IFẸHONUHAN TO MAA LAGBARA JU TI ENDSARS LỌ YOO ṢẸLẸ LỌDUN YII BI TINUBU BA… PRIMATE AYỌDELE
HTML-код
- Опубликовано: 5 окт 2024
- We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
He's just predicting this with the situation of this country!
Ijoba buruku ni ijoba Tinubu yi
Am always against this our Baba before but now this prophecy may become reality,, because all what he has said before APC primary election and presidential election and what would happen after election updates has come past... good of you Sir
Lori iro pastor
O ye ko ti sele bayi oo, ebi yi poju
For real... like 7 different people asked me for money today.... people who are working class
Ko tete sele ooo, tinubu tifee jeki aiye suwa ooo oloriburuku ni tinubu yio kole ni atunbotan ti o ban baa lo bayi
Alfa tóní Ìyàn yíò mú" Omo tiè náà kòní je Tírà.
Lori iro
Lo joko jare, irolabi.
Emigan ti lala si tinubu pe ota pofun ..ni ojokini osukeje yiii ni molala na sugbon oni ona abayo si nkan tosele yii .. ona abayo tiwon fiwon ni pe baba tinubu.. pe gbogbo babalawo togbofa dada kiwon da ifa won towalowo nile nkan tio baso nikanse ... ona abayo kan soso tonibeniyen ... timoba paro ki ifa se idajo funmi ati lorun
Eyin kokin ri Iran toda so ni?
HNNNNNNNNNN