Ogbeni Bobby, mo ngbadun yin gbogbo igba , jokes apart, I mean it. Baale mi na , a jo ngbadun yin ni ooo, 😂😂😂. He always tell me, your paddy paddy, Ogbeni Bobby, he’s too much ooo👌, good 👍🏾🙌
Ogbeni Bobby I always enjoy your show,because of the alubosa orin that you use to put and ur real Yoruba language with your Oyo tone.May the good Lord gives us our Yoruba Nation in Jesus mighty name! GBU!
Happy Sunday sir, Ogbeni Bobby. Ekuse takutaku, Oluwa Olodumare aranwalowo o amin Ase Edumare. At this point of no return no resteat no surrender no going back. Yoruba Nation now now now. May God almighty help us. Ase Edumare. Our Represative is Prof Akintoye Adebanji and Chief Sunday Adeyemo Igboho Olodumare. Yoruba Nation la fe. I salute all Agitators and World Medias members also Original people of Yoruba Land. Yoruba Nation now now now. God bless all.
Won n fi oruko Jesu kirun,se o wa ya yin lenu ni?boya le ti gbo arakunrin ti oruko re n je IFAKALELUYA!Ko si ohun ti ko le sele! Afi ki Olorun saanu gbogbo wa o!Aàmin❤❤❤
Iroyin Boorin kee, Ko Lee Boorin laelae, Iroyin Idunnu nii, lati Odo Oko Arugbo ti Olorun fi ran, Idunnu koni fi ile O’ Bobby sile ati gbogbo waa Aameen .
@ogbenibobby Olo mi jowo o je kajo ma gbadun…… Ebenezer Obey-in the late sixties I was in HSC(upper 6) that’s like 6 decades ago!my lil niece,born in 1964 is now 60 years old! how time flies!may God give us long life,in good health and happiness 🙏😇❤❤❤❤❤❤❤
Ogbeni Bobby, to God, you and Aaya are my Bible, if I have not watch or listen to your program, I don't often get myself, God bless, keep, guide, and protect you and Aaya. Those officers using hands to pick or pack evidence lack critical thinking in security.
The "Ecumenism Movement" through "Chrislam"is in full swing😂. Only in Nigeria could such blending occur. It appears that they are able to serve two different masters harmoniously. 🤔
Thanks bro 😎. Listen to the end of yesternight news, much appreciated 👊🏾👏🏽🙌. E ba wa ki ile ooo, ipade wa bi oyin ooo, o di asale, ❤. Enjoy the day further ✌️.
E seun gaan lopolopo my dearest brother Ogbeni Bobby lagbara Edunmare e ko nii subu daanu Amin ase. Eeenh o se e rii sir o wa ninu bibeli pe bi aye fe bi aye ko nigbati akoko ba to fun bibo Jesu pe gbogbo eeku lo maa wole ti gbogbo ahon ni yio jewo pe Jesu loba . Hallelujah!!!.
Ogbeni Bobby, se e mo pe Dangote ni ibere problem wa ni Nigeria, ati gba ti o ti je Dangote ni kan lo ngbe onje ni cement ni o,gbogbo ohun Dangote nse ilopo ona mejo si mewa lo mo nda ,Dangote ijoba ati awon olowo wa lo nfi iya je gbogbo mekun gbogbo won ni olorun ma san won lesan ise owo won lase edumare
Ogbeni Bobby, Yoruba so pé ''à irin jìnà ni a ò rí abuke òkéré, tí a bá gbọ́n odò jini a ó ri arọ eja" bí ọrọ ìlú Nàìjíríà tí rì nì yẹn nípa àwọn tí ń fi orúkọ Jésù Kristi kí ìrun. Kò sí ohun tí kò ṣẹlẹ̀ ní ìlú Nàìjíríà o.
