Court kọ lati gba bail Yaya bello | Tinubu, Shettima ati Iyawo rẹ travel out | Obasanjo o ku | NNPC

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 23 дек 2024

Комментарии • 222

  • @ArabinrinOyindamola
    @ArabinrinOyindamola 25 дней назад +2

    Babawa ogbeni Bobby 😍 😍 😍 😍 😍 😍 yoruba nation no going back

  • @sholaodumosu2705
    @sholaodumosu2705 25 дней назад +1

    Mi o ma le rerin o, I’m rolling on the floor laughing. Apologies to shamble!! Oga ni Buhari legbe Ijoba emilokan . Shamble pro max gan ni 😂😂

  • @Funmilola860
    @Funmilola860 25 дней назад +1

    My lovely brother OGBENI BOBBY you are too much sir

  • @SeekersOfUniverse
    @SeekersOfUniverse 25 дней назад +2

    Ogbeni Bobby IBA Irani aye igba ni. Nigeria ti se ikini oluule laye Obasanjo o. Nigeria ti se ekeji oluule laye Jonathan o. Nigeria ti se eketa oluule laye buhari Mr are sure you! Nigeria wa a sunkun kaakari bayi laye T.pai...n o . Mr omo olodoo ebi. Yoruba nation lokan. Yoruba nation Lona abayo fun awa Iran Omo alade .E Jowo o IBA iranti aye igbaani, nibo ni moti le ri sweet baba dudu raa ni Nigeria o. Ogbeni Bobby you always make my day I love you ❤❤❤❤❤❤

  • @omolaral
    @omolaral 26 дней назад +2

    Ogbeni Bobby Eku eto, Odidi eyin ni won ma npe. Iba gbe wa de be. Yoruba Nation no going back. God bless you

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 26 дней назад +2

    Thanks bro, ogbeni Bobby ❤, great job, asunji ooo, grateful to God, Amen. Regards from the UK 🇬🇧

  • @AdesolaOladeji-d8m
    @AdesolaOladeji-d8m 26 дней назад +2

    Ogbeni Bobby oponu ni awon asiwaju oloselu yoruba lati ma gbe awon omo wa lo si ile ahusa tinubu gan baba yi osi larare lafi pariwo yoruba nation no going back❤❤❤❤❤

  • @fatimahabubakar3458
    @fatimahabubakar3458 25 дней назад +2

    IBA " DEBATE" who sang these song 😂😂😂😂😂😂❤❤❤❤❤❤, good morning sir. I'm present oo. Omo yoruba toda nito, long live ahya. Oodua nation, no going back

  • @megola1159
    @megola1159 26 дней назад +3

    Ope gidi ni fun awon orin imisi ti Funmi Aragbaye ko nigba tiwon o.
    Happy birthday to her 🎉🎉🎉🎂🎂🎉🎉🎉

  • @ComfortOjo-s4l
    @ComfortOjo-s4l 26 дней назад +2

    Ododo lo ngbe orile ede ai si ododo
    Ododo lo ngbe orile ede leke ljoba Nigeria ti fi ai sododo ba gbogbo Nkan je gbogbo nkan ti dojuru Yoruba Nation no going back Good job Ogbeni Bobby ati Aaya God bless you and your family

  • @tinaparker5248
    @tinaparker5248 25 дней назад +2

    Thanks a million 👍 for the 📰🗞️ info 💙

  • @victoriabadejo8796
    @victoriabadejo8796 26 дней назад +2

    Good evening Mr Bobby. Iba go straight to the point. Dr Abati of Arise news is sometimes partial when commenting on news related to government unlike Rufai.I thought this might be because of his previous job with Ex president Goodluck . Yoruba no going back. Oti seese lase edumare. Love you and Aaya.Happy thanksgiving in advance ❤️❤️❤️❤️🌹❤️❤️❤️

  • @risikatadigun9477
    @risikatadigun9477 25 дней назад +1

    O’ Bobby, Thank you Iroyin Ayo koni tan loode yin laelae Olorun a da yin si fun waa , Anu Olorun yio bayin gbe daale tomotomo , Aameen, ❤❤❤ Salaam

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      Amin Àṣẹ Edumare 🙏🙏🙏🙏🙏❤️🙏🥰🎉🙏

  • @megola1159
    @megola1159 26 дней назад +2

    You sing so good, ogbeni Bobby.
    Release your own & our family members here will surely patronize you. Good job!

