Shettima, Face your wahala, leave Kemi badenoch alone-Atiku aide | Don't beg for me-Dele Farotimi

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 23 дек 2024

Комментарии • 213

  • @moradeyoalaba9406
    @moradeyoalaba9406 8 дней назад +2

    I heard about the Ooni of Ife on the News, I think two days ago.but what I did not knowing or understood is that if it was New or Old, but with the statement it's sounding as new clips of Buhari and Our Yoruba kings. It's a very big shame for Ooni to even go to Buhari with some kings and to alter that kinda of statement and so any appreciation to Baba Bubu with all atrocities that happened in Yoruba Lands. From Bokoharam, to Bandit, to Fulani's hensmen and so on even to every killing of Yoruba soldiers and attacks in Sunday Igboho's Oosa Omo Aladigun Adeniyi Adeyemo 's House and many more. Its shows Ooni Enitan Babatunde Adeyeye Ogunwusi has also swallowed his words and his lines of action in organising meetings with Obas,and Sunday Igboho's Oosa along with Gani Adamu called logun ofe,without no commitment of protecting our Yoruba Lands against the fulani's agenda to our races. Its has shown that The Yoruba leaders were less concerned about their's people's. Its so sad.They all knows but proved to be coward. And they don't even thinking of their owned Children futures that whatever they do today will become theirs reflections of tomorrow. ❤😂They needs to come out and tell Omo Yoruba what we happen after Baba Tinubu. Emi lokan sagas. It is not too late for them all the Yoruba Lands kings, Chief's, Elite's, Man and Women's to wake up and stopped thinking of themselves alone, but shows love to humanity, as the suffering is in higher levels to bearing and lots of life's being lost on daily basis, because Notting is working. Its only Nigeria you paid for almost everything without government intervention and yet not enjoying the services. E.g. Electricity, Roads but yet they we're spending more money's on the roads ,Net work wahala is also a reaps up systems ,They were building markets and yet the school's is in shambles. What is purpose of shop's and new marketing place's without Electricity providers and petrol high prices has also had more problems for Some businesses to functions. Which increases hardship in the whole country..This people's need to wake up from theirs slumber and do the needful. The Security control is a very big issue to deal with too.Gas too is high and yet when others countries in the word's were talking about the climate change, them will be there talking as if they understood what pollution is.The only ways to helped the Nigerian Citizens and is by let go of Nigeria it will also helps other's countries too. Thank you.and God Blessed..❤❤❤😂😂😂😂😂😂😂❤❤❤❤❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @antimol4593
    @antimol4593 8 дней назад +2

    I am more Yoruba than Nigerian. My "Yorubaness" is more than my "Nigerianess". God bless the Yoruba race. Yoruba Nation now. No going back.

  • @adeleyeabimbola1432
    @adeleyeabimbola1432 9 дней назад +1

    😂😂😂😂❤❤❤ O Karen jare omo ologo My dearest sister KEMI BADENOCK .LAGBARA OLODUNMARE LAIPE LAIJINA YORUBA NATION MAA DE ILE ILERI LASE EDUNMARE .

  • @oloriyeyeoge
    @oloriyeyeoge 9 дней назад +2

    Yoruba nation,all the Way❤

  • @antimol4593
    @antimol4593 8 дней назад +1

    I wait with trepidation every day to hear some wonderful good news from Nigeria. Alas! I am always disappointed. When you hear bad news and lies continually for too long they gradually become your truth. Now, I can see why many Nigerians unbelievably support and defend their oppressors who lie bold-facedly to them. The deception is unimaginable and out of this world terribly compounded with impunity and bravado.

  • @Stella-O
    @Stella-O 9 дней назад +1

    Amin o ogbeni Bobby ko ni sun eyin na

  • @AdunniAyoola-j6c
    @AdunniAyoola-j6c 9 дней назад +2

    Yoruba Nation no going back ooooooooo

  • @oloriyeyeoge
    @oloriyeyeoge 9 дней назад +1

    EJIKA NI SHOP❤❤😂😂❤

  • @samueloluwasegun
    @samueloluwasegun 9 дней назад +2

    Yoruba Nation No going back together we moved.