E kasan oooo, Ogbeni Bobby. I wasn’t available ni ano ni ooo, I missed the show🤣😂, visited families & friends ni ooo. E ku eeto ooo, awon ebi nko? A ku isinmi ano. Aaya nko ooo? E ba wa ki gbogbo ile ooo, enjoy the day ❤
Happy Sunday Mr Bobby. Iba go straight to the point. Ibadan lo ni Fuji ooo. Wasiu Ayinde Fuji is adulterated. If you listen to Pasuma and Osupa songs, honestly you will know that apple is different from orange. Ibadan is the home of Fuji. Yoruba no going back. Ki Olorun my wa dele ileri. Love from Blue Springs America ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️
Yes, you are right, my dad left 216 plots of lands but the oba trespass and sold some plots but my brother's has gone to meet him with police to give him a quite notice, or pay us the money.
OGBENI BOBBY KOWA BORIN SUGBON TI ENIA BA TI IBI ISE DE ATI RERA LOMA NMU ORU WA SUGBON ODAMILOJU IBA YANNANA ENITOBA IPANU LORUKO OGBENI BOBBY ORUKO ARA RE LOMA FI SAWO ❤😂❤😂❤😂
Iba ifesowapo E ku ise o, ipade olomo ilu wa yii kii su emi o, koda Ogbeni Bobby ni awon ara ile mi npe mi,nitoripe,bi mio ba tii gbo iroyin olomo ilu yii lojumo ara mi kii le .Iroyin Ogbeni Bobby lonje kin mo gbogbo ohun to nlo ni Nigeria.Olorun a maa ran yin lowo o,E o ni rogun idiwo ta o fi ni gbo yin mo o,amin.
Nips doctor otito ni o so o, this person may have what we call (MS) this Mutiple Sclerosis,this is a disorder in which the body’s immuns system attack the protective covering of the nerve cells in the brains opt nerve and spinal cords, so this doctor is right
K 1 is a very proud person, he doesn't like to respect Ayinde Barrister when he was alive, All because Ayinde Barrister is a peaceful person, even those that knows where he was coming from. Majority that knows his background!
Ko si ikọ̀kan ninu awọn elere fuji to le ba rekọdu Sikiru Ayinde barisita Oooo. Afi emi afi emi ni o n'damu wasiu ayinde jàre.. Alafia fun ẹni to ba le duro ba d'ọ̀gba.Se oun nikan ni won da oye fún ni?
Buroda mi, Ogbeni Bobby. Ijoba orun ku si dede ni ooo. Ni orukoJesu, gbogbo orunkun yio ma wole, Amin🙏🏾. As the BIBLE said, AT THE MENTION NAME OF JESUS, EVERY KNEE SHALL BOW AND EVERY TONGUE SHALL CONFESS, THAT, JEUS IS LORD, AMEN 🙏🏾 ❤
Ogbeni Bobby, eku isinmi onio. Olorun aje ki ari opolopo re. Salawatu Abeni ni o ko bi ololufe bawole mabomi ma sanra. Ara nkan to nba aiye je ni ki enia ma ni iteriba tojewipe igberaga ni yio nmu nwon si Ona. Ki olorun maje ki igberaga ba aiye gbogbo wa jeo. Yoruba Nation, No going back. From Chicago
Mr. Bobby happy Sunday. When we get our Yoruba Nation sir, i want you to come and create a TV station for promoting Yoruba Culture. I believe God will help.
Ogbeni Bobby, mo ngbadun yin gbogbo igba , jokes apart, I mean it. Baale mi na , a jo ngbadun yin ni ooo, 😂😂😂. He always tell me, your paddy paddy, Ogbeni Bobby, he’s too much ooo👌, good 👍🏾🙌
Soooooo! E ma bami ki won ki n ma gbọ nibi ❤️❤️❤️❤️👌 much love and respect to him maami
Ogbeni Bobby omo Yoruba atata eku ogbon Olorun. Kudos to you.
Oga Bobby, your news is not boring oo, is a therapy for me o, Eku ise ilu o
❤❤❤❤❤❤
Ogbeni Bobby I always enjoy your show,because of the alubosa orin that you use to put and ur real Yoruba language with your Oyo tone.May the good Lord gives us our Yoruba Nation in Jesus mighty name! GBU!
