ITAN ILU IWERE ILE

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 13 сен 2024
  • Kò ṣeé ṣe láti sọ ìtàn Àláàfin Aólẹ̀ àti Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò Àfọ̀njá láì mẹ́nuba ìtàn ìlú Ìwéré ilé. Àwọn ohun tó yẹ kí ẹ mọ̀ nípa ìlú yìí bí: (Ohun tí ó bí orúkọ ìlú yìí, àwọn èèwọ wọn, ìdí tí ogun kìí fi í jà wọ́n, Ìgbéṣẹ̀ tí wọ́n gbé tí ogun Ìdàhòmì ò fi run wọ́n abbl.) ni a mẹ́nuba nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò wa pẹ̀lú Kábíyèsí Ọba Rev. Evang. John O. Ola Ọdẹ́dòkun Ayinla III, Oníwèéré ti Ìwéré ilé ní Ọjọ́rú, ọjọ́ kẹjọ oṣù Kejìlá ọdún 2021.

Комментарии • 20

  • @JosephAyanwola
    @JosephAyanwola 5 дней назад +1

    Imoran Baba wa Oniwere yan lotun se pataki liju temi .verygood. Advise to All Yoruba Lands.

  • @adesuaolanrewaju752
    @adesuaolanrewaju752 Год назад +1

    Thanks so much

  • @idrisbalogun9191
    @idrisbalogun9191 2 года назад +1

    Rara oo iya alafin ajagbo na' sin si iwere ile. Idi ni'ye ti kankannfo kogbodo kogun wo ilu iwere ile

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020  2 года назад

      Nítorí pé ìyá Àláàfin Ajagbo jẹ́ ọmọ ìlú Ìwéré náà ló jẹ́ kí wọn ó sin í síbẹ̀. Ẹ ṣeun o!

  • @idrisalooma5120
    @idrisalooma5120 Год назад +1

    I have been to iwere ile around 1999 to 2001 the town is before itasa along budo-musa village

  • @wasiuisaac3689
    @wasiuisaac3689 Год назад +1

    Eku eto

  • @adesuaolanrewaju752
    @adesuaolanrewaju752 Год назад +2

    Ajagbo is the grand father of Aole and it was Ajagbo that his mother came from iwere ile. Aole was afraid of Afonja and because he wanted to destroy him that was why he ask Afonja to go and bring the head of the King of iwere ile then ,knowing that it is a Mission that is almost impossible Or something that will even end the life of Afonja himself

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020  Год назад

      Àlàáfin Aole sent Àfọ̀njá to Ìwéré ilé as an attempt to end Àfọ̀njá because he was more aware of the existence law. This is another proof that the town has been in existence long before Àláàfin Ajagbo's mother.

    • @oyebamijimuhmeen1816
      @oyebamijimuhmeen1816 11 месяцев назад

      Fact.

  • @IMCTV-me4jn
    @IMCTV-me4jn 2 года назад +1

    Ẹ kú iṣẹ́ pàtàkì yìí o

  • @adesuaolanrewaju752
    @adesuaolanrewaju752 Год назад +1

    Listern very well to what this King is saying here, he Said oba oladigbolu married a wife from iwere ile and he still Said it was Alaafin Abiodun that stopped oyo from attacking iwere Or collect royal dues. Because the history of no invasion of iwere has been long before Aole, Abiodun Or oladigbolu

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020  Год назад

      Exactly my point. The law of no invasion of Ìwéré ilé has been in existence from the time immemorial.

  • @adesuaolanrewaju752
    @adesuaolanrewaju752 Год назад +1

    Bukola let this King state it clear the story that one past Alaafin s mother is from iwere ile because the history we learn says that it was Alaafin Ajagbo that his mother came from iwere ile.

  • @historywitharewa1630
    @historywitharewa1630 6 месяцев назад

    I am very very disappointed and also ready mad at this king , does he even worth to be called a king of an important ancient town . This is really shameful. A whole king doesn't know the history of the throne he is on , imagine saying ladigbulo gave birth to aalafin abiodun . He doent deserve nor meant to be on that throne .