  • @martinadebowale3839
    @martinadebowale3839 9 дней назад +1

    KEMI we love ❤️ you the true Yorubas love you baje.

  • @MichaelAlake-b3l
    @MichaelAlake-b3l 8 дней назад +1

    Yoruba Nation no going back and no surrender.

  • @ToluhiToyin
    @ToluhiToyin 8 дней назад

    Ogbeni bubby ese mo dunpe sir fun ife ti eni si wa, olorun a ma ba yin se, mi o Mo bi Mo Se le dupe sugbo olorun yo ba mi sun yin ni esun ire Yoruba nation no going back.❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤

  • @atinukeodukoya355
    @atinukeodukoya355 9 дней назад +1

    Ogbeni bubby Wasiu Ayo fe marshal lo ko Orin ti a fi wile yen o

  • @funmilayoshode1526
    @funmilayoshode1526 9 дней назад

    ❤❤❤ Ogbeni Bobby mo ki yin ooo Éku ise o, Oluwa awa pelu yin. Continue your good job God bless you more. I always gbadun your iroyin, with all the ajasa you mixed to it. Wasiu ayinde K l the ultimate lo ko orin yèè ooo. From Yeye Oge Funmilayo. Dallas TX God bless America. Yoruba Nation no going back ❤❤❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️🙏Thank you so much ma'am

  • @moradeyoalaba9406
    @moradeyoalaba9406 9 дней назад +1

    Ogbeni Bobby, Good evening and thanks a lots for your efforts all the times to bring this News to International for Yoruba Nation. God Almighty will continue to be with you and your family as a whole. Amen In Jesus Mighty Name. Thank you and God Blessed. Gbogbo Orisirisi lapapo.❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤

    • @moradeyoalaba9406
      @moradeyoalaba9406 8 дней назад

      IBA SANAWOLE ATI GBOGBO IBA ORISIRISI LAPAPO. CHEASE Wasiu Ayinde Marshall lo ko orin a mu wole ti oni o.Thank You and God Blessed

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️Thank you too ma'am

  • @antimol4593
    @antimol4593 8 дней назад

    Ogbeni Bobby, thank you very much. I always enjoy your programs. I am from California. I love your command of the Yoruba language. E ba mi ki Aaya o.

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      Aaya ngbo sir. Thank you so so much ❤️🙏

  • @oloriyeyeoge
    @oloriyeyeoge 9 дней назад +1

    Tabi London tailor!😅😂😂

  • @elizabethoyeniya8827
    @elizabethoyeniya8827 9 дней назад

    Myself and my husband always got our fun on your global new. Ina tohun jo yi ni lo ifunra si oo. Yoruba nation is the way out oo. Kemi owo aye koni ka e o,❤❤❤❤❤❤from Texas.

  • @OluyemisiAbegunde
    @OluyemisiAbegunde 9 дней назад +1

    Baba Afe Babalola is only making Dele Farotimi and his book popular . Everybody is looking for the book to buy.Yorubas love Kemi Badenouck❤❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @hannahhunsu4553
    @hannahhunsu4553 9 дней назад

    Ogbeni Bobby oko awa arugbo mo ki eyin ati Aaya OLORUN yio bayin se gbogbo ise yin, Yoruba nation now now now ❤❤❤❤❤❤❤❤❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @kennyogunkoya3634
    @kennyogunkoya3634 9 дней назад +1

    Kemi Badenock Olorun amu e duro.Oni jabot loruko Jesus. Yoruba Nation no going back

  • @christinaogundiya4774
    @christinaogundiya4774 9 дней назад

    Oni su bu Kemi Oluwa a fun e se God will keep you there Amen Omo Okö niKemi Yoruba Nation no going back nitori pe Owo ti won ko je ni Nigeria ohun gun won Eku ise Boby ati Aya Good job inu mi dun fun Gbogbo ise ti e se Olorun a fun yin se happy weekend thanks

