Dr Bilal Asra, Esaoke ti ni ki e mu eri Fidau wa. Ejo lenwi. Yoruba level. Ijo meta, mejo, ogoji ojo ounje awon Alufa ko si eri. Dr Bilal Asra ti challenge re ki jade pelu eri.
E mu eri ti ko ni amulumala wa ti o so clearly lati inu quran tabi lati enu anobi, wipe ko si fidau. A ko lati enu ibn tamiyya ati awon alfa miran. E mu direct and clear evidence wa lati enu eni ti Olohun ran nise. A ko fe alfa, sheikh, Imam lagbaja, tamedu tabi lakasegbe sope.
اللهم زد لشيخ مصري علما وفهما وانفعنا بعلمه واجعلنا للمتقين إماما
Thanks sheikh, you just earned my respect
Dr Bilal Asra, Esaoke ti ni ki e mu eri Fidau wa. Ejo lenwi. Yoruba level. Ijo meta, mejo, ogoji ojo ounje awon Alufa ko si eri. Dr Bilal Asra ti challenge re ki jade pelu eri.
Niki esa oke ati awon egbe yin toku daun si chalenge ti alfa yipe ki won jo fi imo jagba
Sheikh Ajani Bello ni ko si Fidau. Period!
Afizõhu-Llāhu Wā-Rāhãhu Shēikh Al-Misry. Ọlọhun Ajẹki Ariyinpẹ Sir
Mo wo fideo naa gele bi ese so oro naa leso yi,
❤❤❤

Òdòdó Ọrọ