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @Udonfęminukofo
    @Udonfęminukofo 26 дней назад +2

    Waooo, thanks for sharing this useful information about our Yoruba Nation no going back 👍 Up Yoruba Nation IreeeeeeeUnstopable ❤

  • @M.AdeolaLawal
    @M.AdeolaLawal 25 дней назад

    YORUBA nation know going back igbowo ossa owo baba dami yoruba now ❤❤❤❤

  • @olufemioshikoya4651
    @olufemioshikoya4651 26 дней назад +3

    NIGERIA TI LULE. YORUBA NATION LAWA FE. WE MOVE

  • @olusolaadebayo8243
    @olusolaadebayo8243 26 дней назад +2

    E ku ise na. Odaro o with love 💕 from Edgewood . Maryland. 🇺🇸

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      With much. ❤️❤️❤️❤️❤️ To you

  • @yemiige9990
    @yemiige9990 26 дней назад +1

    Hbd mama Aragbaye. Igba odun odun kan ni. LLNP.

  • @MichaelAlake-b3l
    @MichaelAlake-b3l 25 дней назад +2

    Yoruba Nation no going back and no surrender.

  • @bassirousaka95
    @bassirousaka95 26 дней назад +1

    Ekare ogbeni Bobby, olorun eledumare yio bami duro tiyin, and god bless🇺🇸🇺🇸🇺🇸🇺🇸😍😍💝💝💖💖🥰🥰

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      Amin Àṣẹ Edumare ❤️🙏🥰🥰🤣

  • @godwinayoola5808
    @godwinayoola5808 25 дней назад +2

    The spirit of all innocent people that was killed in Nigeria will continue to monitor all our leaders, their children, and their family forever. Amen.

  • @christinaogundiya4774
    @christinaogundiya4774 25 дней назад +2

    Amin o iba nu je oni wo ile wa loruko Jesu iba Yoruba Nation no going back eku ise God Bless Orun Alafia ni ama Sun o Amin o

  • @sholaodumosu2705
    @sholaodumosu2705 25 дней назад +1

    E kaa le o Ogbeni Bobby ati Aaya. Bawo loju ojo lodo yin o? It’s pre thanksgiving day here today o, cooking is going on o 😂

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 26 дней назад +1

    Mo ran ti, won ooo, Ogbeni Bobby, orin I isinmi, MAMA FUNMI ARAGBAYE❤

  • @kudiogunnaike305
    @kudiogunnaike305 26 дней назад +2

    Ogbeni Bobby, ekale oo, eku ise opolo oo. Ekuroo ni won npe to wa ninu eyin.🙏🙌🙏

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️🙏

  • @josephinefadirepo9366
    @josephinefadirepo9366 25 дней назад +1

    In a😢Yoruba Nation NO going back.❤

  • @hannahhunsu4553
    @hannahhunsu4553 26 дней назад +1

    Ogbeni Bobby God bless you massively ljmn Yoruba nation now now now now ise ti OLORUN ti pari ni odi dandan ki adebe layo ati alafia laisi itasile eje pelu ase Eledumare.

  • @nikeonatunji2186
    @nikeonatunji2186 26 дней назад

    Ogbeni Bobby awon naa ni won ko omo omo omo o,omo oluwa fun wa lomo ti yoo sehinde wa o omo
    Lakurubutu o ma ya jo o omo loyeni
    Mo feran orin yi pupo.❤❤❤❤

  • @josephinefadirepo9366
    @josephinefadirepo9366 25 дней назад +1

    😂😂😂Agogo Ayo ni odewa o. I don't think the man is wrong, he has not taken the food out.

  • @stellaodele5734
    @stellaodele5734 26 дней назад +1

    Ogbeni bobbby Orin ayo le fi bere inu wa dun fun orin ti e fi sina eto e ku ise o en eku eto Yoruba Nation la fe no going back

  • @ogunrindeadebisi
    @ogunrindeadebisi 26 дней назад +5

    VOICE MAN YI JO TI ASHIMOLOWO PASTOR HAAA AWON OGBAGBA UK NIYIOOO NI MARYLAND , OGBONI BOBBY EKUETO OOO , AJUE SE OOO NIORUKO JESU OLUWA WAA AMIN 🙏🥰

    • @reginaaladekere3792
      @reginaaladekere3792 26 дней назад

      😂😂😂😂 " Ayo la o fi s'odun...."

