O n rugbo bo! Awon agba Yoruba ti s'oro l'ori iwode ti won fee fi tako Tinubu *Won sekilo nla

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 5 сен 2024
  • #viralvideo #yorubaelders #protest #insecurityinnigeria #entertainmentnewstoday #nigerianpolitician #yorubabroadcastingnetwork

Комментарии • 20

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami5257 Месяц назад +2

    Ninu gbogbo agba ile yoruba , baba Akintoye likan ni o duro ti gbogbo awa omo yoruba ooo.

  • @AbdulAziz-qr9pc
    @AbdulAziz-qr9pc Месяц назад +3

    Awon agba ole ile yoruba

  • @ogunrindeadebisi
    @ogunrindeadebisi Месяц назад +1

    SE Ebi hunpa OMO TINUBU BOLA HAMEED ATI AWON OMO TIYIN AGBA ILE YORUBA

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami5257 Месяц назад

    Awon agba yoruba ko feran awon omo yoruba rara , won ko ki fi ife han , afi etan likan , awon agbo igbo pele agba hausa fi ife han si awon omo ti won . sugbon awon agba yoruba rara o . ti ara won likan ni won mo .

  • @ogunrindeadebisi
    @ogunrindeadebisi Месяц назад

    Awon AGBA Omo Eni KISE yidibebere , Awon AGBA OLEEE .

    • @Olalekan-lz6td
      @Olalekan-lz6td Месяц назад

      Oloriburuku ni gbogbo yin and atiku is coming to put food in your table

    • @ogunrindeadebisi
      @ogunrindeadebisi Месяц назад

      @@Olalekan-lz6td Olalekan NIE TABI OSHI lekan ? Wanijere E AMIN ASE , Aja EMILOKAN, SE Baba E waninuwan ni , ? TABI wan ti promise E

    • @gboluwagaladiti3531
      @gboluwagaladiti3531 Месяц назад

      ​@@Olalekan-lz6tdYorubas are in serious and deadly problems, no leadership, both home and elsewhere. Tinubu is giving Yoruba people away and lively hood away to northerners and the Fulanis in order to keep his power, Fulanis or other ethnic groups in Nigeria are ready to exterminate the Yorubas in order to keep hold in the land.
      Yoruba people do not have any defence, no leadership and nothing to hold on to.
      The question to you is what can we do? If you are honest with me as a fellow Yoruba person.

  • @user-lo7jy9jf4h
    @user-lo7jy9jf4h Месяц назад

    Awon Agba osika agba kastonyan, agba to won to ile, agba to wa loja ti ori omo tuntun nwo. Agba ti ko ranti ojo ati sun, Agba to wa ni ile ti gbogbo ile di aworo. Awon agba ajegudu je ra Awon agba ojelu, Agba bamubamu ni won yo. Ileke oriburuku won len so mo idi ileke to ti ja mo yin ni idi, Se omo ADEYEMO Igboho Osha ko se idi bebere abi yoruba ko ni, se ileke ti tan ni ile oni ileke le se ri bebere idi so ileke mo????
    Agba ika niyin awon agba afe a je ma fe a yo.
    Olorun lugo o nwo ise Owo yin eyin agba rada rada onijekuje agba ya dede.

  • @user-lo7jy9jf4h
    @user-lo7jy9jf4h Месяц назад

    Ka ni baba mi wa ninu yin ni se ni ma ko ni baba

  • @user-bd3ih2en3o
    @user-bd3ih2en3o Месяц назад

    Kinni awon agbara dindinrin naa ri se si ipakupa ti fulani npa wa lati odun pipe,ti won le wa loko ,ti owa nmu iya,ebi ,iponju ba Iran wa lori île wa,

  • @josephmaito213
    @josephmaito213 Месяц назад

    Awon agba olori buruku, onijekuje dede.

  • @Onireason-to9te
    @Onireason-to9te Месяц назад

    Agba for where no retreat no surrender.... Ijekuje ti gbogbo yin tinje otito, the hardship is too much and you people can't advice emi lokan to open border for us to survive, the revolution no going back until you people understand and know the meaning of hunger.... Hunger kills than HIV and AIDS oo

  • @akeemokuneye1576
    @akeemokuneye1576 Месяц назад

    But tinubu can come outside to lead a protest against former president Jonathan, it's very obvious that we yorubas are the most bad tribes in the world.

  • @omooluabiyoruba104
    @omooluabiyoruba104 Месяц назад

    Awon agbalagbaa onijekuje Oloriburukus, , they never never said anything about the Fulanis that are killing Yorubas and our farmers…. Ko Ni dafun gbogbo yin….Awon Agba oofo

  • @ogunrindeadebisi
    @ogunrindeadebisi Месяц назад

    SE awon Grandpa Yi na RONU , ? SEBI TINUBU FUN WAN NI OWO , WAN EBI PAA GBOGBO ODO OOO , ETI FITIN BATI OMOLOMO JE OOO .

  • @Jimoh.Gaskia
    @Jimoh.Gaskia Месяц назад

    Awo.woni.awon.agba.onimo.tiaharawon.nikan.niwonmo.setulasi.ni.kajowa.ni.eyin.baba.jatijatiyi.sebi.eyin.leni.dukikhayi.