Láderin Lote Ilorin 1

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 20 окт 2024
  • Fún alaye àti ibere nípa Itan Yoruba ẹ kan si wa
    Aare Laji Abbas +2348023687432

Комментарии • 106

  • @SholaonikoyiAwopegba
    @SholaonikoyiAwopegba Год назад

    Aaa baba esun gan nio agbayin adale won olebi ooo awon asiwajuwa lotifa sugbon nipa ilorin Yoruba pelu Fulani ogun siunbo awon omo iran kiran

  • @bukolaladyb7821
    @bukolaladyb7821 Год назад

    E de jo ki e ko itan yin simu iwe ki gbogbo yoruba le mo itan ati awon omo wa. E joooo

  • @loantha2996
    @loantha2996 Год назад +11

    Best of the best 👌 👍🏻 Aare Laji Abbas. My Oluko Agba #1.

  • @safetydomain6861
    @safetydomain6861 Год назад +7

    God bless your knowledge Alhaji Laji Abbass. With Yoruba's history of creation and greatness, why are our leaders in Yoruba land not committed to putting yoruba first, work for our sovereignty and allow us to build the greatest black nation in terms of culture, technology and prosperity? How long shall we remain in the bottle called Nigeria? It doesn't matter how good and viable a seed can be, can a good seed ever germinate, flourish and bear fruit in a bottle that is covered? Never! That's what is happening to Yoruba in Nigeria, and our traditional, religious, and political leaders are not concerned because they are making money from the failure of Nigeria, and they are now afraid to speak truth to the power that is feeding them. Here in America, go and check it, we are the ones contributing immensely to the development of America's Healthcare, IT, research and development, yet our leaders can't see beyond today. If Yoruba become a Sovereign independent state today, we would only struggle for 2 yrs to purge out the Nigerian blood in us, and in another 10 years, Yoruba nation could be the Dubai of Africa. Why are the leaders satisfied with our captivity in the Nigerian union that was established by the British for their own business interests? How long should it take us to wake up. The time is now for the revolution to deliver ourselves from these leaders who are selling us to slavery in the Nigerian arrangement

  • @deedotist
    @deedotist Год назад +9

    Aarẹ Òrìṣà Itan, you are a PROPHET and HERO. Ori a má fún yin ṣe ❤

  • @emmanueldare1409
    @emmanueldare1409 Год назад

    Your genotype is real sir. May God bless your wisdom you're such a learned intellect (erudite) not just a mere illiterate

  • @olumakinwaisingbadebo706
    @olumakinwaisingbadebo706 Год назад

    Èè fun akitiyan ati alaye ooro nipa itan Yoruba ethnicity.

  • @alabiolanrewaju9869
    @alabiolanrewaju9869 Год назад +1

    God bless you sir...... Yoruba loni ilorin....e gba wa o....Omo bibi ilorin nimi

  • @bottomsuper1877
    @bottomsuper1877 Год назад +3

    I love your program please let all yoruba understand not to allowed illiterate people , uneducated people to bring lies and preach war in the name of religion. More blessing

  • @azeezkamarudeen8465
    @azeezkamarudeen8465 Год назад

    Ti a ba nso oro nipa itan, baba mi lajj Abass iba yin òo

  • @adeosunadebayo7145
    @adeosunadebayo7145 11 месяцев назад

    Good job you sir,Great historian.

  • @taiwoattah9617
    @taiwoattah9617 Год назад

    GOD. Almighty will bless you and your family and your Generation thanks, For what you are doing for YORUBA LAND,. For telling us about are Heritage YORUBA LAND.. LAJI ABASSY OLODUMARE Will Protect you for this great Job, that you are doing for YORUBA LAND thanks again .

  • @bukolaladyb7821
    @bukolaladyb7821 Год назад

    Iro nan pa fun yin bakan na ni, ni ilu Ilorin oo, won ti mix papo ni Ilorin oo

  • @jibolaadeniji1959
    @jibolaadeniji1959 Год назад +10

    Pls kindly document this story by written a comprehensive book, we can lay hand on it anytime, Kudos to you Sir.