  • @Stella-O
    @Stella-O 9 дней назад +2

    Yoruba nation no going back

  • @AdetolaAina
    @AdetolaAina 8 дней назад

    Ogbeni Bobby, a Ku spade olomo ilu, a Ku ipamo Odun Ayo la ma fi se, e so fun awon to sewo si Kemi, Kemi mo ibiti o nlo ki won ma SE sewo si Kemi mo, e BA mi ki Aaya, o daaro ❤❤❤❤❤❤❤

  • @olabodea.jalloh8101
    @olabodea.jalloh8101 9 дней назад +1

    Yoruba nation no going to bank ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @Ololade-jf6ip
    @Ololade-jf6ip 8 дней назад

    Bobby eku ise takuku Olorun amabayin se, Wasiu ayinde k1 loko orinye, ❤❤❤❤❤❤❤❤🎉🎉🎉🎉🎉🎉

  • @elizabethoyeniya8827
    @elizabethoyeniya8827 9 дней назад

    Iba gbewondebe,ko ni buru fun gbogbo ni ikanni yi by the grace of God,gbogbo awon tohun fi ajulo gbe wa mora yi ma gba ere ise won ni agbara Olorun. ikokan ni omo owo ma un yo sonu, ikokan ni won ma ko ja si six feet. Eku ise jare❤❤❤❤.

  • @OlukayodeHamzat
    @OlukayodeHamzat 9 дней назад +1

    Oga Aya, e ku ero

  • @AdewunmiLawal-yz7pk
    @AdewunmiLawal-yz7pk 8 дней назад +1

    Ogbeni Bobby, Yoruba Nation will go back to the time of Awolowo,and will be like Malaysia or Singapore.If South West is not in Nigeria,it will be like the two above named countries.

  • @AbimbolaIlesanmi
    @AbimbolaIlesanmi 9 дней назад

    Iba gbewa de be,Eku ise o, Ayinde KWAM 1lo ko orin 'efun wa ni demokiresi',Eni to ba Fe somo ni Ayinde ko maa mura owo irinse orin lojo iwaju. I love gbogbo Ayinde o

  • @nurudeenmuritala1697
    @nurudeenmuritala1697 8 дней назад

    Ogbeni Bobby tiwa every where you go gbogbo ibi ni iba tinkle me and tinkle you tide rii o gao 😊😊

  • @carolinefowosire8188
    @carolinefowosire8188 9 дней назад +1

    Ogbeni Bobby yoruba nation no going back awon ti nbani gan aso to fa ya ejika ni shop, ni a npe tailor oni machine ni ejika

  • @taiyebakare4445
    @taiyebakare4445 9 дней назад

    Ogbeni Bobby, you wear too many hats, beautiful voice ❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      Thank you ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @orisoriola9808
    @orisoriola9808 9 дней назад

    Aaya e bami korin yi fun KEMI wen yin rewo bolomo ogun2ce weyin rewo,Olofo ni awon jegudujera asofin LAIJIRIA. Oriola Oris frm dallas tx

  • @yemiige9990
    @yemiige9990 9 дней назад

    Awon abiyamo yoo ti Kemi lehin o. Ko ni subu loruko Jesu. 🙏

  • @titilolaadeeko5507
    @titilolaadeeko5507 9 дней назад +1

    Omoluabi atata ni awon Obi Hushpopi. Owe Yoruba ni eni to ba jale lekan, to ba daran bori, aso ole lo da bora. Sugbon ki won maa gbadura ironupiwada fun. Yoruba gbayi, Yoruba Nation lawa nfe.

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 8 дней назад

    E kaaro ooooo, buroda mi Ogbeni Bobby. Happy sunday oooo❤❤❤❤❤, i can't do without listening to iroyin ayo from you❤❤❤❤. Daddy always telling me, mama Ogbeni Bobby😂😂😂😂😂, se a ni gbo iroyin, Ogbeni Bobby ni😂😂😂😂😂😂. You're too much, bro❤❤❤❤❤ and Aaya much love ❤❤❤❤❤❤❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️🕺🕺🕺🕺🕺🕺💯💯

