1.Mo gbodo yera fun ohun gbogbo to le bami loruko je. 2.Iro pipa lo mu ki n yera fun Bisi ore mi. 3.Oju ni mo fi ba Tola soro koto yera fun wa lana. 4.Omolola yera fun mi nigbati mo ya iso. 5.O ni lati yera fun wa ti ololufe mi ba ti de.
Káàsà!!! ❤ Nǹkan ki s'ẹ́sẹ̀ ràgó, a jẹran tán ó tún k'eegun. Ẹ kú ọgbọ́n inú tí ẹ fi ń ró wa tó j'aṣọ lọ, Èdùmàrè yóò máa ṣ'àlekún ìmọ̀. Àṣẹ ÌDÁHÙN SÍ ÌBÉÈRÈ FỌ́NRÁN YÌÍ RÈ É. 1. Yẹ'ra rẹ wò ọ̀rẹ́ mi. 2. Yẹ'ra kúrò nínú ibi ṣíṣe. 3. Yẹ'ra rẹ wò dáadáa kí ó tó gbé ìgbé'sẹ̀ tí o fẹ́ gbé. 4. Yẹ'ra kúrò nínú à ń fa jọ̀gọ̀dì lẹ́sẹ̀ torí pé, ìgbẹ̀yìn rẹ̀ kì í sunwọ̀n. 5. Yẹ'ra kúrò lọ́nà fún mi kí o má ba à fo'rí jó'ná.
1. Moni láti yẹra fún ẹ, kí o má bàa komi si wàhálà 😂 2. Jọ̀wọ́ yẹra fún wa nan, a fẹ́ ni gbólóhùn 3. Yẹra fún ìwà ìbàjẹ́ ki o má ba ba ọmọlúwàbí ẹ jẹ́. 4. Yẹra fún ọtí mímu tí ó ba n wa ọkọ̀. 5. Yẹra fún Ọ̀rẹkọrẹ
Ninu awon akawe te lo fun yera, "iparoje" lo waye ninu "ara". silebu meji pere ni ara, iyen "a" ati "ra", sugbon gege be se salaye, ni won igba te ti so Oro mejeji po, iyen "ye" ati "ara", to wa di "yera", iparoje waye, iro ohun "a" la pa je! Ise nla lese olootu! Mo gbe fun yin oo
You need to do more on counting of numbers in Yoruba
Mo gbodo yera fun siso ede geesi lori eto masoyinbo lati le mu owo goboyi losi le!
Great work sir thank you
1.Mo gbodo yera fun ohun gbogbo to le bami loruko je.
2.Iro pipa lo mu ki n yera fun Bisi ore mi.
3.Oju ni mo fi ba Tola soro koto yera fun wa lana.
4.Omolola yera fun mi nigbati mo ya iso.
5.O ni lati yera fun wa ti ololufe mi ba ti de.
If i have you as my teacher, i would be brilliant.... if all teachers can be like this, e for beta
Káàsà!!! ❤ Nǹkan ki s'ẹ́sẹ̀ ràgó, a jẹran tán ó tún k'eegun.
Ẹ kú ọgbọ́n inú tí ẹ fi ń ró wa tó j'aṣọ lọ, Èdùmàrè yóò máa ṣ'àlekún ìmọ̀. Àṣẹ
ÌDÁHÙN SÍ ÌBÉÈRÈ FỌ́NRÁN YÌÍ RÈ É.
1. Yẹ'ra rẹ wò ọ̀rẹ́ mi.
2. Yẹ'ra kúrò nínú ibi ṣíṣe.
3. Yẹ'ra rẹ wò dáadáa kí ó tó gbé ìgbé'sẹ̀ tí o fẹ́ gbé.
4. Yẹ'ra kúrò nínú à ń fa jọ̀gọ̀dì lẹ́sẹ̀ torí pé, ìgbẹ̀yìn rẹ̀ kì í sunwọ̀n.
5. Yẹ'ra kúrò lọ́nà fún mi kí o má ba à fo'rí jó'ná.
Shey you will allow me explain in english like this if I come to your program. Oluko mi
😅😅😅😅😅shishi o ni mu ré lé
Great
1. Moni láti yẹra fún ẹ, kí o má bàa komi si wàhálà 😂
2. Jọ̀wọ́ yẹra fún wa nan, a fẹ́ ni gbólóhùn
3. Yẹra fún ìwà ìbàjẹ́ ki o má ba ba ọmọlúwàbí ẹ jẹ́.
4. Yẹra fún ọtí mímu tí ó ba n wa ọkọ̀.
5. Yẹra fún Ọ̀rẹkọrẹ
❤❤❤
Teach us counting of numbers in Yoruba
Eleyi ni Iparoje, Aranmo (Iwaju tabi Eyin) ati Asunki gbolohun
Ìpàró jẹ lọ ṣẹlẹ̀
Ninu awon akawe te lo fun yera, "iparoje" lo waye ninu "ara".
silebu meji pere ni ara, iyen "a" ati "ra", sugbon gege be se salaye, ni won igba te ti so Oro mejeji po, iyen "ye" ati "ara", to wa di "yera", iparoje waye, iro ohun "a" la pa je!
Ise nla lese olootu! Mo gbe fun yin oo
Eko wa ni onka yoruba