  • @babatundeomoyeni2139
    @babatundeomoyeni2139 Год назад

    Thanks for the good Job. More fulfilment Sir.

  • @oyeyemisosanwo7646
    @oyeyemisosanwo7646 Год назад +6

    Thank you as always Aare Laji Abass, you've done very well 👍

  • @VeriteEquite
    @VeriteEquite Год назад +1

    Wow, I am speechless. This man's analysis is deep, impartial and of a doctoral standard.❤❤❤❤

  • @kehindeandu4040
    @kehindeandu4040 Год назад +3

    ARE OPITAN !!!
    YOU ROCK IT !

  • @bukolaladyb7821
    @bukolaladyb7821 Год назад

    Eku ise takun takun na sir.
    Ejo eje ki won gbe itan yoruba pada si ile eko

  • @Oklaby167
    @Oklaby167 Год назад +4

    May your days be long sir. You just gained another noble follower. I love the way you are backing your story up with written facts... Absolutley the best way to learn. You can never deny written facts and figures.

  • @ileifa1
    @ileifa1 Год назад +5

    I love this baba...❤... You are my role model ❤❤ 35:07

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 Год назад +9

    Wàhálà tó wà nínú kí èèyàn máa fi ààyè gba àlejò jù rèé.. Irú òun tó máa ń dá sílẹ̀ nìyí ni ti àwọn alábòsí ti wọ́n ń wípé Ìlọrin kii se ilẹ̀ Yorùbá yii.. Irú èyí tí àwọn kan ṣe ni ìlú Èkó tí wọ́n fi ààyè gba Ibo ju bó ṣe yẹ lọ.. Òun ló jẹ́ kí wọ́n máa ṣe gulegule ni Èkó,, Tí wọ́n ń wípé "no man's land" ni Èkó.. Àpẹẹrẹ rẹ̀ là rí nígbà ìdìbò tó kọjá yìí, tí a sì ṣorò fún wọn, tí a fi yé wọn wipé: "Ẹ bi baba yín léèrè, B'ẹ̀yin lẹ ni ìlú ni, B'àwa la ni ìlú ni, ẹ bi baba yín léèrè".

    • @adewilliams8
      @adewilliams8 Год назад +1

      Bee ni o, Ai tete mu ole, ole yio mu oloko ni oro yii. E kuu ise o!

    • @kehindejosephkashimawo9410
      @kehindejosephkashimawo9410 Год назад

      @@adewilliams8 Ṣùgbọ́n a gbọ́dọ̀ gbé àwọn ìgbésẹ̀ tó ní àpẹẹrẹ kí a fi yé wọn.. A ò gbọdọ̀ jẹ́ kó tán síbẹ̀ rárá.. Àjèjì kii bá onilẹ̀ du ilẹ̀.. To bá yá wọ́n á máa wípé àwọn tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà Yorùbá kan ni Èkó kii se omo Èkó, bí ẹni pé wọn kò mọ̀ wípé orisirisi eya Yorùbá bíi Awórì, Ìjẹ̀bú, Ègùn àti bẹẹbẹẹ lọ ní wọ́n jẹ́ gbogbo Lagos State pátápátá.. Fún àpẹẹrẹ, Ibo a máa wí fún wa pé Sanwoolu kii se omo Èkó àfi bí ẹni pé a lè fi Sanwoolu wé àwọn tí wọ́n wá láti ilẹ̀ Ibo ni ìkọjá tàbí lágbègbè odò ọya (River Niger) ni ìlà oòrùn Nigeria.. Wọ́n á máa lo ète aburú bẹ́ẹ̀ láti dà àárín wa rú.. Wọ́n á tún máa wí pé Fulani ni tibí Fulani ni tọ̀un...To sì jẹ́ wípé ète tiwọn gan ju ti Fulani lọ.. Ọ̀tá to ńṣe bí ọ̀rẹ́ ni wọ́n.. Ó yẹ kí a gbé àwọn ìgbésẹ̀ tó lágbára ni Èkó láti nísìnyí lọ. Kí àjèjì ó mọ ara rẹ̀ ní àjèjì... ..