  • @hannahhunsu4553
    @hannahhunsu4553 9 дней назад +1

    Cheese Cheese Cheese mushin 😂😂😂

  • @motolanimartins4744
    @motolanimartins4744 9 дней назад +1

    Ajọ̀mọ́ gbogbo awọn ojelu wonyi ni gbogbo nkan ti Wike nṣe..wọn jọ ma pin gbogbo awọn ilẹ ti wọn n'jà gbà kiri wonyi ni..Radarada rederede l'oma gbẹyin awọn ọ̀jẹ̀lu asiko yi Ooo🙏

  • @RichardOmokaramon
    @RichardOmokaramon 9 дней назад

    Ogbeni Bobby ibà ọta lenu wuye wuye ẹku eto oooooo.oda bipe awọn t'in sọrọ sí kemi fẹ gba epe ti orí wọn o ba bú ru ki wọn tọka ẹgbẹ kemi ti owa ní ipo agbara ní Naijiria aye wọn a la nọn ní ooo yoruba nation no going back God bless you all

  • @risikatadigun9477
    @risikatadigun9477 8 дней назад

    O’ Bobby, Oro Agba, Omo too Dara ti gbogbo Aayee, OluwaKemi Adura Iya ree , Ati tii gbogbo Abiyamo koni Kojaa ree, O sii nii Subuu Laelae Aameen, Kobewude, Iroo nii won npa Jaree, Ma loo Mooto, Ma loo Mooto Pin Pin, Much Love ❤❤❤ Salaam

  • @AdewunmiLawal-yz7pk
    @AdewunmiLawal-yz7pk 8 дней назад +1

    Ogbeni Bobby, the time of Babangida ,one dollar was 75k , but IMF made him to devalue naira and it became #3 to one dollar .😢 And before he left it was#12 to one dollar .

    • @92olamiArabMoney
      @92olamiArabMoney 8 дней назад

      😢🥺God take Tinubu give us back the great time 😂😂🤲🤲🤲😂

  • @EmmanuelOlofinnika-fl7pe
    @EmmanuelOlofinnika-fl7pe 9 дней назад

    Mo kii yin o, ogbeni Bobby ati Aaya. Ejika ni shop la n pe awon omo Ghana to ma n gbe machine ìrónso kiri nigba yen o. LA California 🇺🇸

  • @MotilolaKomolafe
    @MotilolaKomolafe 8 дней назад

    Ogbeni Bobby e ku ise oo. A ku odun oo. Ohun kan ni o daju pe ti Tinubu o ba le da Wike ati Afe duro Eniti o ju eda alaaye gbogbo a da won durooooo.Eniyankeniyan wonyi o ni si ni Yoruba Nation oooo.

  • @olapejuashaye2982
    @olapejuashaye2982 9 дней назад

    OGBENI BOBBY NIBITI ETI PARO, ORO INA NAIJIRIA FE SO MI DI ONIHOHO. NIGBATI NWO MU INA ORIBURUKU NWON DE, NI PLUG INU YARA MI BE GBINA, OPELOPE OLORUN NI KO JEKI ILE JONA. AWON TAILOR TO MA NGAN ASO NI NWON PE NI OBIOMA. FROM CHICAGO

  • @moreadeyemo1630
    @moreadeyemo1630 8 дней назад

    Eje ki a rora ma soro Kemi loju awon ika eniyan yi o. Ki Olodumare ba wa di Kemi ni Amure o. Amin/ Ashe.

  • @olapejuashaye2982
    @olapejuashaye2982 9 дней назад

    EKU ASALE O OGBENI BOBBY, EKU ISE OLOMO ILU O. K1 AYINDE WASIU OKO EMMANUELLA LO KO ORIN AKOWOLE NYEN O. EKU OTUTU YI O, AOKO ERE OKO DELE LORUKO JESU KRISTI. EBAMI KI AYA KOMA FARA SILE FUN OTUTU. FROM CHICAGO WITH LOVE❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤

  • @AdesolaOladeji-d8m
    @AdesolaOladeji-d8m 9 дней назад +1

    Aganrandi beni wasiu ayinde machaa

  • @ToluhiToyin
    @ToluhiToyin 8 дней назад

    Iya wa Odumosu ese mo dunpe gidi gan lowo yin ma, oke oke le o malo, eyin ati idile yin e ko ni ri ogun ofo emi gigu ni olorun ma fi fun yin ati eyin ati family yin, e ma ko ere oko wale e ko ni gbe saju❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤ you ma

  • @antimol4593
    @antimol4593 8 дней назад +1

    I love Kemi so much 100%. I could not believe she could claim her Yoruba heritage in such a lofty position in Britain. Bravo Kemi. You are perfectly OK. Don't identify with a sh*thole country. Nigeria was already a denigrated space by Shettima and his Boko Haram before Kemi was born.

  • @remmys1
    @remmys1 9 дней назад +1

    Ogbeni Bobby dele FAROTIMI already retired from those Nigerian criminals calling lawyer I bought more than dele FAROTIMI books and I still buy more am still looking for senior advocate of nuisance calling SAN to come conducted it God bless America Free Dele FAROTIMI

    • @faithdavies2681
      @faithdavies2681 9 дней назад

      DELE FAROTIMI IS NOT A CRIMINAL, LEAVE HIM ALONE. DO THE RIGHT THING TO STRAIGHTEN NIGERIA.

  • @motolanimartins4744
    @motolanimartins4744 9 дней назад

    Ẹ ku iṣẹ ọpọlọ Oooo...Ọlọrun a ma kún ẹyin ati àáyá lọwọ🙏.A ko mọ eyí ti a ma gbagbọ ninu ọrọ hushpuppy ati awọn obi rẹ̀.Ọ̀lọ̀rún l'oni ìdájọ ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  9 дней назад

      ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤🎉🎉🎉

  • @hannahhunsu4553
    @hannahhunsu4553 9 дней назад

    Alhaji Ayinde wasiu kwam 1 lo korin na 😂😂😂❤❤❤

  • @Ololade-jf6ip
    @Ololade-jf6ip 8 дней назад

    Bobby oko omoke,oko arugbo, babagbewa debe, Wasiu ayinde k1 loko orin ye, ❤❤❤❤❤❤❤❤🎉

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @adeberokehinde7844
    @adeberokehinde7844 8 дней назад +1

    Orile ede Yoruba, Yoruba nation

  • @sholaodumosu2705
    @sholaodumosu2705 8 дней назад

    A day late, but presenti o. Doing catch ups now ❤❤❤❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  7 дней назад

      Wow! You're the best 🤗🙏

  • @orisoriola9808
    @orisoriola9808 9 дней назад

    Iba tikutiku mo so fun yin wipe oro wike ko gba ojuboro. O si nwo pata ladugbo nigbati iya agbalagba yen ti ntu owo ile (land) yen jo.Oriola Oris frm dallas tx

  • @abiakinsemoyin7084
    @abiakinsemoyin7084 9 дней назад +1

    Oko mi Ogbeni Bobby, inu sese dun julo ni ale yi ni o. Mo lero wipe oti ko mi sile ni oo. Ati wipe mo busy lenu ojo meta yi ni ooo. Gbogbo e julo mo si ma ngbo iroyin re.

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      ❤️❤️❤️🤗🤗🤗

  • @AbimbolaIlesanmi
    @AbimbolaIlesanmi 9 дней назад

    Ogbeni Bobby, Ara awon ohun to ba Nigeria je niyen,eni toba ti loruko, ibaa bayeje, ko tun jogun omo omo Ninu oyun, won gbodo fowo boo mole ni, ohun ti Dele Farotimi so sinu iwe re sele ni ,ododo si ni pelu eri,se e wa rii pe Nigeria ko le latunse mo,Yoruba Nation ni kiakia

  • @ayodelejoseph602
    @ayodelejoseph602 9 дней назад

    Ejika ni shopu ni ooo . God bless you kemi badnoch

  • @oloriyeyeoge
    @oloriyeyeoge 9 дней назад +1

    Mo ti ready lati se alaga ijoko fun Yaya ni bi ti won ba ti n da ejo ewon fun!bt emi ko le se oniduro fun,bcos mo mô pe o ma try lati escape!A salo rau rau! 😢😅😂😂😂😂😂😂😂😂 Ara ko ni iwofa bi onigbowo, abaniyawo ni ara ma n ni😅Ara ko ni niwa o 🙏❤️❤️❤️

  • @AlakadaOpebiyi
    @AlakadaOpebiyi 9 дней назад

    Eyibmo boya otiilobaba tabii iya ee ekale sa Ogbeni Bobby Yoruba Nation Now Now Now Igboho Oosha Noni.