    • @Kemi-w8d
      @Kemi-w8d 25 дней назад

      Luxurious is the most attacked., they just appear from the bush in large number fully armed riding on horses, they usually sprayed the security and everybody before robbing their corpses !

  • @christianamustapha2441
    @christianamustapha2441 26 дней назад +1

    Amin àmin Àshe ni tedumare Ekueto ❤❤❤

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 26 дней назад +1

    Beeni, Ogbeni Bobby, otito, le nso ooo, ko sowo, ko si ounje ni ilu Naijiria

  • @rachealyusuf9635
    @rachealyusuf9635 26 дней назад +1

    Iba Gbewondebe. Loogun ofe o. Eku ise gbewa debe lojojumo. Ese o. Yoruba Nation, no going back.

  • @bisimakanjuola8553
    @bisimakanjuola8553 26 дней назад +2

    Ogbeni Bobby the singer ❤❤❤

  • @josephoyekanmi701
    @josephoyekanmi701 26 дней назад +1

    Ogbeni Bobby/Aaya. E bami so fun odomodekunrin Ayo yi ati gbogbo awon Ayo ti nbe laye, wipe Ayo ni gbogbo wa yio fi se odun oooo IJMN. amen.
    About Obasanjo, he can not died easily like that, he will live longer to reap the wickedness he has committed under the sun.

  • @carolinefowosire8188
    @carolinefowosire8188 26 дней назад +2

    Iba pa lerin😅😅😅😂

  • @AbiolaBello-z8f
    @AbiolaBello-z8f 25 дней назад +2

    Ogbeni Bobby kudos 👍

  • @antimol4593
    @antimol4593 25 дней назад +1

    I like your songs Ogbeni Bobby. I wonder why you are not a professional musician

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 26 дней назад +1

    Ogbeni Bobby, asiko SOROSOKE LA WA YI OOO, A CLOSE MOUTH, IS A CLOSE DESTINY

  • @sundayjonathanaloba6170
    @sundayjonathanaloba6170 26 дней назад +3

    Yoruba nation no going back

  • @FolorunshoTanimola
    @FolorunshoTanimola 26 дней назад +3

    Idi eyin ni won pe

  • @risikatadigun9477
    @risikatadigun9477 25 дней назад +1

    Ti won ba ran loo Dubai, Walahi o Daa, Ti won ko ba ran loo si Oju Olomo o too Kumm
    E ku Etoo , Salaam

  • @akinotiko4386
    @akinotiko4386 26 дней назад +2

    Abati is from Abeokuta.

  • @ShemLogan
    @ShemLogan 26 дней назад +1

    Gov.Adeleke fe gba oju awon ara Ido Osun ni.

  • @bodunshayo1607
    @bodunshayo1607 26 дней назад +1

    Ogbeni Bobby,
    LO GBIYANJU E,
    KE LO PE Telefomu Re, KE BERE OUN TIN TA 😂

  • @ezekielegbalewon4634
    @ezekielegbalewon4634 25 дней назад +1

    Ogbeni Bobby ati aaya è ku ise, Oluwa a tesiwaju pelu yin o. Otito lo ngbe orile ede leke iro ati aise ododo ni Egan orile ede. Nigeria nse eleya ara won kaakiri agbaye 😂.
    Yoruba nation no going back.

  • @nikejajijaji-balogun7331
    @nikejajijaji-balogun7331 26 дней назад +1

    Amen 🙏

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 26 дней назад +1

    Cheese😂❤ oooo, love ❤ 😍 it

  • @Stella-O
    @Stella-O 26 дней назад +1

    Yoruba nation lafe Yoruba nation nitiwa Yoruba nation no going back ❤❤❤❤ ❤ ❤

    • @abiakinsemoyin7084
      @abiakinsemoyin7084 26 дней назад

      Ogbeni bobby se dada ni o, ❤ asi ku gbogbo bi ose nlo. Omugo ni arabinrin yi, ko so otito bi ose fe rin irin re. She is already implicating herself, nitoripe awon American mo bi ose nlo. Ko ye mi to bi awon enia se ma ko ara won sita bi omo ojo mejo. Shio

  • @sholaodumosu2705
    @sholaodumosu2705 25 дней назад +1

    Ayo laa fi sodun o loruko Jesu o tomo tomo.

