@@gbengameyun3393 the fastforward to the time when he was elected but he was not even the authentic candidate picked then before he was coronated 2008...he was allow because he born when his father was on war expedition and the last wife produced him a baby called his father name the boy olatimi o ba gbe wọ sa"shorten to Laminisa"
OBA Yoruba akotileta eda. Awon lon nfawa seyin. Owo niwon fi njoba. Konidara fun won. Awon lontawa fun fulani. Were logboju ninu awon OBA wa. Yoruba emura le lati yonju awon Oba oponu ile Yoruba. Ojaja lo si ile awusa lon dobale fun Emir. Ojaja, the first nlo dobale fun Emir ni ile Hausa. Emurale lati gbe Ade kuro lori awon omoale Yoruba.
Sebi a so fun gbogbo yin pe kosi Oba mo. Lati 1963 ni Oba Obinrin ilu Oyinbo ti gba agbara lowo won. Ilu ti Oba bawa, ko le si president. Won ko fi won se thugs ni ile Yoruba ni. Ikan ti ase sope ki a pada sile niye. Ikan ti ohun bo, oju Ikan ti Emi gbogbo yin ma gbe lo.
Eyin eyan yi pa pa self. Ile ti gbogbo awon omo yoruba nso oyinbo bi wipe, so oyinbo yen ma gbe ounje si ori table fun won. Ile ti ati tun se, so ki'n se wipe mi o fe yoruba ka da duro, but, awon agba ano so wipe Ise Ile Lo Ma Ba Wa De Ita....So, e je ka tun se ka to pada si inu ile no.
Oba Ede ko mo iyi are re.Emia ilorin to je pe o jale ile baba re . Oju gbamiti fun Iwo oba Ede. O tun niyi mo laarin ile Yoruba mo. Oponu ayirada. Oye ki awon Omo re ba baba won soro .
@@OmoIrunmole29you be mumu of highest order you are not even in your right senses you are saying SE oti da fun Iwo you are cursing a glorious king someone that even Ooni of ife respect him a lot
Asiri won tin tu ni. Sebi won ma se bi enipe won ju gbogbo wa lo ni. Olohun Oba tin mon mu won lo wa je ki awon msuslumi omo ilu won ma gboran si won lenu mon.
@andersonomoba186 All muslim kings in yoruba land must be withdrawn only indigenous Kingd who belive in the tradition must be installed as kings in youruba land
E ku ise takuntakun ,ti e bati riwon e maa side abenu fun won e maa be Ile Ile lowe sii won ti Ara ba ni won fu rawon ni won a fi IPO sile odua a gbe wa❤❤
Timi kunle fun emir of ilorin Oba ile yoruba ti di gbantueyo, bi won se nkuru ni won nga ni abuja ati daura Ti o ba ya yin nile yoruba, e jawo kuro ni apon ti ko yo, e gbe omi ila kana 🔥 Obaship is longer relevant; e pada ni be 🤓
Tani-Olorun, may Eledumare bless you. Ojaja and some other prominent traditional rulers love attending social events way too much. There was one Ojaja attended and aimed to shake the dancing governor of Osun State, Adeleke's hand, Adeleke snubbed him momentarily. Though they were later seen together. However, that moment Adeleke snubbed him was painful.😒😒😒
Tori ki won le ta ile yoruba fun awon fulani, ni gbogbo awon oba yi kose fowo si yoruba nation, awon oba obaye je, gbogbo awon oba ile yoruba ti gbabode fun ile yoruba, omoalade edide eji emasun
Tani olorun ekuisetakuntakun we yorubas all over the world love you
Olori buruku ni Emir Iwo ati awon Oba Alade toun foribale fun Emir.
Ojukokoro lo ba awon oba ile yoruba ja. Awon adoju ti ni oba
It is so ridiculous that our Yoruba kings have turned themselves to slaves in front of fulanis.
Thank you, Tani Olohun
Omo! It's so painful
Oba Ẹdẹ ti b'ẹdẹ jẹ patapata!
O ga ooo😮you are blessed prof Tani Olorun,Oba sorawon deru Emir
Yoruba nation no going back
Sheeeehu😂sheeeehu😂sheeeehu. All in the name of religion. Awon ode. 😂😂😂
Oponu oba to un dobale fun Fulani ajeji daran daran .Oba olooju kokoro .
Where did you see him prostrate
Oruko oba yen lo nro kii se ebi oba o. Muniru ni oruko oba yen.
@@ditty6828 e gba dun rara
Timi ki i se ojulowo OBA
Oloriburuku Ni Oba Ede!😢
@@gbengameyun3393 the fastforward to the time when he was elected but he was not even the authentic candidate picked then before he was coronated 2008...he was allow because he born when his father was on war expedition and the last wife produced him a baby called his father name the boy olatimi o ba gbe wọ sa"shorten to Laminisa"
Oloriburuku Oba
I was surprised when I saw video of timi ede kneeling down for emir Ilorin, I was really pissed
OBA Yoruba akotileta eda. Awon lon nfawa seyin. Owo niwon fi njoba. Konidara fun won. Awon lontawa fun fulani. Were logboju ninu awon OBA wa. Yoruba emura le lati yonju awon Oba oponu ile Yoruba. Ojaja lo si ile awusa lon dobale fun Emir. Ojaja, the first nlo dobale fun Emir ni ile Hausa. Emurale lati gbe Ade kuro lori awon omoale Yoruba.