  • @atinukeodukoya355
    @atinukeodukoya355 9 дней назад +1

    Ogbeni bubby otito le so lori oro awon ti o nfe iranlowo ki oluwa ki o Samusi wa
    Agorondi N.A. ni awa Ike I now oo

  • @olapejuashaye2982
    @olapejuashaye2982 9 дней назад

    OGBENI BOBBY MO SESE GBA IWE DELE FAROTIMI LATI OWO AMAZON LONI. ENITI OBA FERA KI NWON ORDER FROM AMAZON. FROM CHICAGO

  • @JosephineAlawiye
    @JosephineAlawiye 9 дней назад

    GREETINGS BOBBY &,Aaya, OLUWA TITOFUNYIN .IROYIN NDUN MOMI.KEMI BADENOCH IS THE DAUGHTER OF SION,TINUBU LAALOJU KO WA SE (VECE PRESIDENT.SHETTIMA HATES THE TRUTH. (OMO YORUBA ATATA, OMO DADDY RE) From UK❤❤❤❤❤❤❤

  • @victoriaoloba7634
    @victoriaoloba7634 9 дней назад

    No man is an institution. God alone is an institution. Thank God Dele says he relys on God.

  • @motolanimartins4744
    @motolanimartins4744 9 дней назад

    Ẹ ma binu Ọgá Bobby..mi o ti mọ ila marun(5 lines) k'a ni Oooo..Okpebholo ni ki n'duro de ohun ni lati k'ẹsẹ lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ àgbá 🤣🤣🤣🤣🤣🤣

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣 àgbàlagbà kì fail ooo. Ke yà rántí se ohun Isoye 🤣🤣🤣🤣🤣. Bi mo se wa yi, ọpọlọ mi o mo ju owo lọ. Owo nikan ni moranti

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 9 дней назад

    Omaa se oo. Is a SADD case. He needs to pray and ask for forgiveness from both parents. I sincerely hope they are both alive upon his return. Aaaaameen.

  • @martinadebowale3839
    @martinadebowale3839 9 дней назад +1

    Madam KEMI ti gba citizen ship Yoruba Nation laiti apply.

    • @morounadebo6640
      @morounadebo6640 9 дней назад

      As how sá? Ọmọ bíbí ilẹ̀ Yorùbá tó tún kàwé ní ilẹ́ Yorùbá ní kékeré rẹ 🤗

  • @hannahhunsu4553
    @hannahhunsu4553 9 дней назад

    Ejika ni shobu,obioma ni awon ti won gbe machine si ejika 😂😂😂Yoruba nation now now now

  • @abiakinsemoyin7084
    @abiakinsemoyin7084 9 дней назад

    Ogbeni Bobby ku ale ooo, si ku dede iwoyi ooo. Aku ipalemo odun ti o nbo. Emi wa yio se pupo. Ni toto Kemi Badenouch ki i nse omo ale yoruba, eniti o ba pe soso yio ri soso, awon ode oponu dede ti won pe ara won ni ijoba shio.

  • @sholaodumosu2705
    @sholaodumosu2705 8 дней назад

    Wike wike wikeeeeee. Oga o. He needs to be stopped.

  • @MinaNoia
    @MinaNoia 8 дней назад

    Good afternoon sir how was your day ❤❤❤

  • @folarinadesanya2088
    @folarinadesanya2088 8 дней назад

    Nice show

  • @Stella-O
    @Stella-O 9 дней назад +2

    Kini e ro wipe e ma gbo lenu awon ojelu ti won pe ara won ni robby stamp wike awon alaini ronu ara galatia awon alatenuje awon eru fulani gbogbo

  • @dupebello3442
    @dupebello3442 9 дней назад

    K1 Ultimate Wasiu Ande

  • @oluwolebakare398
    @oluwolebakare398 9 дней назад

    Ogbeni Bobby, e kilo fun aaya ko rora ma yoju loju findo o! Nitori awon omo ale ajinigbe o! Ti won ba ji aaya gbe, ao ni ri iroyin gbo mo o!

