Yoruba Hymns |Ko Su Wa Lati Ma Ko Orin Ti Igbani |Onibu Ore |E yo ninu Oluwa| Noble Omoniyi
HTML-код
- Опубликовано: 3 фев 2022
- Evergreen Yoruba Hymns Medley (Official Audio) by Noble Omoniyi
Prod by
Joey Dafidi
Sunrizerecordz
HYPEMAN
IG: Bamisile_Olayemi
_____________________________________________________________________________
Don't forget to LIKE, SUBSCRIBE AND SHARE.
____________________________________________________________________________
Contact Me
niyiolorunnisola@yahoo.com
__________________________________________________________________________
CONNECT WITH ME:
Instagram: @nobleomoniyi
Twitter: @neyokoboko
Snapchat: Nobleomoniyi
Ft: IG:Iam.rinoseraph
________________________________
Musicians:
Piano:
IG: Joey Dafidi
Guitarist:
IG: spt_Soul
Bassist:
IG: jesusboy1489
Drummer:
Wale
Talking Drummer:
Professor Alex
BGV:
Soprano:
IG:Iam.rinoseraph
Alto:
IG:miss_raji
Tenor:
IG: Bamisile_Olayemi
LYRICS: * Ko su wa lati ma ko orin ti igbani
Ogo f’olorun Aleluya
A le fi igbagbo korin na s’oke kikan
Ogo f’olorun, Aleluya!
Refrain:
Omo olorun ni eto lati ma bu s’ayo
Pe ona yi iye wa si,
Okan wa ns’aferi Re
Nigb’o se a o de afin Oba wa ologo,
Ogo f’olorun, Aleluya!
* Oluwa orun on aye
Wo Niyin atope ye fun
Bawo la ba ti fe o to
Onibu ore
* E yo ninu Oluwa, E yo
Eyin t’okan re se dede
Eyin t’o ti yan Oluwa
L’ibanuje ati aro lo.
E yo, e yo, E yo nin’Oluwa e yo
E yo, E yo E yo nin’Oluwa e yo./ Repeat
* Okan mi nyo ninu Oluwa
‘Tori O je iye fun mi
Ohun Re dun pupo lati gbo
Adun ni lati r’oju Re
Emi yo ninu Re
Emi yo ninu Re
Gba 'gbogbo lo fayo kun okan mi
‘Tori emi nyo n’nu Re
* Emi yo po'okiki re Oluwa
Iwo ni o da mi nide
Iwo ni koje ki ota yomi
Ogo ni f'oruko re
Iyin ola, ogo ni fun o
Agbara ati'pa je tire
Egberun ahonko to yin o
A wole a juba re
* Ogo ni f'Oluwa t'o se ohun nla (Temi)
Ife lo mu k'O fun wa ni omo re
Eni t'o f' emi re lele f'ese wa
To si Ilekun iye sile fun wa.
Yin Oluwa, Yin Oluwa
Fiyin fun Oluwa
Yin Oluwa, Yin Oluwa
E yo niwaju re
K'a to Baba wa lo l'oruko Jesu
Jek'a jo f'ogo fun onise 'yanu
* Okan mi yin Oba orun
Mu ore wa sodo re
‘Wo ta wosan, t’a dariji
Tal’aba ha yin bi Re ?
Yin Oluwa, yin Oluwa
Yin Oba ainipekun
* Eje k’a f’inu didun (all)
Yin Oluwa Olore
Anu Re O wa titi
Lododo dajudaju
* A f’ope f’olorun
L’okan ati l’ohun wa
Eni s’ohun ‘yanu
N’nu eni t’araye nyo
‘gbat’a wa l’om’owo
On na l’o ntoju wa
O si nf’ebun ife
Se ‘toju wa sibe.
* B’oruko Jesu ti dun to,
Ogo ni fun oruko Re,
O tan banuje at’ogbe
Ogo ni fun oruko Re
Ogo f’oko Re, Ogo f’oko Re
Ogo f’oruko Oluwa
Ogo f’oko Re, Ogo f’oko Re
Ogo f’oruko Oluwa.
* E funpe na kikan,
Ipe ihinrere
K' o dun jake jado
L' eti gbogbo eda;
Odun idasile ti de;
Pada elese, e pada.
* Mimo, mimo,mimo, Olodumare
Ni kutukutu n’iwo O gbo orin wa
Mimo, mimo, mimo ! Oniyonu julo
Ologo meta, lae Olubukun
* A segun ati ajogun ni a je,
Nipa eje Kristi a ni isegun
B’Oluwa je tiwa, a ki yo subu
Ko s’ohun to le bori agbara re
Asegun ni wa, nipa eje Jesu
Baba fun wa ni ‘segun, nipa eje Jesu
Eni t’a pa f’elese
Sibe, O wa, O njoba
Awa ju asegun lo
Awa ju asegun lo
* Ore ofe! Ohun
Adun ni l’eti wa
Gbongbon re y’o gba orun kan
Aye y’o gbo pelu
Ore ofe sa
N’igbekele mi
Jesu ku fun araye
O ku fun mi pelu
Olori ijo torun
Layo la wole fun O;
K'O to de ijo t'aye
Y'o ma korin bi torun
A gbe okan wa soke
Nireti to nibukun
Awa kigbe, awa fiyin
F'Olorun igbala wa Видеоклипы
Now Available on:
Spotify
open.spotify.com/album/5L0VoPrrLZ2zTqNOCJiU1C
iTunes
itunes.apple.com/album/id1608756373?ls=1&app=itunes
Boomplay
www.boomplay.com/share/music/82719540?srModel=COPYLINK&srList=IOS
Audiomack:
audiomack.com/noble-omoniyi/song/evergreen-yoruba-hymns-medley
Kindly Drop a Comment, Share and Like 🙌🏻🙌🏻🙌🏻🙌🏻
You're worthy of my praised
HALLELUJAH IYE HOSSANA AMEN
AÀ111AÀAAA1AA😊😊AQ😊QQQAÀQ1qqqq
This is really beautiful. Well done Noble Omoniyi. God bless you
Thank you for sharing these beautiful songs ❤️❤️❤️❤️❤️❤️
Thy Lord will uphold and strengthen you and the entire band.....
More anointing......
I liked it before listening 💃💃💃
🙌🏻🙌🏻🙌🏻🙌🏻
You make me love Yoruba worship 🕺🕺🕺🕺🕺
Thank you 🙌🏻🙌🏻🙌🏻🙌🏻
Kabiyesi mi Eleru niyin! Mo gbe O ga! More grace to you! Lovely medley 🎵🎶
Thank You 🙏
Awesome 👏
🔥🔥🔥 powerful piece sir
Thank you sir 🙌🏻🙌🏻🙌🏻
This is beautiful sir
Thank you so much.
God be praised 🙏🏼
🙌🏻🙌🏻🙌🏻🙌🏻
🔥
🙌🏻🙌🏻🙌🏻🙌🏻
Apple Music soon?
It is available now. Here’s the Link
itunes.apple.com/album/id/1608756373
💃💃💃🙏🙏🙏❤