O ṢẸLẸ! IDILE ỌDẸJAYI FARIGA, WỌN L’AWỌN MUSULUMI KO GBỌDỌ KIRUN NI YIDI

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 11 окт 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Комментарии • 18

  • @aladjimoustaphaiguewassiou9576
    @aladjimoustaphaiguewassiou9576 3 месяца назад +21

    Ki wọn lọ wá àyè sí ibòmíràn,, àṣejù àwa musulumi ti pọ jù,,,ki lo De,,ṣe, àwa nikan nii

    • @_Abdussalama
      @_Abdussalama 3 месяца назад

      { ٱلَّذِینَ یَتَّخِذُونَ ٱلۡكَـٰفِرِینَ أَوۡلِیَاۤءَ مِن دُونِ ٱلۡمُؤۡمِنِینَۚ أَیَبۡتَغُونَ عِندَهُمُ ٱلۡعِزَّةَ فَإِنَّ ٱلۡعِزَّةَ لِلَّهِ جَمِیعࣰا }
      [Surah An-Nisāʾ: 139]
      (Àwọn ni) àwọn t’ó ń mú àwọn aláìgbàgbọ́ ní ọ̀rẹ́ àyò lẹ́yìn àwọn onígbàgbọ́ òdodo. Ṣé ẹ̀ ń wá agbára lọ́dọ̀ wọn ni? Dájúdájú ti Allāhu ni gbogbo agbára pátápátá.

  • @iloriabiodun9682
    @iloriabiodun9682 3 месяца назад +9

    Ogbomoso , e se be na fun won

  • @alaladefatai2900
    @alaladefatai2900 3 месяца назад +8

    I love that

  • @haynehifanny8006
    @haynehifanny8006 3 месяца назад +3

    "Mu ẹmi lọ" Ṣe ilẹ baba wọn ni? Awọn onilẹ sọwipe kiwọn gafara!

  • @JennyDemmy-x8m
    @JennyDemmy-x8m 3 месяца назад

    I love that to ❤❤

  • @jamiuomogoriola8300
    @jamiuomogoriola8300 3 месяца назад +2

    Odabe ooooo aseju awon musulumi

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 3 месяца назад +1

    Ki Oluwa Olorun Oba... Sanu fun wa ni ! Oba farao lose iru nkan ti awon idile yii se.... E jowo ta loni ile Olorun Oba Jehofa ni..... Ema wo ikan toma sele siwon! Oba farao ko pada ri ojurere Olorun Oba mo titi to fi ku.....

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq401 3 месяца назад +1

    Se dandan Ni Kie soro abuku si eyan Ni
    Teba ti Wani waju bai bi wipe eju gbgb eyan lo ni
    Ema soro

  • @DaoudaABIODOUN
    @DaoudaABIODOUN 3 месяца назад +1

    C'est très dommage pour vous

  • @Awake_Africa
    @Awake_Africa 3 месяца назад +6

    I darabe won I gbodo fun won ni leyen mo. Eranko lasan niwon. They are just too arrogant

  • @horlahinksj7644
    @horlahinksj7644 3 месяца назад +1

    When a religion is filled with intolerance, lack of respect to people that the creator pits in place of authority, lack of manners, such religion is definitely not a good religion.

  • @adeyemiadegboye2548
    @adeyemiadegboye2548 3 месяца назад +7

    Won tun ti gbe iwa were won de ejigbo na. Oju o ki ti awon elesin imole jagidijagan yi ni. Gbogbo igba awon nikan na ni