TANI OLOHUN
OLOHUN BLESS YOU
Ori Ade won ti sun ita, gbogbo won tidi Oba bornvita🤪🤣🤣
Oloriburuku oba ni ede yen oma rare ku ni lase eledumare 😢😢
That's why i love my ikale people
Sebi a so fun gbogbo yin pe kosi Oba mo. Lati 1963 ni Oba Obinrin ilu Oyinbo ti gba agbara lowo won. Ilu ti Oba bawa, ko le si president. Won ko fi won se thugs ni ile Yoruba ni. Ikan ti ase sope ki a pada sile niye. Ikan ti ohun bo, oju Ikan ti Emi gbogbo yin ma gbe lo.
Eyin eyan yi pa pa self. Ile ti gbogbo awon omo yoruba nso oyinbo bi wipe, so oyinbo yen ma gbe ounje si ori table fun won.
Ile ti ati tun se, so ki'n se wipe mi o fe yoruba ka da duro, but, awon agba ano so wipe Ise Ile Lo Ma Ba Wa De Ita....So, e je ka tun se ka to pada si inu ile no.
Timi of Ede has gone astray.
Weldone brother mi Taniolohun
Well said brother mi
Won ti GBA owo
Oba adeyeye ogunwusi ooni ife needs to learn lots of things about that post Holder as ooni ife
Oloriburuku ni awon oba ile yoruba yi nigbati o je pe alabodeni won awon oponu
Nkan tise wa nile Yoruba oo
Gidigban ni kise kekere rara
Thank you Prof. Tani Olohun (PhD)
Love you brother ❤❤❤❤❤❤❤❤❤
Oba Ede ko mo iyi are re.Emia ilorin to je pe o jale ile baba re . Oju gbamiti fun Iwo oba Ede. O tun niyi mo laarin ile Yoruba mo. Oponu ayirada. Oye ki awon Omo re ba baba won soro .
He did right thing, long life to our Emir Ilorin,long life to Oba Ede
Mad !
Koni da fun emir
@@OmoIrunmole29you be mumu of highest order you are not even in your right senses you are saying SE oti da fun Iwo you are cursing a glorious king someone that even Ooni of ife respect him a lot
Many of them are mumus even Ooni of ife respect the Emir a lots
Ejowo o ye ki won yo awon fidi e oba yi kuro lori ipere. Awon yi o kin se oba gidi ni ile Yoruba o.
Oju gbamiti fun timi
Honestly most of those Yoruba king don't know the wot of the stool
Awon oba were. ati paapa omo ale ni gbogbo won patapata from A~Z
Oba of Beni Edo State will never bow down to anybody in Nigeria.
@johnlucky, Yoruba are focused on our own issues. We are not interested in any other traditional leaders outside Yorubaland.
EMIR OF ILORIN OLE 4 1 9 MABULLA FULANI OLE EMIR
Awon oloriburuku baba ofo
Ara won ni won n dojuti kiise ile Yoruba se oba ede komo pe ori ade loun gbe gbole niwaju oriade kan yen , se emir lo fi joba ni
That's how you these ppl are not Oba. Won ko fi di e lasan ni.
All Yoruba oba should go to Benin for training
I swear
GBOGBO awon oba teyin n wo yen kan nso Yoruba lenu ni eje won kii se eje Yoruba boseri nu
Asiri won tin tu ni. Sebi won ma se bi enipe won ju gbogbo wa lo ni. Olohun Oba tin mon mu won lo wa je ki awon msuslumi omo ilu won ma gboran si won lenu mon.
Olorun dakun gbawa kale ninu ajaga ti Ile Yoruba wa
Wa yagbe sara
You need to understand that muslim install all these modern kings in order to achieve the destabilsation of Yorùbá tribe and culture.
Yes
This is true, may God deliver yoruba
Dey play you are decieving yourself
@andersonomoba186 All muslim kings in yoruba land must be withdrawn only indigenous Kingd who belive in the tradition must be installed as kings in youruba land
That was a sad day in yoruba history.
Sad day for omo ede,awon omo eranko
haaa ewoooo
Me self no get respect for the king's again......
Don't respect Muslims kings, they deserve no respect. Omo eru ni awon oba musulumi
Oye ki won gba ade lori oba yi ni awon oba ti won ba ile yoruba je ni yen alabode ni
How many Fulani Emir have come to prostrate for our kings in Yoruba land. Its sad to see kings from Osun state misbehaving like this.
E ku ise takuntakun ,ti e bati riwon e maa side abenu fun won e maa be Ile Ile lowe sii won ti Ara ba ni won fu rawon ni won a fi IPO sile odua a gbe wa❤❤
Timi of Ede! This is highly shameful. No wonder Baba Obasanjo was rude to them.