    • @adewilliams8
      @adewilliams8 Год назад +1

      @@kehindejosephkashimawo9410 Ohun gbogbo ti o n se'le yii, fun itaniji awa omo Yoruba ni. nitoripe "Pansa ko fura, o jona; ti awa omo Yoruba ko ba so'ra awon atohunrinwa yio gbiyanju lati gba Ile wa sugbon awa ko ni gba fun enikankan lailai! Eniyan ko le sun ki a j'ogun re leyin, ti o ba ji tan ariwo a ta! Ariwo ti bere si nii ta bayi o. E seun.

    • @kehindejosephkashimawo9410
      @kehindejosephkashimawo9410 Год назад

      @@adewilliams8 Àwọn olóṣèlú wa àwọn Ọba, àwọn Baálẹ̀, àwọn Baálé gbogbo gbọ́dọ̀ ni itanijí lórí ọ̀rọ̀ yìí.. Àṣà àti ìṣe wa ńparẹ́ lọ.. Orisirisi eya ló wà ní Nigeria tí a kii sii ṣe ọ̀kan náà..

    • @Ifagbemileke444
      @Ifagbemileke444 Год назад

      ​@@kehindejosephkashimawo9410 Yoruba gbọdọ parapọ̀ lati majẹki awọn ajoji gba ilẹ Yoruba mọwa lọwọ nitoripe, idunkoko awọn ajoji yii ti pọju

  • @michaelbabs7288
    @michaelbabs7288 Год назад

    Hmmmmm....Yoruba!
    The language and tradition of the gods.
    I so much love my tribe ❤️

  • @akinkunmiabayomi9206
    @akinkunmiabayomi9206 Год назад

    AARE LADI ABASS TI DI ORISA ITAN , OYE KI AWA YORUBA SO LADI ABASS DI OBA ITAN ILE YORUBA

  • @oluotu5910
    @oluotu5910 Год назад

    Oba itan ❤Olorun yo da yin si fun wa

  • @sulaimonkiehinde1513
    @sulaimonkiehinde1513 Год назад

    More wisdom my brother

  • @Tm_tino
    @Tm_tino Год назад

    May Olodumare continue to bless u Baba Aare Opitan

  • @josephmaito213
    @josephmaito213 Год назад

    Alfa oniro, Labibu omo ikorodu ni, ohun njabo ni.

  • @truthpeace5644
    @truthpeace5644 Год назад +2

    E jowo baba, awon ara bi 'o duro o, won fe pa itan gidi re lati gbe itankitan ga. E jowo, e ko awon itan yi sinu iwe ki o di mimo fun gbogbo iran omo oko Yoruba.

  • @aramidedaniel4122
    @aramidedaniel4122 Год назад

    Aare, please document these facts. I pray this history will not go into extinction.

  • @adewumimonsuru4052
    @adewumimonsuru4052 Год назад

    God bless you sir 🙏 rederede awọn alfa oloṣuka pọ fah.

  • @olakassim5288
    @olakassim5288 Год назад +3

    Real history. Kudos

  • @abdullahijimoh
    @abdullahijimoh Год назад

    Thank you ❤ Aare laji Abbas inumi du popoo pelu Oro iten ilu Ilorin ❤😢 I love the story

  • @kennyolayinka9039
    @kennyolayinka9039 Год назад

    I always tell people say, Labeeb Lagbaji is Not a Muslim, Thank You sir Laji Abass for giving us the understand on ILORIN EMPIRE

  • @azeezzakariyau1260
    @azeezzakariyau1260 Год назад +7

    Baba mi ọlọhun o ba mi kẹ́ ẹ yin. 1:18:20.. i never knew what this oriki ẹ̀ṣọ́ means untill today.

  • @M.dOlarewaju
    @M.dOlarewaju Год назад

    you are bless in the name of alha❤

  • @babatundeogundipe7674
    @babatundeogundipe7674 Год назад

    I need to speak with you privately. You have a serious job in your hands to put all of there down in black and white for the generations yet unborn. So that Fulani and others won't tell our children a false history of their heritage and root. I will call you sir.