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣 Aaya ti dira, omo ore ofe Olorun ni aaya

    • @oluwolebakare398
      @oluwolebakare398 8 дней назад

      @@ogbenibobby Eledumare seun o!

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 9 дней назад

    Bobby, Akpabio ati gbogbo awon administration Tinubu won ko gbadun, awon obirin meji ti won soro nikan ni won wulo ni arin won.

  • @kennyogunkoya3634
    @kennyogunkoya3634 9 дней назад

    Bobby ejika ni shop ni awon toma ngbe machine si ejika.

  • @abayomiorufai5426
    @abayomiorufai5426 9 дней назад

    Alhj Sikiru Shinde Barrister. Ni oooo, Mr. Ogbeni, Iba worldwide.

  • @MamaGodspower
    @MamaGodspower 9 дней назад

    Ogbeni Bobby, e ku ise orile ede Yoruba. Mo feki e mo pe president Tinubu wa leyin Yoruba nation, gegebi olori kole sojade laipari ise tonse, tobaso lakokoyi inkan ledaru

  • @MamaGodspower
    @MamaGodspower 9 дней назад

    Gbogbo owo to nya, Orileede Yoruba Loma jogun ise tinwon bafise

  • @tanimowookusaga4856
    @tanimowookusaga4856 9 дней назад

    Kemi Badenoch, s'ogi gun ki o ma ba gun igi aladin. Ota mbe n'ile, ota nbe l'ode. Sugbon Yoruba Nation no going back. Olodumare a duro ti o nitoripe Omo oko ni o.

  • @AlakadaOpebiyi
    @AlakadaOpebiyi 9 дней назад

    Baami Bobby Ekaabo Sori Eto gbogbo wa.

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  9 дней назад +1

      ❤❤❤❤❤❤🎉🎉🎉🎉🎉

  • @modurodeoluwa
    @modurodeoluwa 9 дней назад

    Ogbeni Bobby E ri pe opolun ni senator yi nso, ebi npa Ara ilu,Ile ti awon Eni eleni to jiya jise to fi ko Ile re,lo wa ye ki won mo wo,ki won mo wa pin Ile yen fun awon Ara won, gbogbo yin ni olorun ma mu

  • @rafiateyiowuawi8526
    @rafiateyiowuawi8526 9 дней назад

    Some of the lawyers and judges in Nigeria need to change their laws rules , and go reverse some of the old rules of laws. We’re not in the 19th Century. We’re in a civilized world now.

  • @moreadeyemo1630
    @moreadeyemo1630 9 дней назад

    Ogbeni Bobby. Alhaji Wasiu Ayinde lo ko orin yen o.

  • @tayoadedara9100
    @tayoadedara9100 8 дней назад

    O yẹ kí Àaya wá oniduro fún Yahaya. 😂😂😂😂😂

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      Ahhhh, eyin la fi se oniduro fún yayahh. E ko represent aaya 🤣🤣🤣🤣❤️❤️

    • @tayoadedara9100
      @tayoadedara9100 8 дней назад

      @ Ó tì o. Yahaya kò ṣeé trust!!!

  • @christinaogundiya4774
    @christinaogundiya4774 9 дней назад

    Baba Tinubu so pe Buhari ma fi Ori ede Yoruba Nation sere Ani Yoruba Nation no going back se e ri wipe iya nu ma sele lai pe Kemi Olorun ama fun e se ro ra o nitori pe Awon Nigeria o dara so ra e Kemi

  • @awujoolaolushola2476
    @awujoolaolushola2476 9 дней назад

    Shettima oko lo ri re o gban yin oko oko gban yin. Kemi badenoch Ayaa ki o fun oko oro to so si awon ojelu oloselu Nigeria. Eti po to e lo po si wa.😂😂😂😂

  • @Kehinde-h9x
    @Kehinde-h9x 9 дней назад

    Mo ro wipe Akpabio yi ti ma nmu ogogoro ki o to wa si ibi ise o jo re. AFI ki Olorun Oba gba wa lowo ijoba amu ni sin o. "Yoruba Nation ko si Bibo just wo ehin mo o. Forward ever laggard Oba Eledua.

