ỌRỌ YAHYAH BELLO YII, O YẸ K'OJU TI GBOGBO YIN O

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 3 окт 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Комментарии • 21

  • @fatalkehinderaheemat1513
    @fatalkehinderaheemat1513 3 месяца назад +1

    Hmmmm my father land my country o gbe enu tan

  • @Ojutv5923
    @Ojutv5923 3 месяца назад +2

    Yaya bello di abere

  • @adeyemiyusuff6458
    @adeyemiyusuff6458 3 месяца назад +5

    Mama Alaroye you are too much

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 3 месяца назад +1

    Awon to nse iwode worowo ni won ma ma le kiri ati Omoyele Sowore, awon Oloselu Ole akotileta arungun.

  • @LukmanAgbaje
    @LukmanAgbaje 3 месяца назад +2

    Hmmmmm Nigeria

  • @Oodua-ii
    @Oodua-ii 3 месяца назад +1

    Please give mama O so ju mi ko ro 👍.

  • @truthsquestions1532
    @truthsquestions1532 3 месяца назад +2

    Ole ni gbogbo won jor!

  • @LukmanBakare-iv2tm
    @LukmanBakare-iv2tm 3 месяца назад +1

    Hello gbogbo awon ti endaruko to je agbofinro niwon ti gba riba

  • @olamidiran2555
    @olamidiran2555 3 месяца назад +1

    Oloribuku ni gbogbo won. Siooor😅

  • @suzanneawoleke6488
    @suzanneawoleke6488 3 месяца назад +1

    Mama Alawiye truth said God bless you ma this so calling Governors know what they doing

  • @adekunlefodilullahmfa7700
    @adekunlefodilullahmfa7700 3 месяца назад +1

    Kii wan mo se loo .
    Olohun nbo Olohun kii se o eni ko kan oba gbogbo wan ni
    Lagbara .
    Olohun ju eda lo

  • @Ọmọọlọrunmoṣọpẹ7991
    @Ọmọọlọrunmoṣọpẹ7991 3 месяца назад +1

    Mama alaroye I’m sorry you didn’t tell us your name but you have a beautiful voice, ę ku isę o

  • @sabainahadetunmbi3661
    @sabainahadetunmbi3661 3 месяца назад +2

    Won KO ni itiju

  • @kemoblunsky3794
    @kemoblunsky3794 3 месяца назад +2

    Nigeria police don turn to Facebook bloggers police, awon ika, ole jatijati.

  • @MaryAlao-c5v
    @MaryAlao-c5v 3 месяца назад +1

    Gbogbo yin e sinmi ariwo e sinmi agbaja a ma se wahala jinna nitori Yahaya Bello oooooooo.
    Nigbati e nso nipa Yaya Bello se oun nikan ni ? Sebi gomina ni yaya ,kini e ti fe se ti baba re si Buhari gbogbo owo Liejeria to ko mi bi ejo ta lo soro nipa re ?
    Ti won ko ba ti mu Buhari nko ro wipe won le mu yaya bello nitoripe omo Buhari ni .
    E jeki won je eleyi ti won ba le je paapa julo mo fe ki won fo egungun Nigeria ki won yo mudunmudun re je .
    Gbogbo awon eniyan ni Liejeria lo ma je breakfast oju won ma bo .
    Sugbon mo mo daju pe egberun Samuel ko le sa mo Olorun lowo .

  • @QuddusOyinloye
    @QuddusOyinloye 3 месяца назад +1

    Yahaya Bello ti di imi Eegun. A ti Peru eyi ni lu to loba to si ni ijoye.

  • @foyekealawode4963
    @foyekealawode4963 3 месяца назад +2

    EFCC are body of police, they are the same thing, they know where he's.

  • @sussanahogunbo6681
    @sussanahogunbo6681 3 месяца назад +1

    IYA ALAROYE E KU OHUN EYI LO FOJU HAN PE OLORUN NIKAN LO LE BA WA TO NIGERIA A SESE FUN WA LOLA OLORUN

  • @derekajisefini2561
    @derekajisefini2561 3 месяца назад +3

    God will punish y’all