iro Lasan

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 29 янв 2025

Комментарии • 54

  • @walesal7906
    @walesal7906 День назад +7

    Edumare awa pelu yin alfa sodiq, omo Yoruba ATATA, love your courage ❤❤❤

  • @azeezbabatunde9542
    @azeezbabatunde9542 2 дня назад +8

    Allahu akbar! So the awareness had gone far. Adupe lowo Olodumare ati awon Irunmole.

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 2 дня назад +8

    Isilamu pelu Iro, Etan ati Ikonileru

  • @mercyjoy5409
    @mercyjoy5409 2 дня назад +14

    since they killed innocent Deborah i left Islam

    • @binaryworld4000
      @binaryworld4000 День назад

      It's islam they used to occupied North Africa lands from blacc people

  • @sunlight9091
    @sunlight9091 День назад +2

    To even say a child should not prostrate for his parents is the worst it. Like what? I grew up prostrating not only for my parents but elders. Honour your father and mother that your days may be LONG.

  • @PaulOMIALE
    @PaulOMIALE День назад +3

    Ekare Alfa, omo oko ni yin
    Èèjè ka pada kuro loko èru
    Ikoni l'èru ni Islam

  • @oluseyeojo3726
    @oluseyeojo3726 2 дня назад +8

    Iwa agidi ati Ipanle to romo esin musulumi . Alafia jinna si esin naa.

    • @IleKewuTV
      @IleKewuTV  День назад

      @@oluseyeojo3726 Iṣẹdalẹ Islam niyẹn.

  • @solabolaji5364
    @solabolaji5364 2 дня назад +10

    Lols...who are those leaving Christianity? For real Christianity did not enslave the people as Islam. The Bible is written in many languages and each is free to exit a congregation if one feels uncomfortable. Ẹ jooor, ẹ face Isilaamu yin, ẹ fi Kristẹni sílè. Yoruba ni mi o!!! Mo feran ìran mi...!!!

    • @IleKewuTV
      @IleKewuTV  День назад +2

      @@solabolaji5364 ati islamu o, ati kiriyo o, igbo rere.

  • @PaulOMIALE
    @PaulOMIALE День назад +3

    Èni ti koba le ronu ko le gba ara rè kuro l'oko èru arabu

  • @MakanjuolaKolawole
    @MakanjuolaKolawole День назад +2

    Konida fun Allah ati Muhammed

    • @IleKewuTV
      @IleKewuTV  День назад

      @@MakanjuolaKolawole Aṣẹ wa.

  • @olatunjifredrick8192
    @olatunjifredrick8192 2 дня назад +4

    Hahahaha

  • @ibukunben8051
    @ibukunben8051 2 дня назад +6

    Kini ka ti gbo ni esin imale

  • @UsamotLukmanoluwatosin
    @UsamotLukmanoluwatosin 22 часа назад

    Opuro aiye ati orun nio

  • @UsamotLukmanoluwatosin
    @UsamotLukmanoluwatosin 22 часа назад

    Amo eyi ti eun se yi Ibinu olohun Oba le un wa,eo si ri

    • @adeoluwaoladeji834
      @adeoluwaoladeji834 15 часов назад +1

      Olorun tibo se olorun olodumare yoruba abi alhah tiyin ni Saudi Arabia, e mope alhah ni olorun olodumare mo babe ti seju oju tira bi asa igbira , bawo ni mase fi Ogun sile Nile yoruba ti ma lo ma fi enu pon okuta Mecca la , lai je eranko eniyan

  • @adedejijamiuolalekan4236
    @adedejijamiuolalekan4236 День назад +4

    How can son Narrated him four father history, say nah Muhammed they Narrated all the remaining prophets stories, and they said nah him bring Quran come, so therefore Quran is not from only Muhammed, nah there stories book

    • @IleKewuTV
      @IleKewuTV  День назад

      @adedejijamiuolalekan4236 Bẹẹni. Iwe itan lasan ni Qurani. Mo ti sọrọ lori ẹ. Ẹ check awọn videos mi, ẹẹ ri n bẹ.