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 9 дней назад

    Bobby, Arise oh Lord let the enemies be scarted,Psalms 68 v 1,God will arise for Dele ,Isaiah 54 v15 surely they shall gathered but they shall fall for his sake. Won ti poto.

  • @Stella-O
    @Stella-O 9 дней назад +1

    E se pupo fun eto olomo ilu wa yi o

  • @adeleyeabimbola1432
    @adeleyeabimbola1432 9 дней назад

    E ku ise takuntakun ati eto ti iroyin asale ti oni Ogbeni Bobby Oba oke a tubo maa gbee yin ro lagbara Alawura. Aaya nko se e ti bawa ra pata keresimesi fun un😂😂😂😂😂Odun ayo ni a maa se lase Edunmare.

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  8 дней назад

      Mi o ti ra ooo, mo ti fẹ lo ra sugbon aaya ni ki n ba ohun f'owo ti iya wa fún wa se ire fún alaini. aaya ti jẹ ki nwa emotional lataro ❤️❤️❤️

  • @yemiige9990
    @yemiige9990 9 дней назад

    Omg !!!!! Haa which leaders are this o ?
    This old woman ? N they want people to by force declear Nigeria citizen !!! Is this a country ?

  • @sholaodumosu2705
    @sholaodumosu2705 8 дней назад

    I got mine copy from Amazon.

  • @motolanimartins4744
    @motolanimartins4744 9 дней назад

    Ṣíṣe ṣise l'oma gbẹyin Wike ati Ọgá rẹ...kini kan ni o n'lu ilu fun Wike jo 💃💃..Ara ti wọn da nilu Eko ni wọn tun fẹ ṣé Abuja. Ọlọrun fẹ fí ojú aṣebi hàn ní..ilu (drum) wọn ṣetan ti o fẹ yá ni

  • @moradeyoalaba9406
    @moradeyoalaba9406 8 дней назад

    As for Seyi Makinde , I Understand that to develop in some area's of attraction will needs to obstruct or destroyed and designed some area's. But I also believe that humanity needs to takes in to consideration..as we all understood the importance of self made works in Nigeria and that government cannot provide for them either. I did not saying that they were rights in their's ways of protest and using abusive words. But the government shouldn't just gives short notice to demolitions of that placed considering they are all have Family. And again the government were supposed to create a new place for them and gave them enough times to move..it's not good to destroyed some life's to create new life for some people. Thank and God Blessed.
    As for Late Alafin of Oyo's wife's called Dami. She useless herself not the throne. And she proven been a useless person more for her to leave the Palace and become Portable 's Wife That is why parents should training their Children to be hardworking, Creativity and not just sent to school. I also appreciate Alafin for sending them to school too. When a ladies don't know how to make money, but very good at spending and enjoying is bound to be ridicule in that manners. I am only sorry for her Child,and I pray he or she wii not end up like her mother, and again she stand the chance of having change her ways.if she does good lucky to herself. Thank you and God Blessed. Yoruba Nation No Going Back Forward Ever.

  • @kikelolaolaitan4137
    @kikelolaolaitan4137 9 дней назад

    Wike fi iku sere, o wa ija awon iya aiye. Ore Obasanjo ni iya yi . Iya yi lo ni Rita Lori Hotel ni Surulere ni Eko. Awon iya aiye ni iya yi o.

  • @adeleyeabimbola1432
    @adeleyeabimbola1432 9 дней назад

    Olorun oba ngbo,n se lo ye ki won ran ayelala tabi aara si awon Oludari wonwon yii nibiti awon elemi esu ti nse alakoso orile ede location 419 ni orile ede ti wo. Fi nri iya