❤❤❤❤❤❤
Babawa ogbeni Bobby ologun orun
Ogun orun ni iroyin yin monje fun min koda lenu ise 😍😍😍😍😍
❤❤❤❤❤❤😂😂😂😂😂😂
Ogbeni Bobby. Ni oju ati ogbon temi, ko BORING OOOOO, I love ❤️ it, & God is your strength, Amen 🙏🏾
Happy Sunday sir, Ogbeni Bobby. Ekuse takutaku, Oluwa Olodumare aranwalowo o amin Ase Edumare. At this point of no return no resteat no surrender no going back. Yoruba Nation now now now. May God almighty help us. Ase Edumare. Our Represative is Prof Akintoye Adebanji and Chief Sunday Adeyemo Igboho Olodumare. Yoruba Nation la fe. I salute all Agitators and World Medias members also Original people of Yoruba Land. Yoruba Nation now now now. God bless all.
🙏❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️💯👌
Mo ro wipe niwon igbati won ti so sita, o ti dofin. Ayafi ti baba ko ba gba ki o je gomina lo ku.
❤ you iba gbewa debe, God bless your ministry IJMN.
Ati APC ati PPD nkaunkaun ni won. Eni ti baba ba Fasile ni o maa wole, won Dibo won o dibo. Naijiria ni yen fun yin.
Won n fi oruko Jesu kirun,se o wa ya yin lenu ni?boya le ti gbo arakunrin ti oruko re n je IFAKALELUYA!Ko si ohun ti ko le sele! Afi ki Olorun saanu gbogbo wa o!Aàmin❤❤❤
Iroyin Boorin kee, Ko Lee Boorin laelae, Iroyin Idunnu nii, lati Odo Oko Arugbo ti Olorun fi ran, Idunnu koni fi ile O’ Bobby sile ati gbogbo waa Aameen .
🕺🕺🕺🕺🕺🕺❤️❤️❤️❤️❤️ Eseun maami to gbaski
Olorun Oba ngbo Ogbeni Bobby IBA PARONURE NI YIN SIR ALIAS OLOYE REPETE 😂😂😂😂😂😂😂❤❤
Ogbeni Bobby, ma da ni aba wipe ki Kemi kuku lo ma se asoju won ni 🇬🇧 si EU ngbati ko fe faramo ilu re Nigeria 😊
Kemi feran ilu rè , awọn olori nigeria to n baye jẹ ni ko feran
NERC a gba pe gbogbo omo Nigeria ko lo wa lori internet.
Wike must change his character, if he wanted to continue as FCT minister, with Ireti Aigbe ,Fubara and those he made homeless in Abuja.
Interesting 📰🗞️ thanks a million 👍🩷
❤❤❤❤❤
NNPC should be scape, tí ó bá ní bákan nínú, oro ọmọ Nigeria ó jọ wọn lójú rárá o.
Alh Kollinton Ayinla ni Olori Fuji kan
Ogbeni Bobby Orin Salawa Abeni le ma nko yi.
Bẹẹni ooooo😊❤❤
Ogbeni Bobby. I’m still in the UK 🇬🇧, mo wa ki Oba CHARLES ni, oooo, later, going to GREECE 🇬🇷 too, jolly jolly holiday with my hubby❤
It was Sir Shina Peter sing that song.
EKALE ooooo OGBENI BOBBY EKU ETO ooooo OLORUN OBA a ma wa pelu yin oooooo Laseeedumare 🙏🙏 Happy Sunday to you and your family ♥️♥️♥️♥️
Happy Sunday ❤❤❤❤❤
@ogbenibobby Olo mi jowo o je kajo ma gbadun……
Ebenezer Obey-in the late sixties I was in HSC(upper 6) that’s like 6 decades ago!my lil niece,born in 1964 is now 60 years old! how time flies!may God give us long life,in good health and happiness 🙏😇❤❤❤❤❤❤❤
A kú isinmi oni Ooo Oga Bobby..