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 26 дней назад +1

    Iwaju loloko nwa mi lo, eyin lokoko, nwa mi lo, mi o, mi o ,mo ye oo mi o mo, 👏, Ogbeni Bobby

  • @morounadebo6640
    @morounadebo6640 26 дней назад +1

    @Ọ́gbẹ̀ni Bọbi mí! Mó ṣe Àmín àdúrà ó love you plenty ❤❤❤❤❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      I love you too plentiful ❤️❤️❤️❤️

  • @dorcaslamid9029
    @dorcaslamid9029 26 дней назад +1

    Ayo ni afisodun o pani lerin, mo rerin moyomi loju 😂😂😂😂😂😂

  • @isholakoladesamuel3477
    @isholakoladesamuel3477 25 дней назад

    Greetings to Aaya and Mr Bobby

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @Stella-O
    @Stella-O 26 дней назад +1

    Pastor bole nibe se iwo je olorun ti o ni emi eniyan kosi mugu mo baby ti seju e fi etan ngba owo lowo awon alaini olorun oba agba awon talika lowo awon alonilowogba aninilara pastor ni oruko jesu

  • @adenleoluwatosin5899
    @adenleoluwatosin5899 25 дней назад +1

    Ogbeni bobby Yoruba ni abati oo infact omo abekuta ni.

  • @RichardOmokaramon
    @RichardOmokaramon 26 дней назад +1

    Ogbeni Bobby pẹ lu ogo ọlọrun yóò má dùn nì ooo ko nì kọ ooo aye man se NNPC ní ofo wọ́n nì yo je ki a tete gba yoruba nation.yoruba nation no going back

  • @rafiateyiowuawi8526
    @rafiateyiowuawi8526 26 дней назад +1

    Nigeria is not serious. How can someone got that money and he’s still walking majestically. Nigeria is not a country, full of corruption and full of injustices.

  • @esthershosanya1059
    @esthershosanya1059 26 дней назад +1

    E ba was so fun President Tinubu ati Remi Tinubu , ki won rora ma se,nitori Sean nbo,iya ti e fin je omo Nigeria, ki Olorun dariji eyin ati oko yin o, se emo wipe eyin na bimo . E lo toro idariji., e fe ki a wa si ile mo . Yoruba Nation no going back

  • @MaggiFued
    @MaggiFued 26 дней назад +1

    Traveling is wearing the president down. May God strengthen him o.

  • @risikatadigun9477
    @risikatadigun9477 25 дней назад +1

    Aaya ati Oga re ti di ntanasanna Olofofo mo wa lowo , Sugbon sa Ofofo yi niye Lori pupo ti a si gbadun ree gidigidi, Olorun a fi eere to po sii o Aameen Salaam.

  • @follykukku5982
    @follykukku5982 26 дней назад +1

    Ogbeni Bobby she also do street interviews for people in UK.

  • @RachealAjimoti
    @RachealAjimoti 26 дней назад +1

    Padi eyin ni o nje

  • @sholaodumosu2705
    @sholaodumosu2705 25 дней назад +1

    Aare lo ile faranse, shetima na ko si Nile, ajepe boda Wike lo di le mu. Ko sa ma mu gintoniki pupo 😂

  • @samueloluwasegun
    @samueloluwasegun 26 дней назад +1

    Yoruba Nation No going back together we moved.

    • @titilolaadeeko5507
      @titilolaadeeko5507 26 дней назад +1

      Ogbeni Bobby, iriri yin po o pelu ogede ati tomato esa ni oja Ketu. Sugbon a dupe fun ibiti Oluwa gbe yin de loni. E o ni di ohun elo alo pati( abandoned vessel) Ao jo je ire Yoruba Nation.

    • @titilolaadeeko5507
      @titilolaadeeko5507 26 дней назад +1

      Nigeria ku amojuba GMO refinery, lori iro ati itanje.won ma to tu.

