌ WA
Yoruba nation ni afe no Yoruba nation no peace
Baba Ekiti e ku ise takuntakun, e o ni se lasan lagbara Olorun
Ominira ile YORUBA la fe
Ekuse takuntakun God will bless you,awan aworan tefihan onijekuje ota Alafia Yoruba wan yogba itiju keyin ni