Sokoto kii ṣe orirun Musulumi ni Nigeria. Ko si ẹni ti o ti awọn afẹmiṣofo leyin nipa iṣẹ aburú wọn. Awọn ijọba ni o ṣeṣẹ wọn d'oju ala. Aimọkan yin pọ gan, madam.
@@AwodeleOgundare Islam kọkọ de Nigeria ni agbegbe Borno lọdọ awọn Kanuri (Bariba) ki o to di odun 1000. O de ilẹ Hawusa ati agbegbe ilẹ Yorùbá ni ọdún 1300 si 1400. Ìjọba lo fun Sultan ile Sókótó ni ipò olórí lẹyìn òmìnira orilẹ ede náà.
@@_Abdussalama Ẹyin naa ti sọro naa, pe ijọba lo fun Sultan ni ipo olori awon musulumi. Sultan yii lo n kede igba ti gbogbo musulumi maa bẹre aawe ati igba ti wọn maa ṣọdun. Ẹyin naa sa mo bẹe. Ṣokoto si ni Sultan n gbe, nibi ti Uthman Dan Fodio to bẹrẹ Jihaad jokoo si. Tabi ki i ṣe nitori pe Dan Fodio ni awon Hausawa yii ni Gobir ko ṣe musulmi daadaa lo ṣe gbogun ti wọn! Tabi ki i ṣe awọn Kanem ni Borno yii ni ija buruku ṣẹlẹ laarin awon atawon ọmo Uthman Dan Fodio ni. Ki lo de to jẹ awọn Fulani musulumji Ṣokoto ni wọn di Emir ni gbogbo ilẹ Hausa? Abi kin ni itumo Emir, ki i se Amir-li-mumiin (Olori awon Mumini) ni wọn ge kuru bẹe ni! O si daju pe ẹ ko tẹ le iroyin igba ti awon Boko Haram ati afẹmiṣofo bẹre nile wa, bi ẹ ba tẹle wọn ni, ẹ ba mọ ohun ti awon eeyan bii El-Rufai, awon bii Sheik Gumi atawọn mi-in nilẹ Yoruba nibi paapaa sọ lori ọrọ wọn. Ẹni to ba n ṣe iwadii ọrọ ki i ṣe alaimọkan, nigba miiran, tọhun a maa nimọ ati ọgbọn ori ju awọn ti wọn mọ ọna kansoso lo, nitori ti eeyan ba jẹ oniwadii ọpọ ọna ni yoo mọ, ohun to ba si mo ni yoo fi ṣe agbekalẹ ohun to ba fẹẹ sọ jade. Ọrọ rẹ paapaa yoo si yatọ patapata si ti alaimọkan.
@@Alaroyeonlinetv Ko eyii ti o kan mi pẹlu awọn ọdaran Fulani abi ẹya mii bi ko ba n ṣe aiwulo ijọba ti ko ṣe iṣẹ abo bi o ṣe yẹ. Islam ti wa ni Nigeria fun aimọye ọdun ki wọn to bi Dan Fodio. Oun kan fi ìjọba Fúlàní rẹ jọba ni. Ko tunmọ si wipe ibẹ abi latari rẹ ni Islam fi gberi ni agbegbe ti a mọ si Nigeria lonii. Ẹ ku Iṣẹ Iroyin yin o.
Mama Alaroye you are too much
Please, divide Nigeria now and let everyone go in their separate ways for peace to reign.
Know more one Nigeria they should divide Nigeria ooo maybe that one will be solution
IYA ALAROYE E KU OHUN AFI KI OLORUN GBASAKOSO FUN NIGERIA O TOJU SU WA O KI OLORUN SAMU WA LOPOLOPO A SESE FUN WA LOLA OLORUN AAMMIINN
Eyin lo kan, ema moju to
Se awon ijoba ma so pe awon o gbo nkan to nsele ni abi won kan da aguntan tori pe ona ti won gba wole ni Ko je Ko won mo nkan ti won le se
You are one of the best pundit anywhere. Much love and respect. Please show love with thumbs-up for mama o soju mi koro.
