Kemi Olufunto Adegoke Badenock, Ọmọ Yoruba Atata

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 22 дек 2024

Комментарии • 85

  • @oliveodele3514
    @oliveodele3514 7 дней назад +6

    Seun Kuti ndogbon lati wo inu ijoba Nigeria 🇳🇬 ni omo ale oti gbagbe ohun ti Ijoba Nigeria fi oju iya baba e ati baba e ri. God Almighty shall shield 🛡️ Kemi she’s our own daughter ❤. Great 👍!

  • @christianamustapha2441
    @christianamustapha2441 7 дней назад

    Ogbeni Bobby Akueto Eledumare Àgbawa lowo Àwon Omo ale Najiriya ooo Yoruba atata i le yoruba Kiya Kiya ❤❤❤❤

  • @sikiruoluwasegun6804
    @sikiruoluwasegun6804 7 дней назад +2

    Atokun eku eto, God blessed oluwa kemi olufunto, imukumu toun mu ni o unda seun lamu,ko lo gbenu dake,won ti gbowo fun

  • @kudiogunnaike305
    @kudiogunnaike305 7 дней назад +1

    Thank You Lord Almighty for answering our prayers and always being there for us. We are Grateful Abba Father 🙏💐👏🙏. Well done 👍 from Colchester

  • @yemiige9990
    @yemiige9990 7 дней назад

    Ogbeni Bob , emaa simi diedie o. Tori mo ti gbo agbo ile ni osan Sunday.
    Oya mi lenu lati ri yin again .
    Olorun yoo kun yin fun agbara o. 🙏🙏🙏

  • @funkejames4223
    @funkejames4223 7 дней назад

    Good evening sir ogbeni Bobby.. e ku eto..aseti o si fun eledumare.. Oluwa A bawa se yori o amin

  • @JosephineAlawiye
    @JosephineAlawiye 7 дней назад +1

    Ogbeni Bobby, MO ngbadun oro otito te so si (SEUN KUTI) Ko ya MI lenu, Ara re ko bale bi awon egbon.❤❤❤❤❤❤❤

  • @margaretibijoke4973
    @margaretibijoke4973 7 дней назад

    E ku ise takuntakun o jare ogbeni Bobby, Olorun ti gbe Kemi Badenock soke na, oke oke ni o si maa lo, ninu egun ni mariwo Kemi yoo ti soso re, loruko Jesu 🙌🙏❤️

  • @MinaNoia
    @MinaNoia 8 дней назад +3

    Good evening sir ogbeni Bobby happy Sunday yoruba nations know going back much love for you ❤❤❤❤❤

  • @justinafawumi812
    @justinafawumi812 7 дней назад +1

    Ki awon na yi pada kuro ninu ninu iwa jibiti ati tani ma mu m i ki won se atunse.Olorun Eledumare awa pelu Kemi Badenoki asi se ase yori lagbara Eledumare. Yoruba nation ni awa reti Olorun asi ba wa se ni aseyori ❤❤❤❤❤❤

  • @OlabisiBabatundeFayomi
    @OlabisiBabatundeFayomi 7 дней назад +1

    Ogbeni Bobby, Ema but onugbo ooo, Kalakuta Republic, sugbon awon lokan, won sha white , sumu sumu laye gba, oga ooo

  • @JosephineAlawiye
    @JosephineAlawiye 7 дней назад +1

    Eko wo loni, Talo to SEUN KUTI. Oruko (FELA BABA) re lo gbe Sita. Woran,woran re po.(Kemi ti gun oke agba ,(Yoruba Nation ) ni Tiwa Eleda ti fowo si) Aamin😂❤❤❤😂 Love to Aaya. From UK.

  • @justinafawumi812
    @justinafawumi812 7 дней назад +1

    Ogbeni Bobby eku eto asi tun ku isimi oni. Efi awon ti so isokuso lori oro Kemi Badenoki sile,ara ni o nta won se emo wipe eni ta ba na ni ara nta , ati wipe igbe ki ke ni ise ibaka eje ki won ma ke kiri
    😂😂😂😂😂😂😂

  • @OlufunkeAdesanya-t9b
    @OlufunkeAdesanya-t9b 7 дней назад +1

    Ogbeni Bobby e ku ise takuntakun. Se alaafia ni Ile wa. A ku pale mo odun. Odun ayo la ma se loruko Jesu.

  • @OlabisiBabatundeFayomi
    @OlabisiBabatundeFayomi 7 дней назад +1

    Seun Kuti na small goat Ewure,
    Abami Eda ma fun ni ifoti gbona laipe

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 7 дней назад +1

    Ori Seun kope, omo amugbo,igbo ti yi lori, iya baba re le oba lori oye ( Olufunlayo kuti.)ailosi ile iwe kojeki ori re pe.😂😂❤ nitori inu nbi fun gbogbo ohun ti o nsele si wa.