E ku isẹ takuntakun ❤❤❤❤.Ọlọrun a pin yin ni ere ayọ..Iba gbè wọ́n de'bẹ̀.. let's go there 🎉🎉🎉🎉🎉🎉
Àṣẹ Edumare iya mi to sure ju❤️❤️❤️❤️
Eku ise Ogbeni Bobby, Queen Salawa Abeni lo ko Orin na o ,iba akede Yoruba Nation Odaro
🎉🎉❤❤❤❤❤
Ogbeni Bobby ko wa boring o a npanu ju a ngbadun yin o mo ncrack joke ni o 😂😂😂❤❤❤
Ogbeni Bobby. Gbogbo ogbon ni awon Ile ise monamona wa lati da gbogbo omo Nigeria pada si Estimated bill. Ole ni won.
Ogbeni Bobby eku ise takuntakun OLORUN yio se ase pe ise ninu ayeyin okan yin yio bale.Yoruba nation no going back
Àṣẹ Edumare ❤❤❤
Ogbeni Bobby E ti wa ju olorun ha ma ba yin se eto na kudusi to U❤😂🙏
Amin Àṣẹ Edumare 🙏🙏🙏🙏❤️
Ogbeni Bobby, to God, you and Aaya are my Bible, if I have not watch or listen to your program, I don't often get myself, God bless, keep, guide, and protect you and Aaya.
Those officers using hands to pick or pack evidence lack critical thinking in security.
Wowwwwww! ❤❤❤❤❤❤❤
Eku eto iyawa salawa abeni❤❤❤❤
Ogbeni Bobby Mo ki yin e ku ise o ,ise nla lense o, O daaaro o. ka sun re o .
Eseun gan ni o ❤❤❤❤❤❤🎉🎉🎉
The "Ecumenism Movement" through "Chrislam"is in full swing😂. Only in Nigeria could such blending occur. It appears that they are able to serve two different masters harmoniously. 🤔
Thanks bro 😎. Listen to the end of yesternight news, much appreciated 👊🏾👏🏽🙌. E ba wa ki ile ooo, ipade wa bi oyin ooo, o di asale, ❤. Enjoy the day further ✌️.
Se money security ni awon ti won fi tele awon eyan loo si ori ii ATM.
E seun gaan lopolopo my dearest brother Ogbeni Bobby lagbara Edunmare e ko nii subu daanu Amin ase. Eeenh o se e rii sir o wa ninu bibeli pe bi aye fe bi aye ko nigbati akoko ba to fun bibo Jesu pe gbogbo eeku lo maa wole ti gbogbo ahon ni yio jewo pe Jesu loba . Hallelujah!!!.
Hello Ogbeni Bobby
E ku ise takun takun
Eku Orin a hun Gbadun yin o fun Orin ti e hun ko Adupe Oluwa Seun
Eseun ❤❤❤❤
Alhaja Salawa Abeni ni o ko o
Awon eliyii to soonu. Olorun abaa waa too. Confusionist ERA. Only In Nigeria. Eyii naa 9ice
Salawatu Abeni, "Wákà Queen" ni ó kọ orin náà o. Ẹ kú isẹ náà.
❤❤❤🎉
O da bi pe ina Bisco ni à ma n pe ni aye igba na!
🎶 🎵 🎶 BISCO ISANA ODUN 2ce
BO DUN BA DE O
MA RA FUN OMO MI ❤❤❤
Iya wa Salawatu ni eni ti o ko orin naa.( Orin Waaka ni)
Ijo yoyo by Alhaji Ayinla Kollinton. I'm not sure if he eventually married Salawa Abeni
Ogbeni Bobby Alawada iroyin ololufe yoruba nation gbogbo Agbaiye god bless you god bless Ayah yoruba nation no going back Onirugbon ewa I love you
❤️❤️❤️❤️❤️❤️🙏🙏🙏 Àṣẹ Edumare ateyin naa 🙏❤️❤️
Ogbeni Bobby, se e mo pe Dangote ni ibere problem wa ni Nigeria, ati gba ti o ti je Dangote ni kan lo ngbe onje ni cement ni o,gbogbo ohun Dangote nse ilopo ona mejo si mewa lo mo nda ,Dangote ijoba ati awon olowo wa lo nfi iya je gbogbo mekun gbogbo won ni olorun ma san won lesan ise owo won lase edumare
Ogbeni Bobby, Yoruba so pé ''à irin jìnà ni a ò rí abuke òkéré, tí a bá gbọ́n odò jini a ó ri arọ eja" bí ọrọ ìlú Nàìjíríà tí rì nì yẹn nípa àwọn tí ń fi orúkọ Jésù Kristi kí ìrun. Kò sí ohun tí kò ṣẹlẹ̀ ní ìlú Nàìjíríà o.