Olori buruku ni awon ijoba tani nilu Nigeria 🙉
This is what Buhari cause when he was on site
Ti eba laju sile ti fulani Olorun ba gba ijoba oruko yin Ko ni pare ninu iwe itan
pls we are begging. let us go our separate way na. one Nigeria is not working na. abi kinni gbogbo eleyi na
We don't want one Nigeria again.
One Nigeria na SCAM
Esin ofo
Yoruba ronu
Sokoto kii ṣe orirun Musulumi ni Nigeria. Ko si ẹni ti o ti awọn afẹmiṣofo leyin nipa iṣẹ aburú wọn. Awọn ijọba ni o ṣeṣẹ wọn d'oju ala. Aimọkan yin pọ gan, madam.
Nibo wani orirun musulumu ni Nigerian???
@@AwodeleOgundare Islam kọkọ de Nigeria ni agbegbe Borno lọdọ awọn Kanuri (Bariba) ki o to di odun 1000. O de ilẹ Hawusa ati agbegbe ilẹ Yorùbá ni ọdún 1300 si 1400. Ìjọba lo fun Sultan ile Sókótó ni ipò olórí lẹyìn òmìnira orilẹ ede náà.
@@_Abdussalama esehun adupe oo
@@_Abdussalama Ẹyin naa ti sọro naa, pe ijọba lo fun Sultan ni ipo olori awon musulumi. Sultan yii lo n kede igba ti gbogbo musulumi maa bẹre aawe ati igba ti wọn maa ṣọdun. Ẹyin naa sa mo bẹe. Ṣokoto si ni Sultan n gbe, nibi ti Uthman Dan Fodio to bẹrẹ Jihaad jokoo si. Tabi ki i ṣe nitori pe Dan Fodio ni awon Hausawa yii ni Gobir ko ṣe musulmi daadaa lo ṣe gbogun ti wọn! Tabi ki i ṣe awọn Kanem ni Borno yii ni ija buruku ṣẹlẹ laarin awon atawon ọmo Uthman Dan Fodio ni. Ki lo de to jẹ awọn Fulani musulumji Ṣokoto ni wọn di Emir ni gbogbo ilẹ Hausa? Abi kin ni itumo Emir, ki i se Amir-li-mumiin (Olori awon Mumini) ni wọn ge kuru bẹe ni! O si daju pe ẹ ko tẹ le iroyin igba ti awon Boko Haram ati afẹmiṣofo bẹre nile wa, bi ẹ ba tẹle wọn ni, ẹ ba mọ ohun ti awon eeyan bii El-Rufai, awon bii Sheik Gumi atawọn mi-in nilẹ Yoruba nibi paapaa sọ lori ọrọ wọn. Ẹni to ba n ṣe iwadii ọrọ ki i ṣe alaimọkan, nigba miiran, tọhun a maa nimọ ati ọgbọn ori ju awọn ti wọn mọ ọna kansoso lo, nitori ti eeyan ba jẹ oniwadii ọpọ ọna ni yoo mọ, ohun to ba si mo ni yoo fi ṣe agbekalẹ ohun to ba fẹẹ sọ jade. Ọrọ rẹ paapaa yoo si yatọ patapata si ti alaimọkan.
@@Alaroyeonlinetv Ko eyii ti o kan mi pẹlu awọn ọdaran Fulani abi ẹya mii bi ko ba n ṣe aiwulo ijọba ti ko ṣe iṣẹ abo bi o ṣe yẹ.
Islam ti wa ni Nigeria fun aimọye ọdun ki wọn to bi Dan Fodio. Oun kan fi ìjọba Fúlàní rẹ jọba ni. Ko tunmọ si wipe ibẹ abi latari rẹ ni Islam fi gberi ni agbegbe ti a mọ si Nigeria lonii. Ẹ ku Iṣẹ Iroyin yin o.