  • @jeremiahobanishola9425
    @jeremiahobanishola9425 7 дней назад +1

    Iba,fela gan ja ija pe ki Yoruba da duro.

  • @kehindeadanri1670
    @kehindeadanri1670 7 дней назад

    Ogbeni Bobby eku Etoooo.
    Aku isinmi o.

  • @jeremiahobanishola9425
    @jeremiahobanishola9425 7 дней назад

    Iba gbewon debe of Yoruba nation.. iba,loogun ofe ooo.eku ise takuntakun,yio ma dun yin see.mo gba ti fila yi o.

  • @usmanwahab6262
    @usmanwahab6262 8 дней назад

    May God bless kemi berdennork and bless Yoruba nation

  • @moradeyoalaba9406
    @moradeyoalaba9406 7 дней назад

    Happy Sunday, how is weather over there. Yoruba's should be wise now,not to see any fault or speaking Carelessness about Kemi Badenoch ,but to see reasons for her words. She was insulting by Vice president Shettima by saying she should remove her Yoruba name..Do will want her to keep muted. I am proud of her .kudos ❤❤❤😂😂😂. Yoruba Nation Forward Ever. Thank you and God Blessed you.
    Seen kuti ko mo ohun ti o nso ni o.Eniti Nigeria ti fi agbara ba ebi e ja titi ti emi won fi loo si.o se ise omo lasan ti kemi jewo Omo Oko.ati ogidi ti o si mo esi oro. Olorun Eledumare yoo maa pelu Kemi ati ninu gbogbo igbese re ,Orun o maa se Alatilehin re ati gbogbo ibi ti Omo Yoruba atata ba gbe wa Amin Ase.

  • @ibrahimbadamasi1211
    @ibrahimbadamasi1211 7 дней назад +1

    Omo oko Yoruba Oluwa Kemi gbo gbo Omo Yoruba eku ori reoo remain blessed

  • @kennyogunkoya3634
    @kennyogunkoya3634 7 дней назад

    Ogbeni Bobby aku similar oni o ase opolopo re laiye laye laye to dara o

  • @ajaratsalako3998
    @ajaratsalako3998 7 дней назад

    Ogeni Bobby. E ku eto o. Olorun a de ise yin lade.

  • @taiyeajiboye3968
    @taiyeajiboye3968 7 дней назад

    Olukemi Badenoch God will protect you,you be bless,Yoruba nation no going back.

  • @sofoluwesongonuga4212
    @sofoluwesongonuga4212 7 дней назад +1

    OGBENI BOBBY AND KEMI BADENOCK . BOTH ON TRACK YORUBA COUNTRY TI DURO.

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  7 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @Joladeallison1351
    @Joladeallison1351 7 дней назад

    Ogbeni Bobby a day fun e oh. 😂😂. Omo Yoruba atata ni Kemi Badenoch.

  • @MotunrayoAreke
    @MotunrayoAreke 7 дней назад +1

    Same to u sir boby ❤❤❤❤❤❤

  • @SundayOguntuase-u9m
    @SundayOguntuase-u9m 7 дней назад +1

    I Sunday,I am more Yoruba than Nigerian.

  • @MotunrayoAreke
    @MotunrayoAreke 7 дней назад +1

    Good evening sir bobby

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 7 дней назад +1

    Ori Seun kope, omo amugbo,igbo ti yi lori, iya baba re le oba lori oye ( Olufunlayo kuti.)ailosi ile iwe kojeki ori re pe.

  • @AshimiBose
    @AshimiBose 7 дней назад +1

    Ogbeni boby eku eto yoruba nation no going back

  • @BdhhsdBbsbbd
    @BdhhsdBbsbbd 8 дней назад

    Hello oooo ogbeni bobby happy Sunday my lovely friend iba to gbagbe wa ni Cairo

  • @juliannaolujinmi2009
    @juliannaolujinmi2009 7 дней назад

    Kehinde is joining the team happy Sunday Ogbeni Boby

  • @AshimiBose
    @AshimiBose 7 дней назад +1

    Ogbeni boby happy Sunday Yoruba nation no going back

  • @SeriOgunyemi
    @SeriOgunyemi 6 дней назад

    Well come ogbeni bobby eki etooo

  • @martinadebowale3839
    @martinadebowale3839 7 дней назад

    Beni ile ijosin ni awon were wa. Se won sese lo eyan ni onpe. KEMI o ba Babanla wo.

