A kí ọ Naijiria Ilẹ̀ ìbí wa ọwọ́n Ẹ̀yà àtèdè lè yàtọ̀ Níṣọ̀kan la dúró Gbogbo wa la ó fayọ̀ sìn Ilẹ̀ ìbí wa ọwọ́n Àsìá wa yóò jami Pé ẹ̀tọ́ ló ń jọba Nígbàlàáfíà tàbí ogun Èyí yóò jérè wa Láti fi lé ọmọ lọ́wọ́ Àsìá láìlábàwọ́n Ọlọ́run gbogbo ẹ̀dá Gbọ́ àdúrà wa yìí Jẹ́ ká ní Orílẹ̀-èdè Níbirẹ́jẹ kò sí Kálàáfíà àti ọ̀pọ̀ Jẹ́ bùkún Nàìjíríà
Forgetting to address how Nigerians are suffering and fixing the problem. Instead you are coning up with a new "National anthem" that has nothing to do with anything. 🤦🏿♀️🤦🏿♀️🤦🏿♀️🤦🏿♀️🤦🏿♀️
e yii naa dara pupo!
Ẹ̀șé
❤
I really love this ❤❤❤
Nigeria we all thee
Ẹṣé tí ẹ fi ìfẹ́ hàn.
Such interesting lyrics
Bẹ́ẹ̀ni ni ò.
A kí ọ Naijiria
Ilẹ̀ ìbí wa ọwọ́n
Ẹ̀yà àtèdè lè yàtọ̀
Níṣọ̀kan la dúró
Gbogbo wa la ó fayọ̀ sìn
Ilẹ̀ ìbí wa ọwọ́n
Àsìá wa yóò jami
Pé ẹ̀tọ́ ló ń jọba
Nígbàlàáfíà tàbí ogun
Èyí yóò jérè wa
Láti fi lé ọmọ lọ́wọ́
Àsìá láìlábàwọ́n
Ọlọ́run gbogbo ẹ̀dá
Gbọ́ àdúrà wa yìí
Jẹ́ ká ní Orílẹ̀-èdè
Níbirẹ́jẹ kò sí
Kálàáfíà àti ọ̀pọ̀
Jẹ́ bùkún Nàìjíríà
I love this as a student ❤
❤🎉
It is ment to be the new national anthem
😅
Forgetting to address how Nigerians are suffering and fixing the problem. Instead you are coning up with a new "National anthem" that has nothing to do with anything. 🤦🏿♀️🤦🏿♀️🤦🏿♀️🤦🏿♀️🤦🏿♀️
Listen tó the lyrics.
😂