  • @jasanyaadewunmi7063
    @jasanyaadewunmi7063 Год назад

    As much as I appreciate your dexterity in the history of the Yorubas. I will also enjoy you to document all these for future. Please it's very important.

  • @adekunleezekiel6935
    @adekunleezekiel6935 Год назад

    More wisdom baba Ààrẹ ìtàn

  • @abdullahijimoh
    @abdullahijimoh Год назад

    Oju ti tiwo awon omo ale Ilorin be ni ❤

  • @bukolaladyb7821
    @bukolaladyb7821 Год назад

    Fulani ni won, ema yorayin lenu

  • @shesaniwaloye2023
    @shesaniwaloye2023 Год назад

    Baba mo ngbadun eee ooo ❤❤❤❤

  • @oladejosaheed4384
    @oladejosaheed4384 Год назад +2

    Pls Are put all dis thing into record like book for the future of our children...

  • @josephmaito213
    @josephmaito213 Год назад

    Omo ikorodu ni alfa toun so itan, mi o ki nse egbe were yi.

  • @bukolaladyb7821
    @bukolaladyb7821 Год назад

    Ti won ba pe oruko yoruba mo oruko won, a tete mo pe yoruba ni eni ten so re

  • @bukolaladyb7821
    @bukolaladyb7821 Год назад

    We need history in school.
    Afe itan ni ile eko wa

  • @olumakinwaisingbadebo706
    @olumakinwaisingbadebo706 Год назад

    The truth is always better. Yoruba now

  • @bottomsuper1877
    @bottomsuper1877 Год назад

    Mr wisdom .very simple analysis

  • @olumakinwaisingbadebo706
    @olumakinwaisingbadebo706 Год назад

    Opolopo awon eniyan
    wa alaimokan ni wan

  • @josephgbolabo2401
    @josephgbolabo2401 Год назад

    Aare Ojo Adale , please leave that guy alone he really sick , kindly talk to our government the nation is getting tougher every day , God bless you

  • @oyebodeoyerinde420
    @oyebodeoyerinde420 Год назад

    Awon Alfa ti Awon baba won ntoro baara ni Ile Yoruba niwon NSO Itan tiwon ko mo,

  • @onipofiabdullateef7229
    @onipofiabdullateef7229 7 месяцев назад

    Baba laji Abbas, May Allah bless your for preparing the Yorubas for the posterity right,your hankering towards affirming the reality in the context of history of Yoruba is a top notch one. I'd be glad to discuss with you regarding the issue of laderin because I have a contrary opinion to yours, permit me to point to Sheikh Adam Abdullahi Al Ilory as a source of my conversation. He was the one said something different about laderin. Please forward me your number for a better discussion. Thank so much , Sir.

  • @kehindeosenisaliman3247
    @kehindeosenisaliman3247 Год назад

    Awon èru èsin musulumi èru mecca Awon èru saodi arebia

  • @ShamsideenOlajide
    @ShamsideenOlajide Год назад

    Abdallah ni oruko baba e, kii de se Muslim

  • @olumakinwaisingbadebo706
    @olumakinwaisingbadebo706 Год назад

    Oloye Raji Abbas : ki Oluwa kio ran yin lowo

  • @kehindeosenisaliman3247
    @kehindeosenisaliman3247 Год назад

    Oloriburuku ni labeebu omo alé èru fulani ni gbogbo awon afah yen

  • @OluwatoyinMudashiru-ph5ww
    @OluwatoyinMudashiru-ph5ww Год назад +2

    Are,Opitan,kare,omo,,oko,opolo,e,o,ni,daru,bafa,oloribu,ni,ejo,ko,awon,babala,wa,na,si,alejo,gba,ti,awon,babala,ni,aye,atijo,won,ko,eyan,mora,ni,gbogbo,agbaye,awa,yoruba,la,ko,eyan,mora,ju,ki,oloun,sanu,awon,baba,wa,gba,alejo,oran,

  • @davidolurin5019
    @davidolurin5019 Год назад +1

    Ese o emiyin a gun Olorun a ma fi ogbon kun ogbon yin

  • @olumakinwaisingbadebo706
    @olumakinwaisingbadebo706 Год назад

    Yoruba NATION must depart from Nigeria's territory and stay autonomy.

