Oluwo is very comical, and innovative. He knows how to provoke his haters! He is RIGHT about our forefather Adam - the first man that God created! He has the DNA of Adam in him, that is why he wants to serve the God of our forefather 😁 I love this chap!
@@onlinework4521 Gẹ́gẹ́ bí àwọn ìran rẹ ṣe wà láti England. Ṣèbí èdè Gẹ̀ẹ́sì ní àwọn baba-nla yín má ń sọ? Aláìmọkan! Mo ṣàlàyé oun tí kò yèé fún ni. Ìwọ tí kò yé ń dá síi. Lọ̀ọ́ sinmi sílé jàre. Òún pè èèyàn l'afọ́jú. Kí ní ẹrí kàn pé Ọ̀rúnmìlà and Ṣàngó bọ̀ òrìṣà rí nígbèsíayé wọn?
Talo ran ni se
1million shoe
E beru olorun oo
Abajo tofi gun rakumi lo si yidi ati igbo mimu ni palace
Haaa
Se oba leniyi sa😮
1.5 million naira shoes and some of his subjects can’t even afford one square meal.
Na weed
Oba beebe o a elenu meji oba daluru oba alabode oba onisokuso
It is now confirmed that this king is both sick in the head and mind. Will this material things put food on the table of the locals?
Igbo labi
Oba Akannbi, is not serious.
Oluwo is very comical, and innovative. He knows how to provoke his haters!
He is RIGHT about our forefather Adam - the first man that God created!
He has the DNA of Adam in him, that is why he wants to serve the God of our forefather 😁
I love this chap!
Wéré oba amugbo
And these gullible people are laughing. Wèrè king
The money that should be use2 empower the less privileged life of vanity
Igobo
On colos on colos 😂
Afiki olohun sa anu wa
😅😅😅
Ṣé olóòótọ́ ni pé Ádámù ní ẹṣin? Ṣé ọkùnrin àkọ́kọ́ tí a dá láti inú àmọ́ ni ẹṣin ṣá?
Koda ki ori eni tan ba fi joba mape rara ori oluwo ko pe rara, o se ma fi owo se anu fun awon eniyan..... Awon Ode omo ilu iwo na rerin 😡...
The prophet Ibrahim is hanif is not Islam is hanif is the religion of Ibrahim not Islam but prophet Muhammad copy him to is lam is hanif
{ مَا كَانَ إِبۡرَ ٰهِیمُ یَهُودِیࣰّا وَلَا نَصۡرَانِیࣰّا وَلَـٰكِن كَانَ حَنِیفࣰا مُّسۡلِمࣰا وَمَا كَانَ مِنَ ٱلۡمُشۡرِكِینَ }
[Surah Āli-ʿImrān: 67]
Èyí ni ìdáhùn sí àìmọ̀kan-an rẹ.
@@_Abdussalama😏😏😏 afọju fọna hàn afọju ur generation come from Saudi Arabian
@@onlinework4521 Gẹ́gẹ́ bí àwọn ìran rẹ ṣe wà láti England. Ṣèbí èdè Gẹ̀ẹ́sì ní àwọn baba-nla yín má ń sọ? Aláìmọkan! Mo ṣàlàyé oun tí kò yèé fún ni. Ìwọ tí kò yé ń dá síi. Lọ̀ọ́ sinmi sílé jàre.
Òún pè èèyàn l'afọ́jú. Kí ní ẹrí kàn pé Ọ̀rúnmìlà and Ṣàngó bọ̀ òrìṣà rí nígbèsíayé wọn?