Baba toloun gbe ga kawon aladanwo omo kan waa ni awon fee fi ete kan, otito foju han abi ko han bayi. Esaa je kamaa so ododo kasi maa se ododo. Ati Markas, ati Acadip ati Adahbiya ati gbogbo awon ti won ba duro ti ododo ninu awon musulumi ki oloun ma doju tiwa, ki oloun gbe Islam ga. Lahaola walakuwatan, ilaa biLlah.
@teejay9674 Same to you 👈 Your comment show's you're not oni jagidijagan indeed. Point one finger to a fellow human, the rest fingers point back's to you.
Gbogbo eyi ti iwo so yi, kini itumon ti o fe ka funn? Wiwa alaafia abi? O ya mi lenu pe e si wa laiye, abi kosi musulumi ladugbo yin ni, e o ni oree musulumi ni, iru ise wo len se? Se e o ba musulumi pade lati ojo ti won ti bii yin saiye ni? O waa ye ki eti ku, tori nigbati gbogbo musulumi je murderer, o ye ki awon ti mo ti daruko yi ti pa yin. Oloun aa fun yin ni suuru o! Tori gbogbo awon oro yin yi fi han bi inu musulumi se nbi yin to. Pelu gbogbo ibinu yin yi, eyin gangan ni alakatakiti, oni jagidijagan. E loo ni suuru, ki esi wa ododo kan, and oloun okan soso ni ao maa sin abi.
"Tiwọn ba fẹ́ da ìjà wọn ja, we are ready" i love the boldness 👏👏👏
Malam is always joyful to listen to
Baba toloun gbe ga kawon aladanwo omo kan waa ni awon fee fi ete kan, otito foju han abi ko han bayi. Esaa je kamaa so ododo kasi maa se ododo. Ati Markas, ati Acadip ati Adahbiya ati gbogbo awon ti won ba duro ti ododo ninu awon musulumi ki oloun ma doju tiwa, ki oloun gbe Islam ga. Lahaola walakuwatan, ilaa biLlah.
I am very happy with reunion jasaakum Lahu aeran I am very excited
Alfa Yesaoloonaka I happy and thank Allah for you
Wallohi baba dada ni baba wa baba adepoju
Subhaanallah, only can cure this okanlomo
Awon Agba Lawyers respected ✅
What are the ones that formally encouraged and fund Alfa Yesaolunnaka next of actions
How I wished Mallam Yusuf’s wife can addressed us I am sure she is an intelligent beautiful woman like Mallam Yusuf
You've got no business with her as a man.
The lawsuit yi ma gbenu gan how I wish it would be televised
Very intelligent
Malam eku suru
Wonderful diligent remarkable sensible reunion,this is the beginning o ti bere niyen
Adepoju loves going to court. Is Jamiu Adegunwa next or he begged you and you forgave him? 🤔 He says he will NEVER beg you.
U wants him join thise nuisance by exchange defamation or what I will report them to government if they won't apologize
Awon Oniyeye
O ti ka loju Oka, o ti ka loju sebe... Ko sogun mo ko sote mo...
Ki lo de gan ki ni family yi se gan
One billion naira after deformation of character
Olohun ju eda lo
ACADIP VISITS TO MARKAZ LO BA TAN 😂😂😂😂😂
What’s funny about that?
So you are able to hack this account to
Lo ba tan
Awon werey dede, asan eranko lasan lasan. Murderers, awon oni jagidijagan , alakatakiti esin. God punish you all
abiooo awon ti won gba dun
@teejay9674 Same to you 👈 Your comment show's you're not oni jagidijagan indeed. Point one finger to a fellow human, the rest fingers point back's to you.
Look at u, okponu ur brain no dey work 🙉🙉🙉