IDAHUN SI ORO BABA ZAITUNY NIPA ORO BABA MUHYIDEEN AJANI BELLO KI ALLOHU KEWON

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 15 дек 2024

Комментарии • 6

  • @Chilatech
    @Chilatech 2 часа назад

    JazakumuLLAHU Khayran Sir God bless you

  • @muhammadmudathir7382
    @muhammadmudathir7382 4 часа назад

    This short naseehah should be sent to BABA ZAITUN حفظه الله ورعاه

  • @taofeekbello9629
    @taofeekbello9629 4 часа назад

    Jazakumullah khayr yaa shaykhanaa. The clarification is well understood may ALLAH open our heart to see the truth as truth and the courage to establish it and let us see false as false and the courage to dissociate from it privately and publicly.

  • @nafisatadeola1678
    @nafisatadeola1678 4 часа назад

    Assalamualaikum waramotulahi wabarakatu

  • @HadizaOyediran-cm8yi
    @HadizaOyediran-cm8yi 5 часов назад +3

    WaLlahi mo ri Shehikh Aboto to se waasi pe eni ti a te fun yio rojo, eni ti o te fun eeyan yio rojo, ninu video naa gaan Shehikh Aboto te fun eeyan, ibeere ni pe se daadaa ni won se fun al ummah ni abi aburu? WaLlahi daadaa ni won se, akoko ni pe, awon yi o ki nse alabosi, ki won waa maa wa eri fun nkan ti won nse ki aiye le maa ri won gege bi oni mimon, won o tan awon eeyan pe nkan ti awon nse yen gangan lona. Mo si gbo video Shehikh Adam nibi tiwon ti so pe idobale ati ikunle o lo, ati pe awon gaan ko si inu e. Ki waa niy wahala awon eeyan yi nipa oku sise. Ijo wo ni awon lo si ibi oku ti won waa nfi idi e munle pe oku sise o daa gege bi baba Muyideen ti ma nso koda ti won o tun bu won pelu, ti awon yen o ba kinse alabosi, won o se ba baba gbee si ibi pe won nlo awon ijoko yi lati so fun won pe nkan ti won ko si o daa. Won ni nitori pe Jaafar je odo ni won fi ni ki awion araale e ma dana pe awon eeyan ni ki won o gbe ounje lo fun won, to ba pe ina dida je adua ati
    Saara fun oku, se Jaafar o to si adua ati saara? Ti eyin aafaa jokujoku yi o ba pate fidau, ina dida ati ounje fun awon eeyan ni ojo meta, ojo mejo, ogoji ojo, koda odun kan fun omo odun kan to ku tabi koda oyun inu to baje, eni
    Ibi, ole ati alatenuje ni yin ati alabosi. Se bi eti baa de
    bi pe leyin fidau eyin gaan tun njoko si party ti awon eeyan oku nse leyin fidau. E mon ododo sugbon e gbee kale tori aiye ati ife inu