Prophet Segun Micheal IRIJU OLUWA ATI IKO ELEDUMARE We the members of Cherubim & Seraphim Movement Church, Surulere AYO NI O always proud of you More Anointing Sir Ese Debi Ere.
E je k'e ni t'o ba fe wo'so, k'on wo'so. Aso adura t'a won kan nran gbe wo, ti gbogbo bi idi won to burewa ma han si'nu aso adura yen l'e fe k'elomiran ma a ba yin se. 'Awon kan ka'so s'ara bi eegun', emi ilara lo je k'awon kan ti won ma nwo'so adura bi igba ti eru ba mura, ma a so'sokuso. Mo ti ma ngbo isokuso yi l'enu opolopo yin, awon ti won de nso na, Irisi won o wu eniyan, be e ni imura won dabi t'eru. Omo oba l'awa, omo Olorun Olodumare, nitori bee, a a k'aso s'ara. L'o ba tan.
Prophet Segun Micheal
IRIJU OLUWA ATI IKO ELEDUMARE
We the members of Cherubim & Seraphim Movement Church, Surulere AYO NI O always proud of you
More Anointing Sir
Ese Debi Ere.
Wisdom
E je k'e ni t'o ba fe wo'so, k'on wo'so. Aso adura t'a won kan nran gbe wo, ti gbogbo bi idi won to burewa ma han si'nu aso adura yen l'e fe k'elomiran ma a ba yin se. 'Awon kan ka'so s'ara bi eegun', emi ilara lo je k'awon kan ti won ma nwo'so adura bi igba ti eru ba mura, ma a so'sokuso. Mo ti ma ngbo isokuso yi l'enu opolopo yin, awon ti won de nso na, Irisi won o wu eniyan, be e ni imura won dabi t'eru. Omo oba l'awa, omo Olorun Olodumare, nitori bee, a a k'aso s'ara. L'o ba tan.
This man 👏🏽
Indeed PSM is a Light