  • @funshofrankbabatunde
    @funshofrankbabatunde Год назад

    The fulanis are the interviewers. Labeed eru fulani

  • @BR-tc8wo
    @BR-tc8wo Год назад

    Labeeb that cannot fight with Saidi Shittu is the one fumbling here. Elenu lasan lasan !

  • @rotimiboadley5112
    @rotimiboadley5112 Год назад

    Bawa opintan epe laaye kanrin kese ninu alafia .

  • @muritalabello8653
    @muritalabello8653 Год назад

    Great job

  • @cosmasadebowale5877
    @cosmasadebowale5877 Год назад

    Good Comments by Alhaji Abais

  • @hamzatjamiu4926
    @hamzatjamiu4926 Год назад

    Very interested

  • @bukolaladyb7821
    @bukolaladyb7821 Год назад

    Please sir put all the history you know into writing. Oruko yin on pare ninu ile yoruba lai lai.

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 Год назад

    Laaye. Beeni

  • @olabisisanusi9601
    @olabisisanusi9601 Год назад

    Awon naa mo wipe Ilorin koki se hausa llorin is part of yoruba

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 Год назад

    FACTS of life.

  • @M.dOlarewaju
    @M.dOlarewaju Год назад

    thanks

  • @toluwaladeoluwasoji3959
    @toluwaladeoluwasoji3959 Год назад +1

    Ilorin need to slow down and learn.. all his saying about ilorin a big truth. When they do that the land will be a big peace within. Fulani as cost a big messed up in that land and bastards and supporting bad things...

  • @akinolaakinpelu3604
    @akinolaakinpelu3604 Год назад

    Please write Yoruba history in a book.

  • @evanielsen8683
    @evanielsen8683 Год назад

    What about ojo ise kuse ?

  • @OluwatoyinMudashiru-ph5ww
    @OluwatoyinMudashiru-ph5ww Год назад +1

    Were,ni,olorun,e,ri,to,we,gele iya,sori,oloribu,ko,ni,dagba,takaka,alagidi,ñi,olosi,omo,ale,to,ya,ti,aba,gbale,yoruba,wa,gbogbo,awon,fulani,ado,malu,ĺá,ma,le,danu,olosi,omo,malu,oloribuŕuku,malu,o

  • @ShamsideenOlajide
    @ShamsideenOlajide Год назад

    Anobi gan yi nje Mohammed ki Islam to de

  • @evanielsen8683
    @evanielsen8683 Год назад

    All of you sha want orisha akunlebo in ilorin it can never possible

  • @bunyaminabdulhakeem5509
    @bunyaminabdulhakeem5509 Год назад

    Laderin ko Ladefon ni 🤣🤣🤣🤣

  • @OluwatoyinMudashiru-ph5ww
    @OluwatoyinMudashiru-ph5ww Год назад +2

    Are,o,pitan,ose,emo,gba,fun,awon,ijoba,oloriburuku,fulani,yi,itan,wa,e,ma,je,o,pare,tori,ni,afi,pe,ki,ama,ko,eranko,mo,eyan,fulañi,omo,malu,ejo,won,ko,ojo,lo,ko,eyele,po,mo,edie,were,ni,irán,aba,malu,sun,apoda,oloru,o,