  • @hadjiyaro881
    @hadjiyaro881 7 дней назад +1

    OGBENI BOBY WASERE CONFIRM,SEUN FESO AWON ONIGBO DI OPONU AFOFUN GBEMU BI TI E AWON OLORIBURUKU DEEDE 😂😂😂😂😂😂😂😂

  • @oluwolebakare398
    @oluwolebakare398 7 дней назад +1

    Igbo ti seun n'mu o je ki ori e pe mo. Ti baba e Fela ba wa laye a gbe oriyin fun Kemi Badenoch.

  • @SulaimonYusuf-u3t
    @SulaimonYusuf-u3t 7 дней назад

    Mr Bobby happy Sunday

  • @AdunniAyoola-j6c
    @AdunniAyoola-j6c 7 дней назад

    Yoruba Nation no going back ooooooooo

  • @oliveodele3514
    @oliveodele3514 7 дней назад +1

    Shettima should remove his Fulani name too before talking to Kemi😮YORUBA nation no going back!

  • @titilayooyebanji-ps9sg
    @titilayooyebanji-ps9sg 7 дней назад

    Mo si oko wa mon

  • @Joladeallison1351
    @Joladeallison1351 7 дней назад

    The Almighty God will protect Kemi Badenoch. His shield will be around her.

  • @afolabiroseline351
    @afolabiroseline351 7 дней назад

    Inu mi dun pupo Lori Oro Kemi Badenoch Yi. Olorun Oba Alaanu yio bawa roo ni agbara. Owo awon asebi ko ni kaa. Kemi yio tubo goke agba. Yio maa ni enu Oro ni o.

  • @kikelolaolaitan4137
    @kikelolaolaitan4137 7 дней назад

    Awon oyinbo Uk gangan lo gbe Fulani sori Yoruba ati Igbo. Yoruba no dey gree for anybody .

  • @kikelolaolaitan4137
    @kikelolaolaitan4137 7 дней назад

    Ara lo ta won, oro na dun won, e ma sokun ku ni gbogbo iran Fulani ati iran aguachukwu. Iran Yoruba nikan lo de ipo Oluwakemi. Oro dun won, e ma sunkun ku ni .😭😭😭

  • @oregbesanmulikat8292
    @oregbesanmulikat8292 7 дней назад

    Sewu kuti omo ale yoruba

  • @Joladeallison1351
    @Joladeallison1351 7 дней назад

    Nigeria, ikoko obe UK ni.

  • @dupebello3442
    @dupebello3442 7 дней назад

    Kemi so fun igba keji Tinubu pe o ye kio wa ni ogba Ewon oni o wa nsoro pe ki oun yo Kemi kuro lori oruko oun. O daro Bubby Buuby aje pe Aye

  • @martinadebowale3839
    @martinadebowale3839 7 дней назад

    Igbo ti yi Lori.

  • @rgbphotomediaprod.2384
    @rgbphotomediaprod.2384 7 дней назад +1

    Seun o gbadun rara, koseku koseiye ni gbogbo oro tonso ni gbogbo aiye e. Kojo Fela ninu oro siso.

  • @AbimbolaIlesanmi
    @AbimbolaIlesanmi 7 дней назад

    Aku isinmi oni o Iba ifesowapo ati gbogbo ile o,emi wa yio se opo isinmi laye lalaafia lagbara Olorun, se awon ota fe ki Kemi pe ara re ni omo Hausa tabi Ibo ni? radarada

  • @hadjiyaro881
    @hadjiyaro881 7 дней назад

    SEUN TIFA IGBO ORI SAARE 🚬🚬🚬😂😂😂😂😂😂😂😂

  • @kikelolaolaitan4137
    @kikelolaolaitan4137 7 дней назад

    Emi gege bi enikan ko pe ara mi nigerian, omo oduduwa ni mo ma pe ara mi. Aboki ko le gbe Uk ni bi ko si owo ofe bi ti Abuja.

  • @OlabisiBabatundeFayomi
    @OlabisiBabatundeFayomi 7 дней назад

    Baa Ayaa

  • @dorcaslamid9029
    @dorcaslamid9029 7 дней назад

    Tunubu wo awon fulani niran ni,kanran keku maje sese afi se awadanu, ni Tunubu ma fi oro won se, igbeyin laloyo ta

  • @Joladeallison1351
    @Joladeallison1351 7 дней назад

    Seun Kuti njewo Omo bi o se je ni😢😢😢

  • @femijosiahakinrebiyo2712
    @femijosiahakinrebiyo2712 7 дней назад

    Yoruba ni mi tokantokan

  • @Trimisu
    @Trimisu 7 дней назад

    God will help kemi.

  • @kikelolaolaitan4137
    @kikelolaolaitan4137 7 дней назад

    Mo ko ko ro pe Seun ni opolo ni sugbo orire ko pe rara. Ijoba amunisin to se iku pa iya baba re(Funmilayo, akoni obirin). Akoni enia ni awon egbo ati baba re.

