Salute!!! Eyin olopa Nigeria 🇳🇬, Oluwa Olorun Olodumare Jehovah yio tubo ro yin l'agbara o. Enirere o sin ni tan l'ori ile aiye wa yi o. Mo ki yin pe, e ku ise takuntakun, e sin ku igbiyanju. Oluwa Olorun Olodumare Jehovah yio duro ti eyin ati ile onikaluku yin o. Nigeria 🇳🇬 ko ni baje o, o baje ti.
This one is not a babalawo. Genuine Babalawo are under oath never to use their knowledge for evil. Evil people should not be using their greed and evil doing to give this sacred profession a bad name. Enough of this. Evil people.
@@ibaileibaomo7660 Very scary stuff out there and at times I think the government has turned a blind eye to these happenings. This can't be allowed to go on unchecked.
Olopa yen fi ogbon mun arakunrin yen ni, won tigbo wipe oma nfi eyan se Ogun owo, eran ti olopa yen fun kokiise eran eyan. Sugbon lati ni idaniloju wipe afi ni sowo ni
Hmmmnn hmmmnn nwon ti gbo nipa re tele pe ise buruku lo ma nse, o pe oya Oba mi oke yio tu asiri won, e jawo ninu ise buruku. Alaroye e ku ise ribiribi ati dada ti e nse, Oba oke yio mati yin lehin Amin.
@ Eyin Ti E Je Olopa Otito, E Ku Ise Takuntakun... Imoran Mi Ni Wipe, Bi E Ba Fe Mo Pupo Asiri Awon Odaju Wonyi, E Ma Se Iwadi Nipa Awon Dukia Nlanla To Wa KaKiri. Ona Ti Won Gba Ni? Ati Bebelo.. Isale Oro Legbin... Isale Agbara Si Legbin..
Hmmmm A ni see Loruko jesu Ile ise olopa ati tawon alaroye koni jona o Amin Hmmmm Teeyan bade ile iwosan ile ejo ogba ewon eeyan yio dupe o Hmmmm Omo tooba ya garawa ewon lo nlo
Suliamon 😂😂😂 Babaláwo Ṣùgbọ́n Ògún ni ó sábà ń bọ Kò sọ pé òun dífá ooo. Ọlọ́pàá náà dà! Ọlọ́run á mú gbogbo ẹ̀yin ẹni ibi tí ó ń da ìlú yìí láàmú pátá
Salute!!! Eyin olopa Nigeria 🇳🇬, Oluwa Olorun Olodumare Jehovah yio tubo ro yin l'agbara o. Enirere o sin ni tan l'ori ile aiye wa yi o. Mo ki yin pe, e ku ise takuntakun, e sin ku igbiyanju. Oluwa Olorun Olodumare Jehovah yio duro ti eyin ati ile onikaluku yin o. Nigeria 🇳🇬 ko ni baje o, o baje ti.
Oluwooo ati babalawooo😁
These are the reasons are ancestors embraced MOMODU and JESU
Alaroye eku ise o❤
The fact that the first guy stubborn 😂
Eyin Olori buruku babalawo.... Eewon ni gbogbo nyin ma ku si... Lagbara Olorun Oba Jehofa 🙇 AmiiiiiiN
Ọba Jehovah irọ wò? K'a dupẹ lọwọ awọn ọlọpa fún iṣẹ ribiribi ti wọn nṣe. Jehovah yín to nworan ti gbogbo nkan nbajẹ láti àìmọye ọdun.
Eleribu ni won
Allah Akbar 😢
Elofeeyin Awon odaran Yi tiagba ... Epawon Awon apayan wonyi sir
Awon oloriburuku imolile musumi ton je babalawo sodik lawal emi o ri babalawo ton je oruko esin ajeji sodik lawal
No mind the confused idiots jare. True babalawo doesn't do money ritual. All these lazy bums calling themselves emergency babalawos
Lol, make sure you move away from your village you will see a lot of things….
There alot of babalawo is Christian names
This guy get confident kilode 😅
He's ogboju apaniyan.
This guy is a correct criminal
This one is not a babalawo. Genuine Babalawo are under oath never to use their knowledge for evil. Evil people should not be using their greed and evil doing to give this sacred profession a bad name. Enough of this. Evil people.
