EMEFIELE, ASIKO IDAJỌ TI DE, MAA GBADUN AYE Ẹ LỌDỌ AWỌN DSS

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 5 окт 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Комментарии • 24

  • @sabainahadetunmbi3661
    @sabainahadetunmbi3661 Год назад +4

    Oluwa yio mu gbogbo won

  • @saheedadewale5901
    @saheedadewale5901 Год назад +2

    Iya Alaroye mo n gba dun yin gan nii ooo lati Dubai

  • @afolayanajisafe8809
    @afolayanajisafe8809 Год назад +1

    Madam olohun iyo eku ise o
    Ohun yin konisa amin

  • @olanrewajumiftaushittu535
    @olanrewajumiftaushittu535 Год назад +3

    Eyin leemo ohun ti buhari ko fi lee, sugnon emi maa.
    Ohun nipe t'oba je ahusa ni igbakejii re ni ti kii se Yoruba, buhari o bati yoo.
    Yoruba ni igbakeji aare ati olori ile igbimo asojusofin, aati wa gbo pe awon naa tun ni gomina CBN? Notori naa, idi niyen

  • @biochar.
    @biochar. Год назад +3

    you this woman😄🤣😂

  • @omoshewayinka2581
    @omoshewayinka2581 Год назад +3

    Bi Òlòrun şe ma mu won lęyo kan kan niyęn ..

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 Год назад +1

    If Tinubu wants to fix Nigeria problem he should change the constitution.

  • @kehindebellosikirubello989
    @kehindebellosikirubello989 Год назад

    Emefiele oloriburuku eda eyan

  • @adecrown4413
    @adecrown4413 Год назад +1

    O ma seo. Asi tun ri awon to nkorin gbe Emefiele. Nigeria.

  • @abbeylove4934
    @abbeylove4934 Год назад

    Emefiele onibo ninu eleyi ooo

  • @saheedadewale5901
    @saheedadewale5901 Год назад +1

    Oni agbara oooo

  • @heleno1327
    @heleno1327 Год назад +1

    Emefiele nikan ko lo ye ki won mu oye ki won mu Buhari na,Olorun amu gbogbo won Ishallau

  • @lambeoluwaseyi6604
    @lambeoluwaseyi6604 Год назад +1

    OLORUN.OBA ADUPE.OOOO

  • @mustaphaalibagu2662
    @mustaphaalibagu2662 Год назад

    Emefiole should be treaded as harding criminals, any money & properties collected from him should be use to rebuild new banks in ishagamu Ogun state. He's a wicked man, I believe he didn't acted alone but with the then presidencies and wives of presidencies

  • @Oodua-ii
    @Oodua-ii Год назад

    Please thumbs up this video. Thank you.👍

  • @classyjoyce5452
    @classyjoyce5452 Год назад

    Olorun amu gbogbo won

  • @oyewole5530
    @oyewole5530 Год назад +1

    They will release him before you know it

  • @jamiumeyile-hh3uz
    @jamiumeyile-hh3uz Год назад

    God go punish you emifeele lekan si jagagba la fe oooo

  • @EstherPrince-tk8qd
    @EstherPrince-tk8qd Год назад

    Tinubu himself will be arrested because himself is a corruption man

  • @solomonadegbenle2219
    @solomonadegbenle2219 Год назад +1

    OLORIBURUKU ati ERU Tinubu ni eyin ALAROYE ti endarapo mo iwa buruku Tinubu,
    Gbogbo yin lemo wipe olori odaran ni Tinubu yin,
    Amo nitori wipe oga yin ni criminal Tinubu,
    Eko lati so ododo iyin OLORIBURUKU gbogbo won yi.

    • @tayelolugbenga1898
      @tayelolugbenga1898 Год назад +1

      Omo ale. Listen to ursef.

    • @mariamasie9329
      @mariamasie9329 Год назад

      Truth never die

    • @timothywale8055
      @timothywale8055 Год назад

      Emai ti jeka bu Alaroye ore mi , esin ma jeki ade oju wa sile na ,lati ma wo Maradona keji fun odun meji na ,ki ni igbayeh lao to mo ibiti oloko nwa wa lo