  • @PaulOMIALE
    @PaulOMIALE День назад

    Awon didirin lo nshé islawere

  • @kemoblunsky3794
    @kemoblunsky3794 15 часов назад +2

    Nina buruku ni won tun fi n ko yin ni ede elede,😅😅😅, won a ma fi egba fun won ni eko ati ede ajeji, afi bi afise,SMH, more reasons ti won fi n ganusi kakiri ile olowo, awon babi anla 😂😂😂

  • @UsamotLukmanoluwatosin
    @UsamotLukmanoluwatosin 22 часа назад +1

    Eni tobawu kose Islam,eni tobasituwu komase,kosi tipatipa ninu Islam

    • @IleKewuTV
      @IleKewuTV  13 часов назад

      @@UsamotLukmanoluwatosin Jọwọ bawa yẹ hayat-ul-Qur'an yii wo pa pa pa Quran 5:33. Ko sọ fun wa nkan tii aaya yẹn sọrọ le lori.

    • @UsamotLukmanoluwatosin
      @UsamotLukmanoluwatosin 11 часов назад

      @IleKewuTV tio ba woye si Qur'an yi daada wariwipe ese meta lowa nibe,(1) gbogbo gun ti Olohun (2) gbogbo gun ti Anabi (3)sise ibaje lori ile,Ese kookan loni agbara buruku ti kosi dara rara.ohun ti Olohun Oba fe ko sele ni wipe ki alaafia le joba.idi ni wipe eni tio gbogun ti Olohun Oba, awon to ni Olohun lodo won o ni gba fun,eni tosi tun gbogun ti Anabi, awon to feran Anabi won o ni gba fun,otun wa un wuwa ibaje lori ile.(iwa ibaje bi ki eniyan pa eniyan)iru eni tio ba un se inkan meteta yii,ko ni fun ara aiye ni isinmi,kosi ni je ki aiye o ni alaafia.idi ni yen ti Olohun Oba fi ni ki ijoba pa,ki kan mo igi,tabi ki ijoba o ge owo ati ese re ni ipasipayo.kii se musulumi loma da ejo yen fun iru be o,eni toba n be ni ijoba ni yoo sebe.

  • @UsamotLukmanoluwatosin
    @UsamotLukmanoluwatosin 22 часа назад

    Oki un se alfa rara, u're not alfa atall

  • @UsamotLukmanoluwatosin
    @UsamotLukmanoluwatosin 22 часа назад

    Apadasi aburu lo bao ati awon irure yoku

    • @adeoluwaoladeji834
      @adeoluwaoladeji834 15 часов назад +1

      Mr Fulani togbo yoruba, olorun yoruba lawa nsin mi o le sin alhah Saudi

    • @UsamotLukmanoluwatosin
      @UsamotLukmanoluwatosin 15 часов назад

      @adeoluwaoladeji834 Se Olohun Yoruba yato si Olohun larubawa ni?alaimokanmokan lasan nio Olohun Oba oyo kan soso naa lo un be losi seda gbogbo nkan patapata

    • @IleKewuTV
      @IleKewuTV  15 часов назад

      @@adeoluwaoladeji834 Allah alapa ọtun meji.

  • @abdullateefarije-cy3qp
    @abdullateefarije-cy3qp 2 дня назад +1

    Who are you to decide for we Muslim

    • @ascendusa1661
      @ascendusa1661 2 дня назад +6

      And who are you to decide for the rest of us. The sharia that you guys want affects the rest of us and that's why it's unacceptable. No one is deciding for you not to go to mosque or practice your religion. You have always practiced your religion without sharia in Yoruba land. Why now must you have sharia in our land? This is Yoruba land, not Kano. Yoruba decides what we want in our land. And we do not want Sharia period.

    • @omisanmiolayinkaadesoji7985
      @omisanmiolayinkaadesoji7985 2 дня назад +5

      Oponu nie jare, Eran ni e.

    • @adebayojohnson3624
      @adebayojohnson3624 День назад +4

      Pele oo Eru awon Orisa Qureshi 😂😂😂😂

    • @abdullateefarije-cy3qp
      @abdullateefarije-cy3qp День назад +1

      I don't see a single person convinced with this your ranting I swear I don't find a single person u.re.just wasting your energy and time

    • @adebayojohnson3624
      @adebayojohnson3624 День назад +3

      Lol for real people dey leave Islam for real
      People are leaving Islam not only in Nigeria in other Arab countries they're leaving