  • @freecookiesd5234
    @freecookiesd5234 26 дней назад +1

    As an HR and Admin in Nigeria, why do you need to give someone to fill forms for you?. I don't know why Nigerians always rely on agents for immigration documentation

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      That's Nigerians for you. Eni ti ko ti travel ri, ti ko mo ònà Airport, ti ko mo ibi ti ilu to n promise visa e wa lori Map, awọn mi visa agents ni nigeria, diẹ ninu won lo mo iṣẹ yen

  • @dorcaslamid9029
    @dorcaslamid9029 26 дней назад +1

    Iba orin, ohun yi dun, Oluwa a so agbara dotun

  • @adejumoismaila9964
    @adejumoismaila9964 26 дней назад +1

    Odi eyin ni ogbe ni Bobby

  • @92olamiArabMoney
    @92olamiArabMoney 25 дней назад +1

    😂😂😂😂😂😂 😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂 OmO Haley 😹 Ayo Ni aofi shey Odun oo aoni shey Odun ibanujé

  • @bassirousaka95
    @bassirousaka95 26 дней назад

    Ogbeni Bobby, we want you to come and visit us in USA please, and I will be one of your lovely brother to welcome you, esi ku eto oo, olorun oba a bami duro tiyin in Jesus Christ name, amen 🙏🇺🇸🇺🇸🇺🇸🇺🇸🥰🥰

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      O da mo ti gbọ, o nidi ti mi o se fẹ wa sí US bayi, àbúo mi ati iya mi ti mo ti ri to 10yrs tàbí ko ti ju bẹ lòó ni mo fe wa wo sugbon iṣẹ ti gbe oko re kúrò nibe , o dìgbà ti gbogbo won ba pada ki n to wa US yin.

  • @orisoriola9808
    @orisoriola9808 26 дней назад +1

    Iba LABULE Ogbeni bobby, Idi eyin ni a npe labule wa ti aba deti wa ninu eku ti won ti nse epo ati ma sun isu koko tama fi epo ogere ati iyo je oriola Oris frm dallas tx.

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      Baba oko paraku niyin . Mo rántí koko pupa naa, anamo yellow, iṣu jaloke...ati bebelo

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 25 дней назад +1

    Bobby, Davido did the right thing & Adetoun Tinubu daughter in law back him up, the world knows what is happening in Nigeria Given away of any food that is about to expires, they always give it to homeless people in London.

  • @follykukku5982
    @follykukku5982 26 дней назад +1

    She was in UK.

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 26 дней назад

    Ope ni fun Jesu, KABIYESI, ATERERE KARI AYE, GREAT GOD

  • @esthershosanya1059
    @esthershosanya1059 26 дней назад +1

    Ashimolowo ,o ma je ise ti o se ni aiye , nigbati o ba de odo Olorun, bi won ti nse ni eleyi o, ogbeni Bobby , e seun o fun ise nla ti e nse o. Olorun a ma se Iran lowo , ni Igun mererin aiye o

  • @sholaodumosu2705
    @sholaodumosu2705 25 дней назад +1

    NNPC nah joke! Overnight refinery to taji. Iro ti fo won Lori. E gbe Gbogbo Enu yin soun joor. Awon Oniranu.

  • @elizabethoyeniya8827
    @elizabethoyeniya8827 25 дней назад +1

    Ogbeni Bobby,koni re yin o,you always take us there every day,igi ope ni awon ohun elo to po,ewe ati igi ope wa lati ko ile, eyin ari oguso, ekuro,adin-agbon,epo pupa, eesan fun idana.e so fun Aaya pe ki won fi President wa sile he will be walking around till is time end write it down but mind you the wicked shall not go on punish,eku ise jare .yoruba nation no going back.

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      Àṣẹ Edumare 🙏❤️🙏🥰🎉

  • @MaggiFued
    @MaggiFued 26 дней назад +1

    O' Bobby, welidonu o. Oun lo bi Se ko iwe re. Really enjoying U greatly. People notice how our president walk tiredly all the time. While pressy and wife are boarding the place the wife is suppose to be in front of him. Coming down, the hus ( pres) should be inifrnt while d wife follows. E ye ba wa loju je jare.

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 26 дней назад +1

    Of course. Visa o kann
    owo. American can rejects ones visa any time.