O ga ooo
Awon were dede,eni tio ba ti fine E ma Sa fun won,
Nigeria ti so awon people yi di odaju patapata, kinni eleyi bayi tori oloun, haaa...
This is madness in full bloom. How did we get to this point? What the hell is going on in Nigeria?
Is it Nigeria or just that the people are lazy and wicked.
@@ibaileibaomo7660 Very scary stuff out there and at times I think the government has turned a blind eye to these happenings. This can't be allowed to go on unchecked.
Olopa yen fi ogbon mun arakunrin yen ni, won tigbo wipe oma nfi eyan se Ogun owo, eran ti olopa yen fun kokiise eran eyan. Sugbon lati ni idaniloju wipe afi ni sowo ni
Hmmmnn hmmmnn nwon ti gbo nipa re tele pe ise buruku lo ma nse, o pe oya Oba mi oke yio tu asiri won, e jawo ninu ise buruku.
Alaroye e ku ise ribiribi ati dada ti e nse, Oba oke yio mati yin lehin Amin.
@ Eyin Ti E Je Olopa Otito, E Ku Ise Takuntakun... Imoran Mi Ni Wipe, Bi E Ba Fe Mo Pupo Asiri Awon Odaju Wonyi, E Ma Se Iwadi Nipa Awon Dukia Nlanla To Wa KaKiri. Ona Ti Won Gba Ni? Ati Bebelo.. Isale Oro Legbin... Isale Agbara Si Legbin..
Alaroye ekuise ilu ....
Eni to o ye ki won ti naa daku
Oloriburuku
E pa gbogbo won danu koda kiwon wa Larin awon Eniyan ninu ilu
❤❤❤
Eyin olopaa ilu Ondo state, eku ise nla o...... Se eri olopaa towards mi ilu Abuja ye e lo mu sir....
Why people are wicked
THIS JORNALIST ARE UNPROFESSIONAL SEE HOW THEY ARE ASKING TOO MANY QUESTIONS AT A TIME. THEY NEED TO BE TRAINED. GHORSHEEE 😅
They all do it. Even in abroad press conferences, they all shout out questions at the same time.
This is serious!
Oloriburuku ni baba yi.
Odaran ponbele ni okunrin yi. E mu u daadaa.
E o ni Bo n be
Hmmmm
A ni see
Loruko jesu
Ile ise olopa ati tawon alaroye koni jona o
Amin
Hmmmm
Teeyan bade ile iwosan ile ejo ogba ewon eeyan yio dupe o
Hmmmm
Omo tooba ya garawa ewon lo nlo
Ema pa won danu
Oniro buruku ni okunrin babalawo yi,apaniyan ni. Bawo ni oku eniyan se lo duro sinu igbo de lati ge Ori re? O maa jewo ti won ba mun daadaa.
Eku ise eyin olopa
Edakun tori.olorun kebawa sofun.awon.olori wakiwon.mapa awonika odaju boya wonbadinku.kilode temi.eyan ojoawon.eyanyi loju.atieyitope rareni.babalawo.atawon.tonta eran.araeyan fun kijoba.mapawon.ibadara ju.enibati payan.kanpa onitohun na.oburu sebi.first.Lady nasorona.nijosi atajinigbe atapayaninkankanna.niwon idajo kanna.loyewon.kiwonpa.wonati dinku.eri poloribu.niwon monsitun.lenu oro.lagbara olorun.wonnibo.nbe
This babalawo have be killing people for long such a wicked world
OSi nparo
Alaroye ekun ise takuntakun oo
6:25.. what kind of stupid statement was that? ANI AYO LATI SO FUN YIN WIPE, ISELE NIKAN KO LO SELE.. How was that suppose to be AYO (Joy or Happy)
Sodiq lawal Muslim ni e so that alfa is your name
Opoun to you now all male muslim is Alfa abi
Why turning his face away? Show his face let his family be ashamed.
Suliamon 😂😂😂
Babaláwo
Ṣùgbọ́n Ògún ni ó sábà ń bọ
Kò sọ pé òun dífá ooo.
Ọlọ́pàá náà dà!
Ọlọ́run á mú gbogbo ẹ̀yin ẹni ibi tí ó ń da ìlú yìí láàmú pátá
Harding criminals
Oniro buruku ni okunrin babalawo yi,apaniyan ni. Bawo ni oku eniyan se lo duro sinu igbo de lati ge Ori re? O maa jewo ti won ba mun daadaa.