E kasan oooo, Ogbeni Bobby. I wasn’t available ni ano ni ooo, I missed the show🤣😂, visited families & friends ni ooo. E ku eeto ooo, awon ebi nko? A ku isinmi ano. Aaya nko ooo? E ba wa ki gbogbo ile ooo, enjoy the day ❤
Ogbeni Bobby, I don't think all this should be surprising to you. The end of the world is just around the corner. This is in the Bible.
Yeah ❤❤❤❤
Ki Olorun bawa se Amin
I’m standing in for mama Dorcas o, so cheeeeessss 😂😂
😅😂😂😂😂😂❤cheseeeeeeeeee
Thank you so much Ogbeni Bobby.....you are doing well.
❤❤❤❤❤❤🎉🎉🎉
Happy Sunday Mr Bobby. Iba go straight to the point. Ibadan lo ni Fuji ooo. Wasiu Ayinde Fuji is adulterated. If you listen to Pasuma and Osupa songs, honestly you will know that apple is different from orange. Ibadan is the home of Fuji.
Yoruba no going back. Ki Olorun my wa dele ileri. Love from Blue Springs America ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️
❤❤❤❤❤❤❤❤❤🎉🎉🎉You are very much correct 💯
Salawa Abeni ni o ko ori na o.ogbeni Bobby.Happy Sunday o from Arizona
Amin oooo, ewon ki se ti gbogbo wa ooo, loruko Jesu.
Yes, you are right, my dad left 216 plots of lands but the oba trespass and sold some plots but my brother's has gone to meet him with police to give him a quite notice, or pay us the money.
T.pain,ijoba RICE to ó ní ẹran ninu.Kudos to you Ogbeni Bobbi iba Yorùbá Nation. ❤❤
Yoruba Nation no going back
Love 💕 you too !
❤❤❤❤
Tall, taller, tallest. Short, shorter, shortest. Olorun lo da gbogbo wa, ni aworan ara re 👏🏽
OGBENI BOBBY KOWA BORIN SUGBON TI ENIA BA TI IBI ISE DE ATI RERA LOMA NMU ORU WA SUGBON ODAMILOJU IBA YANNANA ENITOBA IPANU LORUKO OGBENI BOBBY ORUKO ARA RE LOMA FI SAWO ❤😂❤😂❤😂
😂😂😂😂😂❤❤❤❤❤
Cheese oooo, e ya mi lati ori de ese, 😂❤
Ogbeni Bobby ema rora tu asiri awon alaisalomu tori awon nka ngbo ti won si ntu mo re fun won.ese sir
Ogbeni Bobby. Awon ijoba UK 🇬🇧 lo ye oooo, ofin lotun, ofin losi 😂
Wake Queen Salawa Abeni ni o
Iba re Jesu, iba re Alagbara, iba re Atobiju oo, Jesu, a juba re ooo, Amin❤
Osun ti tan ni oja tipetipe.
Oja ibo la ti Lee ri osun ra.
Ibadan lo ni Fuji o. Ijebu lo ni Apala❤❤❤
Egba loni fuji
Iba ifesowapo E ku ise o, ipade olomo ilu wa yii kii su emi o, koda Ogbeni Bobby ni awon ara ile mi npe mi,nitoripe,bi mio ba tii gbo iroyin olomo ilu yii lojumo ara mi kii le .Iroyin Ogbeni Bobby lonje kin mo gbogbo ohun to nlo ni Nigeria.Olorun a maa ran yin lowo o,E o ni rogun idiwo ta o fi ni gbo yin mo o,amin.
Se lootọ ❤❤❤❤❤ ogbeni Bobby lọ faaaaar niyen.....