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 26 дней назад

    E ku ataro oooo, gbogbo ile nko? Aaya, se oginiti yi ko poju ni ilu Italy 🇮🇹 ooo

  • @risikatadigun9477
    @risikatadigun9477 26 дней назад +1

    Esin ti kinnikan O se koni je ko kuu boroboro,Niwoo Obasanjo Okay o, Eru Ikuu nba Ebora Owuu 😂😂😂Aimoye Emi teyin na ti fi sowo Sohumm , Ti iku baade e so fun pe Sooja ni yin lo ba tan.

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      🤣🤣🤣🤣Ebora Owu o Fe soda . Ẹseun ana ooo iya mi Risikat....mo ri owo sticker Te fi ránṣẹ sí mi o, se aaya lo ni abemi ❤️❤️❤️. Aaya ti n bere re lọwọ mi o, o ni gbogbo owo ti won ma nfun ohun ni mo ma nnà jẹ

  • @MathewAdekunle-x1f
    @MathewAdekunle-x1f 26 дней назад +1

    ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @EstherAdegbenro
    @EstherAdegbenro 25 дней назад +1

    Odi eyin ni o ogbeni Bobby e ku eto opolo yin o ni joba.

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      Ẹseun baba mi ❤️❤️❤️🙏

  • @maryalamu
    @maryalamu 26 дней назад +1

    OGBENI BOBBY ODI EYIN NI WON NPE

  • @helenaoyenubi475
    @helenaoyenubi475 26 дней назад +1

    Odi eyin ni won npe o

  • @Kanjuabenko
    @Kanjuabenko 26 дней назад +1

    Won dode won, won si pawon

  • @sholaodumosu2705
    @sholaodumosu2705 25 дней назад +1

    Aimoye visa denial from UK to USA. Sebi dey even looked at her papers, some they won’t even looked at the papers.

  • @MotilolaKomolafe
    @MotilolaKomolafe 25 дней назад +1

    Dr Abati is not Yoruba man and he is always working for the government. Their problem is that they did not know nemesis will catch them up one day..All we need is Yoruba Nation for truth.

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 26 дней назад +1

    Fresh things ni ni supermarket, mostly, BREAD, VEGETABLES, etc, ni ilu oyinbo

  • @josephinefadirepo9366
    @josephinefadirepo9366 25 дней назад +1

    Iba yonene eku ise takuntakun. Momagbadun ohun yi.

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 26 дней назад +1

    Bobby, any child 4rm Yoruba land and went to University in Yoruba land, definitely they will go to Northern part or Eastern part of the country for their NYSC or by marriage, they will serve wherever the husband is.

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 26 дней назад +1

    Elee le yaa ni oroo Yaya Bello ye jaa re oo.

  • @Embeejay918
    @Embeejay918 25 дней назад +1

    PASTOR OLE EBI NI YIO PAYIN KU

  • @AbimbolaIlesanmi
    @AbimbolaIlesanmi 26 дней назад +1

    Ogbeni Bobby, emi naa ranti guddy guddy , bazoka gum ati Okin biscuite ni Offa o

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      Aahh, òkín biscuits, se o si Wa l'ọja sa?

  • @godwinayoola5808
    @godwinayoola5808 26 дней назад +1

    Ogbeni Bobby!!!!!!!!!!!
    Kosi iberu Olorun lokan awon Aare ati awon Gomina wa rara, won ti so Olorun di egbe won nitori owo ti won jiko, ati nitori ipo ti won lu jibiti re.
    OMASE O.
    Awon eniyan mi segbe nitori ti won koni imo.
    Ole, olosa, alo koniun figbeta ni awon olori wa.

    • @ogbenibobby
      @ogbenibobby  25 дней назад

      Hmmmn. Won ma tẹ nigbeyin gbeyin

  • @Mummytiobad55
    @Mummytiobad55 26 дней назад +1

    That is Ashimolowo’s voice!!!! This man should be arrested!!! He is a scammer!

  • @derinolusunmade7724
    @derinolusunmade7724 26 дней назад +1

    Ekale Ogbeni Bobby, pastor yi na fe ra private jet ni, kosi boya.

  • @Dorcas00
    @Dorcas00 26 дней назад

    Buroda mi Ogbeni Bobby, e MU mi ranti baba wa, e ku ohun orin ooo