Itan miran titun ti bale si ilu Oyo. Itan gbogbo iwa buruku awon Basorun ilu Oyo ati awon Oyomesi toku, pelu ti eyiti o soju wa. Iyen ni ti Basorun ati awon Oyomesi alalubosa to nja yodoyodo lenu won, ti orun re si nta sansan kaakiri gbogbo agbaye.
Awọn Afọbajẹ kọ ni yóò ro kabiyesi ni ipẹbi o, Awọn Alawo nla, Onisegun, Awọn iya mi Ọpaki, Ọlaki, Afinju niyẹ, Arogba Asọ ma balẹ, Oníṣàngó, Ologun, Oloogun, Oluọdẹ etc... Awọn Afọbajẹ gan yóò soro diẹ láti máa rí Kabiyesi ninu ipẹbi lai gbasẹ lọwọ àwọn tí o n SE ètò Ipẹbi ..... Isẹ Afọbajẹ ti tan lẹyin ti wọn ti yan ẹni tí yóò goróyè.
Asiko oba wa Yio tu wa Lara ni Ile Yoruba oooo.
AARE LAJI ABAS SE AWON AFOBAJE YI KOLESE AIDAA FUN OBA YEN NINU IPEBI O
Itan miran titun ti bale si ilu Oyo. Itan gbogbo iwa buruku awon Basorun ilu Oyo ati awon Oyomesi toku, pelu ti eyiti o soju wa. Iyen ni ti Basorun ati awon Oyomesi alalubosa to nja yodoyodo lenu won, ti orun re si nta sansan kaakiri gbogbo agbaye.
😂 alubosa n run de ibiyi naa.
Al hamdu lillahi 💖
It appears we now have the Governor's Oyomesi And The Selection Of Alaafin Of Oyo for students of History to study
Awa n gbadun yin, net work Dara Lori RUclips
OPE FUN ELEDUMARE IGBA OBA TUNTUN ASAN GBOGBO WA OMO OODUA
Congratulations.
Congratulations to us! Se Oba Rasheed ti ilu Iwo wo IPEBI sha? Bcuz that man doesn't respect Isese at all.
Yes, but he doesn't complete his days in ipebi ilé Òunto, according to reliable source.
Aare congratulations ooo. Amo Eki Olota Of Ota o. Kilode?
Are the same betrayers oyomesi who will organize the ipebi? I wish he is not under threat in ipebi.
No oo the ipebi will be organised by baba lawo and awon afobaje
Oyomesi are the afobaje
@raoufmoustapha3649 Yes, oyomesi is afobaje, but they are not the one who will conduct the ipebi
Awọn Afọbajẹ kọ ni yóò ro kabiyesi ni ipẹbi o, Awọn Alawo nla, Onisegun, Awọn iya mi Ọpaki, Ọlaki, Afinju niyẹ, Arogba Asọ ma balẹ, Oníṣàngó, Ologun, Oloogun, Oluọdẹ etc... Awọn Afọbajẹ gan yóò soro diẹ láti máa rí Kabiyesi ninu ipẹbi lai gbasẹ lọwọ àwọn tí o n SE ètò Ipẹbi .....
Isẹ Afọbajẹ ti tan lẹyin ti wọn ti yan ẹni tí yóò goróyè.
Una go always find a way to defend rubbish. Hes not the chosen one. He's imposed