Araba tv,lojosi ti governor osoko so oro seyi makinde wipe ni ekiti wipe gomina oyo gbona koja bi a se nwo loju,osokomole ekiti gomina lo so bee nigba awuyewuye lbo naa
Iwo to nso oro Lori awon omo to ku,ki olorun fi orijin won, sugbon mo fe ki eyin ti e nka oku awon omo yen mo, Alhaji oriyomi ati olori Naomi, lorun e je alaiso ododo oro, se awon ni won te omo won pa mo won lowo ni,abi abosi ni e nse, olorun ri yin,
Araba ko si otito kan ni odo awon oloselu Nigeria rara, ni America omo school kan yin ibon pa omo school egbe re,gbogbo photo ati oruko awon omo yen ni government gbe Sita, fun gbogbo Ara America, ti Nigeria ni won o fi nkankan han wa,won kan so 35 children ni won nso, a fe mo awon omo yen, governor seyi Makinde, e gbe awon omo yen jade,
ARABA TV,WELL DONE
Araba tv,lojosi ti governor osoko so oro seyi makinde wipe ni ekiti wipe gomina oyo gbona koja bi a se nwo loju,osokomole ekiti gomina lo so bee nigba awuyewuye lbo naa
Olorun a ba won yanju gbogbo e
Baba wa Araba, e ku ise takuntakun. Yoruba nation now, no going back. Forward ever backward never.
Iwo to nso oro Lori awon omo to ku,ki olorun fi orijin won, sugbon mo fe ki eyin ti e nka oku awon omo yen mo, Alhaji oriyomi ati olori Naomi, lorun e je alaiso ododo oro, se awon ni won te omo won pa mo won lowo ni,abi abosi ni e nse, olorun ri yin,
Good news ❤❤❤❤❤
Araba ko si otito kan ni odo awon oloselu Nigeria rara, ni America omo school kan yin ibon pa omo school egbe re,gbogbo photo ati oruko awon omo yen ni government gbe Sita, fun gbogbo Ara America, ti Nigeria ni won o fi nkankan han wa,won kan so 35 children ni won nso, a fe mo awon omo yen, governor seyi Makinde, e gbe awon omo yen jade,
Ori awon agba yen gbale ni. Those children who lost their lives are less human, abi?