  • @taiyeajiboye3968
    @taiyeajiboye3968 7 дней назад

    Pete Pete ti a ba naa ni Pasan eni ti o ba ta ba ko ma binu,fulanis e lo tun be see,e fi Yoruba Lorun sile.

  • @oregbesanmulikat8292
    @oregbesanmulikat8292 7 дней назад

    Omo oko yoruba ni kemi

  • @mrscpower6200
    @mrscpower6200 7 дней назад

    Olorun a ma ba wa duro ti omo wa atata ti Olorun ba wa fa lowo soke. Olorun to da orun ati aiye ko ni fi Kemi Badenock le ife awon ota lowo. Seun kuti ti ori e ti gbale Igbo ti Seun nmu ko je ki o gba dun. God will forgive her because we are imperfect and He will always raise her up ijn. Fela baba Seun did worse than anyone to Nigeria government

  • @adeleyeabimbola1432
    @adeleyeabimbola1432 7 дней назад

    Ogbeni Bobby ,e seun gaan lopolopo jare ,E woo sir e ko ma pe oorun osan ni Seun kuti fi wa sile aye ni .ati eje igbo iya ti bi seun kuti maa nba baba re fela Jo kaakiri ni ko to dii pe o di aya fela omo ale patapata gbaa ni seun kuti.

  • @margaretibijoke4973
    @margaretibijoke4973 7 дней назад

    Tinubu o ni soro, sugbon yoo gbabenu, sugbon Olorun yoo pade awon sebi sebi

  • @aderemiadeeko8509
    @aderemiadeeko8509 7 дней назад

    Kemi parents are Yoruba. Basically she is Yoruba.
    However, She has her choice if she does not want to claim a Nigeria citizen. She is Black British citizen because she has Great Britain Birth certificate.
    She does not have Nigeria birth certificate - is a fact.

  • @dupebello3442
    @dupebello3442 7 дней назад

    Se e mo pe church Harikisna boya oun lo nda ori Seun ru tio je kio mo nkan tio nse ati tio nso gbogbo be ina lo ma jo won

  • @dorcaslamid9029
    @dorcaslamid9029 7 дней назад

    Ti Tunubu baripe Won ni je kohun wo ile ni 2027,o ma pin Nigeria ni

  • @titilayooyebanji-ps9sg
    @titilayooyebanji-ps9sg 7 дней назад

    Oskontolo.oskente. oleku.oleju.Nibo ni ka ti.pade e non.Dressing yi le o

  • @mrscpower6200
    @mrscpower6200 7 дней назад

    Seun is in relevant, he doesn’t have sense, Omo oko ni Kemi Adegoke Badenock je. God that fight for David in the bible will always fight for Kemi ijn

  • @HannahAdeboye
    @HannahAdeboye 6 дней назад

    @Ọ́gbẹ̀ni Bọ́bì mí! Just seen ó

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 7 дней назад +1

    Ori Seun kope, omo amugbo,igbo ti yi lori, iya baba re le oba lori oye ( Olufunlayo kuti.)ailosi ile iwe kojeki ori re pe.😂😂❤ nitori inu nbi fun gbogbo ohun ti o nsele si wa.

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 7 дней назад +1

    Ori Seun kope, omo amugbo,igbo ti yi lori, iya baba re le oba lori oye ( Olufunlayo kuti.)ailosi ile iwe kojeki ori re pe.

  • @mrscpower6200
    @mrscpower6200 7 дней назад

    Olorun a ma ba wa duro ti omo wa atata ti Olorun ba wa fa lowo soke. Olorun to da orun ati aiye ko ni fi Kemi Badenock le ife awon ota lowo. Seun kuti ti ori e ti gbale Igbo ti Seun nmu ko je ki o gba dun. God will forgive her because we are imperfect and He will always raise her up ijn. Fela baba Seun did worse than anyone to Nigeria government

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 7 дней назад +1

    Ori Seun kope, omo amugbo,igbo ti yi lori, iya baba re le oba lori oye ( Olufunlayo kuti.)ailosi ile iwe kojeki ori re pe.😂😂❤ nitori inu nbi fun gbogbo ohun ti o nsele si wa.

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 7 дней назад +1

    Ori Seun kope, omo amugbo,igbo ti yi lori, iya baba re le oba lori oye ( Olufunlayo kuti.)ailosi ile iwe kojeki ori re pe.

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 7 дней назад +1

    Ori Seun kope, omo amugbo,igbo ti yi lori, iya baba re le oba lori oye ( Olufunlayo kuti.)ailosi ile iwe kojeki ori re pe.😂😂❤ nitori inu nbi fun gbogbo ohun ti o nsele si wa.