  • @ademolaatanda763
    @ademolaatanda763 Год назад

    Hippocrates ni a won alfa ye

  • @OluwatoyinMudashiru-ph5ww
    @OluwatoyinMudashiru-ph5ww Год назад +1

    Se,bori,bo,ri bi,anta,olorikori,elenu,ya,bi,igba,sakara,omo,ale,fulani,iran,malu,darandaran,onibara,oloribu,onigele,opa,medogun,olosi,eru,esin,osinwin,iran,adaran,se,bori,bo,se,tun,leri,bi,ako,alangba,adarikoko,oni,dun,oni,nago,labe,,alara,gbigbe,onibara,,onigele,ya,onigele,oran,o,onibe,lenu,bi,teye ,olosi,eleke,papo,bi,amuku,osan,were,aro,ejeti,ta,si,lopo,ara,aroo,

  • @dayobalogun5248
    @dayobalogun5248 Год назад

    I believed your account but why have you not replied baba ni agege that started this revisionist

    • @abimbolaoyelowo1606
      @abimbolaoyelowo1606 Год назад +4

      How many times will that be done, you should have gotten answers if u have been following for the past 3 years. He has thrashed that from depth to brim

  • @mamaiya6633
    @mamaiya6633 Год назад

    E gbon iro funfun ti Alfa yi npa wipe Afonja sa wa ba awon ni Ilorin ni ,lieing to people as if they're not stranger to Afonja.Omo- oko yoruba tooto wake up and let us come together and drive out these Fulanis from Ilorin and the whole yoruba land.

  • @olalekanrichmore4948
    @olalekanrichmore4948 Год назад +1

    Labeebu lagbaji oponu ni o.omo ale lawon Fulani ilorin

  • @OluwatoyinMudashiru-ph5ww
    @OluwatoyinMudashiru-ph5ww Год назад +2

    Ejo,e,ko,bi,erun,ba,pe,ile,o,ma,bu,alajobi,olosi,alagidi,talika,omo,ale,emo,gba,fun,kan,pa,itan,wa,re,anigba,fun,won,,tori,e,ni,afi,pe,ki,onikaluku,gba,ilu,e,lo,e,ma,gba,fun,won,awa,yoruba,ni,ani,ilorin,apoda,ni,oloru,onigele,ofó,alakisa,onibara,ni,

  • @akinkunmiabayomi9206
    @akinkunmiabayomi9206 Год назад

    Imagine all lies this people are telling through Arabic. If they can lie in yoruba history, imagine the Arabic language

  • @yinkamark5markit582
    @yinkamark5markit582 Год назад

    Thank you our Father. The extremes Alfa's and some Muslims are giving Yoruba's Race too much problems. They must put stop to this.

  • @22creativeempire27
    @22creativeempire27 Год назад

    Mr laji you said quran teach you so much what about our ancestors did they not teach you everything you you today itan yoruba you're telling people is yoruba story not Arab. You're confused if you're yoruba you can't bit be Muslim

  • @mamaiya6633
    @mamaiya6633 Год назад

    Awon Alfa oloorun,oni iro pelu bedsheets osi ti nwo ngbe ru u,awon omo Fulani ti nwo fe gba ilu Ilorin lowo awon Omo-Oko yoruba tooto ti o ni ilu,All these jobless Alfas that doesn't have job than lieing to people about their religion will make alot of people not to be come Muslim. They always behave as if they're the P A of Allah they call.But they're liers,all they're doing is to please the Saudi Arabia people in other to get money, promising them that they will turn Ilorin and whole yoruba land to a Muslim Nation. Always talking as if they're not stranger in Ilorin, calling Ilorin Geri Alimi ,instead of Ilorin Afonja. Our elders in yoruba land and all Afonja family wake up and join hands with all the real Omo-Oko yoruba tooto and drive all the Usman Dan Fodio generation back to their land in Futajalon. Thank you Oloye Laji Abass,we shall always support you in promoting our Yoruba history.

  • @bottomsuper1877
    @bottomsuper1877 Год назад

    They 're beggars .

  • @Drolafimihan
    @Drolafimihan Год назад

    Eranko ni labeeb . zero brain 🧠

  • @OTUNBABOLAJI
    @OTUNBABOLAJI Год назад

    Please which language exactly this useless and shameless language are they speaking? They cannot preach with any other languages than Yoruba let one of them do lecture with Fulani or Hausa language that they are claiming.