Baba Ekiti mo ki yin Sir, E ku eto ko ni su yin koni re yin Loruko Jesu. Eku ise ilu oooo. Olorun yio mu wa de ile ileri LASE Edumare. Yoruba Nation ni kan soso lona abayo fun gbogbo wahala yi oooo. Yoruba Nation no going back 👍👍👍👍👍👍👍👍👍.
EKU ISE TAKUN -TAKUN BABA-EKITI, ADANIWAYE A WA PELU YIN ATI GBOGBO EYIN AJIJAGBARA ILE YORUBA PATA-PATA, ADUPE LOWO GBOGBO AWON TI WON PEJU-PESE SIBI IPADE TI WON TI SI-OKU-SARIA NI IPINLE EKITI ,AWA OMO YORUBA A KO FE OFIN SARIA RARA O, OMINIRA PATA-PATA KURO NIUN NAJIRIA NI AWA OMO YORUBA FE
Baba Ekiti mo ki yin Sir, E ku eto ko ni su yin koni re yin Loruko Jesu. Eku ise ilu oooo. Olorun yio mu wa de ile ileri LASE Edumare. Yoruba Nation ni kan soso lona abayo fun gbogbo wahala yi oooo. Yoruba Nation no going back
👍👍👍👍👍👍👍👍👍.
Baba Ekiti, mo ki yin o. Ayo ati alafia ni yio ma ba yin gbe o... Amin.Yoruba Nation, no going back.
EKU ISE TAKUNTAKUN SIR BABA EKITI ❤❤❤❤❤
Babe Ekiti proper we Yoruba Nation 💕 you more.
The words that Baba Ekiti said were said by CPT Traore. Be brave, never be afraid. Thank you, Baba Ekiti.
Baba Ekiti ose o fun igboun safefe.God bless you in Jesus name.
Amin ooo
We say No to Sharia law in Yoruba land 💪 much love sir 💕
Ese gan
Ashe Edumare
Ekuse takuntakun baba mi
Baba ekiti eku ise o eku eto
EKU ISE TAKUN -TAKUN BABA-EKITI, ADANIWAYE A WA PELU YIN ATI GBOGBO EYIN AJIJAGBARA ILE YORUBA PATA-PATA, ADUPE LOWO GBOGBO AWON TI WON PEJU-PESE SIBI IPADE TI WON TI SI-OKU-SARIA NI IPINLE EKITI ,AWA OMO YORUBA A KO FE OFIN SARIA RARA O, OMINIRA PATA-PATA KURO NIUN NAJIRIA NI AWA OMO YORUBA FE
Awon ojaja pa pirin je