No ko wa bo rin at all
Asa wa ede, wa ni gbo gbo igba is amazing
❤❤❤🎉
Yoruba Nation now now now
Salawa Abeni ni o
Ogbeni Bobby ati Aaya. Aku isinmi oni o. Ose ayo fun Gbogbo wa loruko Jesu.
Amin lorukọ Jesu ❤❤
Ogbeni Bobby wa la wa ooo😂😂😂
Nips doctor otito ni o so o, this person may have what we call (MS) this Mutiple Sclerosis,this is a disorder in which the body’s immuns system attack the protective covering of the nerve cells in the brains opt nerve and spinal cords, so this doctor is right
Ogbeni Bobby. Agbami omi deep deep ni eleyi ooo😮
Ilu le...Sir Victor Olaiya's song first came in the early sixties then reproduced in the late late eighties by him
Ogbeni Bobby ese sir won o mase ara won ni Loruko JESU Dangote ati awon Kaba arin yo daru titi lai amin.
Alhaja Queen Salawa Abeni lo ko orin yen.
NNPC will not sell crude oil for Dangote,because selling it for Dangote will not let them loots money!
You are on point ❤
K 1 is a very proud person, he doesn't like to respect Ayinde Barrister when he was alive, All because Ayinde Barrister is a peaceful person, even those that knows where he was coming from. Majority that knows his background!
Ogbeni Bobby, eku ise takuntankun o, se Aaya ngburo iyawo re Bobrisky o.
😂😂😂😂😂 E ma jẹ ki aaya binu ooo
Queen Salawe Abeni Song
👌💯
Ko si ikọ̀kan ninu awọn elere fuji to le ba rekọdu Sikiru Ayinde barisita Oooo. Afi emi afi emi ni o n'damu wasiu ayinde jàre.. Alafia fun ẹni to ba le duro ba d'ọ̀gba.Se oun nikan ni won da oye fún ni?
Mr Bobby e ku ise Olorun a tubo ma ro yin lagbara ami Se e ri Dangote ati awon emewa e gbogbo won Olorun ma da Ede won ru , Ika ni gbogbo won
Longtime Ekale sir dad Bobby yoruba nations know going back ❤❤
Salawatu Abeni
God bless you sir ❤❤❤❤
Yoruba Nation no retreat no surrender
Ogbeni Bobby e jo nibo latun jasi bayi o,lori awon chrislaham yi o?
Buroda mi, Ogbeni Bobby. Ijoba orun ku si dede ni ooo. Ni orukoJesu, gbogbo orunkun yio ma wole, Amin🙏🏾. As the BIBLE said, AT THE MENTION NAME OF JESUS, EVERY KNEE SHALL BOW AND EVERY TONGUE SHALL CONFESS, THAT, JEUS IS LORD, AMEN 🙏🏾 ❤
Ogbeni Bobby, eku isinmi onio. Olorun aje ki ari opolopo re. Salawatu Abeni ni o ko bi ololufe bawole mabomi ma sanra. Ara nkan to nba aiye je ni ki enia ma ni iteriba tojewipe igberaga ni yio nmu nwon si Ona. Ki olorun maje ki igberaga ba aiye gbogbo wa jeo. Yoruba Nation, No going back. From Chicago
Hmmmn. Oro nla lẹ sọ ❤❤❤❤❤❤
Irohin to ta lenu.
O ta lenu😂😂😂😂😂
Lo baa taaan. Se otan epo si ilu oyinbo. Hes gaining either or. 9ice one. Let Nigerians gain 2. Is high time.
Mr. Bobby happy Sunday. When we get our Yoruba Nation sir, i want you to come and create a TV station for promoting Yoruba Culture. I believe God will help.
That's the target. We are destined to rule ❤❤❤❤❤❤
ALHAJA SALAWA ABENI ni ooooo
Adeyimika Ayinde Siki Oluyole Barrusati, Barrister Mr Fuji, Oku ohun re si n 'fohun sibe. Su u n' re o!
Queen salawa abeni
Salawa abeni
Eku eto ogbeni bobby olohun ama bawato salawa abeni ni o
Ase nt'edumare ❤❤❤❤
Yoruba Nation no going back ooooooooo