ÎṢẸ́ KI I PA NI: EGBOOGI OLORO TI ỌMỌKUNRIN YII MU LAMUJU TI ṢEKU PA A

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 1 июл 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
  • РазвлеченияРазвлечения

Комментарии • 13

  • @olajideoluwayomi6529
    @olajideoluwayomi6529 2 дня назад +1

    Ẹyin ọdọmọde ẹ dẹ́kun Ògùn olóró ni mímú, ki ẹ ma ba ku ikú àìtó jọ

  • @temidayoadesokan9955
    @temidayoadesokan9955 2 дня назад

    O ma se o , o ye Olorun . Ki Olorun fi oriji

  • @AdekunleZainab-yt7tk
    @AdekunleZainab-yt7tk 2 дня назад

    Hummn egbe buburu ni nba iwa rere je 😎

  • @giveway...6838
    @giveway...6838 2 дня назад

    Awon Obi ! Ma mi isimi dada bayi

  • @oluwaseunadebowale3504
    @oluwaseunadebowale3504 2 дня назад

    Omase o... Ki olorun sanu awon odo WA ni orile ede naijiria
    Isowo ti awon odo SE nmu egbogi oloro ti poju

  • @LawalKazeem-dd5hj
    @LawalKazeem-dd5hj 2 дня назад

    Eni awi fun oba jekogbo, hmmmmm oga o, won kiun gboroo

  • @talithakoum6576
    @talithakoum6576 2 дня назад +1

    Ewe ti ewure mo je lo ma pa. Oloriburuku omo.

    • @KayodeVincent-hp4nk
      @KayodeVincent-hp4nk 2 дня назад

      Is the curse necessary 😢

    • @talithakoum6576
      @talithakoum6576 День назад

      @@KayodeVincent-hp4nk He already cursed himself. The moment he tasted it and he continued to use it until the drugs saw his end. Is either you kill the drug or the drug kill the you. One has to occur. Who put it in his mouth, anyway?

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 2 дня назад

    Omase oo

  • @user-fp1pz2gg8x
    @user-fp1pz2gg8x 2 дня назад +1

    O MA SE OOO RIP🙏

  • @adiokem
    @adiokem 2 дня назад

    One spanner lost😂

  • @lukmonolamilekan8616
    @lukmonolamilekan8616 2 дня назад

    Nkan tomo jee loyo werey you will be blaming yourself anywhere you're now 😅