Well done sir. There's this part of your Masoyinbo episode where you asked about "strike" I need you to explain more about "ìdasẹ́sílẹ̀" and "ìyansẹ́lódì" What English fits both appropriately?
Awon ara ilu fi fehonuhan notori ijoba apapo fi kun owo epo. Ani lati fi fehonuhan fun oludari ile ise wa notori owo osun ko to nkan nkan. Awon oloja oja oba fi fehonuhan ni afin oba nitori wipe awon olode ko shishe won bi ishe. Awon olowa oko fi fehonuhan fun ijoba ipinle nitori awon agbeoba ko je ri won ri imu mi mo. Emi fi fehonuhan fun EA Yoruba wipe ki won ma din owo awon alejo ti won kopa ninu masoyinbo mo ti won ba gba onka won 😂 Olootu, eshe takun takun fun ishe yin, a o ma riyin ba #Ashe
Great info
I love you zaddy 💝💝 keep it up👍
E ṣeun adupẹ, olukọ wa!
You're doing a great job
Ese pupo Oluko
Amo e ti rewa ju❤❤❤
Well done sir.
There's this part of your Masoyinbo episode where you asked about "strike"
I need you to explain more about "ìdasẹ́sílẹ̀" and "ìyansẹ́lódì"
What English fits both appropriately?
Yorùbá dùn lédè. ❤
Ẹ ṣeun gan-an ni olootu Ẹ kú ìṣe takuntakun
Keep it up
Proudly yoruba
More. Pls give us more. 🎉
Weldon ❤
I love what you do. Keep it up👏👏👏
Thank you for this teaching...
God bless you sir.
You're doing well.💯
God bless u more sir for the wonderful work that u are doing
Ọlọrun a maa fi kún ọpọlọ yin.
Ẹ n gbiyanju gidigidi 💯
Yes I can use it in five sentences Mr presenter
1)Ìfèhonúhàn Lórí Owó òsìsé ìjoba tó kéré
2)Olámidé Badoo kó pèlú àwon tí ófièhónúhàn ní àná #Olamide_Badoo
Great analysis ❤
Good job well done Sir...pls what is this your board called
Ódàrà
This is such a vibe ❤
Good
More knowledge baba miam also interested to be on your programme.
Haliamudulila.
Ẹ kú iṣẹ́ takuntakun.
E senu oluko, e ku imo.
eku ise takuntakun
E seun púpò.
Awon ara ilu fi fehonuhan notori ijoba apapo fi kun owo epo.
Ani lati fi fehonuhan fun oludari ile ise wa notori owo osun ko to nkan nkan.
Awon oloja oja oba fi fehonuhan ni afin oba nitori wipe awon olode ko shishe won bi ishe.
Awon olowa oko fi fehonuhan fun ijoba ipinle nitori awon agbeoba ko je ri won ri imu mi mo.
Emi fi fehonuhan fun EA Yoruba wipe ki won ma din owo awon alejo ti won kopa ninu masoyinbo mo ti won ba gba onka won 😂
Olootu, eshe takun takun fun ishe yin, a o ma riyin ba #Ashe
E ku ise
Your tonal mark for ìfí(do mi) is wrong. It should be Ìfi(do re).
Listen to him again. He said Do-rẹ but drew the sign wrongly.
Professor, go and try what he is doing if you sabi ham.
E ku ise oluko.
Ẹ kùn ohùn
I thought it was an open-up
Pls don't speak English ooooo. It is sweeter with Yoruba. We understand better in our native language iree ooo
🏆🥹 ... am i the only one mind-blown that he is literally writing on the screen?
That's the work of a green screen, the edit makes it look like that to us
not only you