Stand up, sit down, knee down
Oye ki iru Oba be lo sigba ni 😊
I agree with you Talolorun, wipe oba Ooni lese thesame thing
Oba doable ki balẹ
Timi no get level
Timi kunle fun emir of ilorin
Oba ile yoruba ti di gbantueyo, bi won se nkuru ni won nga ni abuja ati daura
Ti o ba ya yin nile yoruba, e jawo kuro ni apon ti ko yo, e gbe omi ila kana 🔥
Obaship is longer relevant; e pada ni be 🤓
And If this Oba come to Ife this is how they will stand like this greeting Ooni of ife
Idojuti nla ni Eleyi ooo
Ki Ọba yẹn lọ se bi Okunrin ooo!!! Idojuti fun iran yoruba gbaa ni Timi Ẹdẹ se o. Hunnnn!!!
Timi Ede is among Acadip group, Islam has made him useless my brother. He used to go to Meca with Adepoju.
😂😂
Oh I see
No wonder
Abajo
Ekun ise opolo brother mi
Timi Agbale omo Apon oroko leti ode😢, .....o kpakasor.😢😢😢
Ekuse takuntakun ooo
Olorun atubo maranyin
lowo ooo
Opolopo awon Oba wa
lotiya dindinrin nitori owo Yoruba Nation Now
Now NO GOING BACK
Awon oba ti o ye ki won padanu
Lesekese, oloribuku ni Oba EDE yi
Good evening sir
Ibo la ti ti awon alabode Oba wonyi hahaha.
I trust my Oba. The Orangun ile Ila would never do such.
Oponu ma ni rashidi..
To ba ti fa IGBO eee tan.
Isokuso lo ma n so ..
Nítorí owó ni gbogbo àwọn ọba ìyà yí ṣe ńṣe iranu kaakiri.
Good job sir
They supposed to dethrone the king straight away
This is shameful.
Timi ede n dobale fun Kolapo.
Awon oba alatenuje.
Oba yeye ni Oba Ede. They should depose the Timi of Ede immediately.
Exactly, they should make him a scapegoat
Tani-Olorun, may Eledumare bless you. Ojaja and some other prominent traditional rulers love attending social events way too much. There was one Ojaja attended and aimed to shake the dancing governor of Osun State, Adeleke's hand, Adeleke snubbed him momentarily. Though they were later seen together. However, that moment Adeleke snubbed him was painful.😒😒😒
Haaaaa ayemi ooooo. Timi of Ede e si doju ti awa omo Yoruba patapata.
Timi dobale fun omo Ale Emir Ilorin
Shame on you.
OBA RASHIDI ELETEKETE ELETE JONPA OMUGBO OPONU.
Kilo nse eyin oba wonyii na.
MO si respect OBA EDE but eleyi kudie kato rara, instead ko ju IRUKERE si,in show emir him too is a king like emir
After they will say aafa kii dobale.
Ki Ori Ade naa fo Ori oba alaigboran ko fo tutuu
Emir = Baale, sultan = Oba
Any Oba that comes to ife if he no fit Dobale kiwon ma wa si ife oo
Won ti lo sibi ti won ti pase fun awon oba Yoruba pe ki won mase lo si party mo abuku nla ni ki Oba Yoruba maa dobale niwaju oba fulani
Ori osi lori Timi Agbale Ede.
Tani o lorun you are the best
But 😂am 😂
Oni
Onigele
Tooto leso oba alade ki foribale fenikan ayafi eledumare
😂 oni ife gan ma dobale ki emir Ilorin
Moro wipe olori buruku ni oba iluyin ti ooni obaadobale Fi agidi teloriba fun emir eyin ogede Omo ale wonyi
Tori ki won le ta ile yoruba fun awon fulani, ni gbogbo awon oba yi kose fowo si yoruba nation, awon oba obaye je, gbogbo awon oba ile yoruba ti gbabode fun ile yoruba, omoalade edide eji emasun
Oba onijekuje
Tani olohun efi awon oloriburuku yi sile nigba ti o baya olodumare yio jewo ara re...
Oba were ton fo ri Ade dobale fun Eru.
Yoruba has lost it all😭😭😭😭😭😭😭😭😭😭😭😭
Assuming there's a secret meeting to get Ilorin back these kinds of kings will never support. Akukujoye o san ju enu mi o kalu.
Ơba were wo ni yẹn, alalẹ Yoruba ma bi o
Oba eleribu
Se awon baba wa ti won ni kaka ka dobale fun Fulani, ka kuku roju ku. Se won o Mo ohun ti won ri ni. Awon oba yi ti ba asa Yoruba je .
ama gbo gbo ogu ati agbara ti ani ni ile yoruba awan baba wa ti baje ise ogun ati ogu agbra ni wan fi da ile yoruba ama awan baba wa ti baje ooo
You are right Yoruba King doors not have respect any more
Thesame Timi Ede will not kneel down before Ooni o! Sungbon toripe oba fe je maalu, lose ndobale fun maalu
This is actually very painful to watch 🙁
AWON OBA ILE YORUBA OLOSELU LO FI WON JOBA
Odidi oba timi ede ede mopo arogun timi omo ogunle asote
Oba ilu wa idobale ni baba Tobi maa nki