IJAKADI NLA BESILE LARIN ELESIN IMOLE ATI ELESIN IGBAGBO

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 8 сен 2024
  • TA LO MA PARI IJA YI

Комментарии • 13

  • @user-bd3ih2en3o
    @user-bd3ih2en3o 2 месяца назад

    Kogbodo si abosi ara,kiawon onidajo ibile Yan,tabi,agbofinro,koyanju Oro ija naa pelu,idajo toje ti iberu Olorun.

  • @tinaparker5248
    @tinaparker5248 2 месяца назад

    10 10 ❤

  • @KehindeoseniSaliman-ou4jt
    @KehindeoseniSaliman-ou4jt 2 месяца назад

    Awon ELEsin mejeji na ni won NBA gbogbo Ile Yoruba Jen ooo

  • @user-ig6zg4zp4p
    @user-ig6zg4zp4p 2 месяца назад

    E jowo ki kabiyesi ba wa bomin ero si Yoruba ko tun Gbodo barawonja lasiko Yi o Yoruba ,e sa jowo oo ,ki o ma da bii edi ,kisteni munsulumin e ma je kase rawa ni eleyame ya baba to nsoro Yi Yoo Dara fun yin o , e ba wa pati re ,

  • @user-dm2lm2dw2e
    @user-dm2lm2dw2e 2 месяца назад

    E Fi suru si ija esin, ema je Ko da Ogun sile ni Ile Yoruba,ki awon agba gba ki won pari ija fun won,ki eje ki Ife joba

  • @adefemiojokanke5222
    @adefemiojokanke5222 2 месяца назад

    Ekueto baami

  • @OkeowoTaiwo
    @OkeowoTaiwo 2 месяца назад

    Baba arole 10 10,ohun to pamo oju olorun olorun lo to.awa o fe ija esinkesi nile yoruba.yoruba nation now now

  • @KehindeoseniSaliman-ou4jt
    @KehindeoseniSaliman-ou4jt 2 месяца назад

    Yoruba nation nikan na ni ONA Abayo fun gbogbo Ile Yoruba patapata ooo

  • @user-bd3ih2en3o
    @user-bd3ih2en3o 2 месяца назад

    Se ni île yoruba ni ijayi ti sele?Awa o ni GBA ija ESIN laaye rara ni gbogbo île yorubaooo,Nitoripe,Ogun fulani to njawa la nronu si bi ase maasegun.Omoiya omo baba ni Awa Iran Yoruba ooo.Nitorinaa ki eyin agba alase yoruba adugbo Yan fi iberu Olorun yanju Oro naa finished.

  • @adeolajoshua371
    @adeolajoshua371 2 месяца назад +1

    Nobody is supporting the pastor, what he did was very wrong, they should not have taken law into their own hands

  • @carolinefowosire8188
    @carolinefowosire8188 2 месяца назад

    The pastor need to sentence to jail

    • @andersonomoba186
      @andersonomoba186 2 месяца назад

      What of those that kill Deborah what should happened to them?